Gba aiye mi oluwa, Mo ya si mimo fun O Gba gbogbo akoko mi Ki nwon kun fin iyin Re. Gba owo mi, k’o si je Ki nma lo fun ife Re; Gba ese mi, k’o si je Ma jise fun O titi Gba ohun mi, je ki nma Korin f’oba mi titi; Gba ete mi, je ki wom Ma jise fun o titi. Gba wure, fadaka mi Okan nki o da duro; Gba ogbon mi, ko si lo Gege bi o ba ti fe. Gba ’fe mi. fi se Tire; Kio tun je temi mo; Gb’ okan mi, Tire n’ ise Ma gunwa nibe titi. Gba ’feran mi, Oluwa Mo fi gbogbo re fun O Gb’emi papa; lat’ one Ki’m je Tire titi lai.
@adewunmiayomide81383 жыл бұрын
My part, Alto, very lit! 😍
@cccikoroducentralchoir29803 жыл бұрын
Beautiful rendition
@danielosolarin65213 жыл бұрын
Dodimu by Yemi Akinpelu 👍👍👍
@deborahalabi46523 жыл бұрын
I love scpc 💕💕🥰🥰
@olubomiolufola25013 жыл бұрын
SCPC shall live and never die... Keep the fire burning 🔥 🔥 🔥 🔥