Пікірлер
@hanahussin3015
@hanahussin3015 Сағат бұрын
Enuyin oni koba yin wasiu ayinde nkan teso tipoju enu yin lo ema jeki won fi aye ran yinoooo anu e semi gbogbo awon eyan lo n soro yin ni buruku eloyi pada anyway osupa ni fans mi omo alalubarika brother saheed osupa
@hanahussin3015
@hanahussin3015 Сағат бұрын
Eyin Alpha ejowo ema binu
@hanahussin3015
@hanahussin3015 Сағат бұрын
Is very bad for him to be saying that word to a whole Alpha won wa ye yinsi ede so aduru oro yen si awon eniyan olohun tiwon koyin ni keu opoju
@user-ub2bx1xn5k
@user-ub2bx1xn5k 4 сағат бұрын
ON THE OTHER HAND IT'S BEEN A NORM TOO FOR THE ALFAS TO BE MORE MONEY CONSCIOUS THAN PREACHING THE RIGHTS OF FUNERALS IN THEIR OWN RELIGIOUS WAY. SO THEY NEED TO USE THIS AS A LESSON TO LEARN ON THIS VERY SUBJECT. THE LESSON HERE IS TO ALLOW TGE ALFAS PREACH REPENTANCE AND FEAR OF GOD ST FUNERALS EVENTS SO MOST PEOPLE CAN CHANGE AND MOVE CLOSER TO GOD. NOT HUNGRY FOR MONEY OR AVENUE TO USELESS THEMSELVES.
@RasheedRokeeb-u7c
@RasheedRokeeb-u7c 11 сағат бұрын
Oju ti ore mi oju oti ....proveb
@bolaelegbede7843
@bolaelegbede7843 14 сағат бұрын
You are a clown.
@kathyhenry3645
@kathyhenry3645 15 сағат бұрын
Ki olorun fori jin gbogbo wa oo
@akindelegiwa5874
@akindelegiwa5874 16 сағат бұрын
Olorun olodumare ni oni dajo❤❤idajo je ti olorun,, awon afa ti lule❤❤❤loba tan
@akindelegiwa5874
@akindelegiwa5874 16 сағат бұрын
Enin ti ori bati da,, ❤ori ti da a naa ni,,, wahala yin ti poju, ki Onikaluku lo ran aye tie,,, awon afa hun wa owo ni sugbon won ba ijakule pade,, omo Yoruba gidi,, e maa pelu obo jawura,, e jeki a fi oro wa le olorun olodumare lowo,, ki o bawa se tiwa naa ni irorun,,
@hanahussin3015
@hanahussin3015 Сағат бұрын
Rubbish lo n so
@akindelegiwa5874
@akindelegiwa5874 16 сағат бұрын
Awon afa ori social media oro oloro ni obi hun ku le lori😂, olorun olodumare ti se wasiu Ayinde ni aanun, o ti ri aanun gba,, ki olorun olodumare jeki emin wasiu Ayinde gun,, ki aye awon omo temi naa ni itumon si rere, lase olorun olodumare
@akindelegiwa5874
@akindelegiwa5874 16 сағат бұрын
Iwa ati ise lafi hun ma enin olorun ki se gbogbo eleyi ti gbogbo awon afa hun se ati awon oro alufasa ti o ti gbogbo enun awon afa olote ati onilara wonyi jade lenun won ki olorun gbawa ooo
@akindelegiwa5874
@akindelegiwa5874 16 сағат бұрын
Ali Quran so fun wa wipe ti o ba di akoko kan won yio maa ka Ali Quran,, koni si eniyan kan kan ti yio teti gbo oro inun re maa,,,, se iru iwa awon afa wonyi naa ko lo maa fa a ,, awon afa ti so ara won di olorun olodumare le awon eniyan lori,, i
@akindelegiwa5874
@akindelegiwa5874 16 сағат бұрын
Se awon afa wonyi ni won fe gbe iya wasiu Ayinde de alijanna ni a bi kini gbogbo eleyi naa
@akindelegiwa5874
@akindelegiwa5874 16 сағат бұрын
Ara lo hun ta yin olote niyin se dan dan ni ki e lo ibi isinku iya wasiu Ayinde ni se won fi iwe pe yin ni,, business yin ti daru
@akindelegiwa5874
@akindelegiwa5874 16 сағат бұрын
Se dan dan ni won fi hun lo si ode ni,, e moju to aye yin,,, olorun olodumare ko roro,, eyin afa wonyi ni e hun pe ara yin ni hun kan pataki ti olorun ko pe yin😂😂😂
@akindelegiwa5874
@akindelegiwa5874 17 сағат бұрын
Ni igba ti wasiu Ayinde ti bere agbe tie ni sise❤inun igbo ni opolopo eyin afa wonyi hun gbe ni igba naa,, ilara
@akindelegiwa5874
@akindelegiwa5874 17 сағат бұрын
Se e ri ti gbogbo wa lowa lara wa, sugbon omo Yoruba gidi ti ori e pe, ko gbodo pelu awon wonyi maa bu, wasiu Ayinde,, awon afa ti won hun fi iwa won ba aye iran Yoruba je,, ole ni gbogbo yin e lo wa ise se
@rasakbunmi6136
@rasakbunmi6136 22 сағат бұрын
Ewo ni were eyin Alfa o kinse nibe ki won to fun yin liwo
@rasakbunmi6136
@rasakbunmi6136 22 сағат бұрын
Alfa akeem Ori e buru,,Iwo npe k1 ni alagbe,,Alfa akeem kinni Iwo,,,,oga alagbe,,,, keep shop now alagbe....ni Iwo akeem,,,,who's Alfa,,,,stupid people with stupid knowledge....
@christianasktoluwase2893
@christianasktoluwase2893 22 сағат бұрын
OTI Di Akitan 10:42 PATA Pata
@christianasktoluwase2893
@christianasktoluwase2893 22 сағат бұрын
Tile Nso Fun President Bola Pe Mi Ole Ni O Laye
@SakiratAdejoke-b3r
@SakiratAdejoke-b3r 23 сағат бұрын
That's statement is not good atoo wasiu ayinde be careful
@olowojobaisaac
@olowojobaisaac Күн бұрын
E jowo ki ni iwulo Alfa ni ile yoruba?
@sholabisulaimon162
@sholabisulaimon162 Күн бұрын
Soo ki gbogbo wa maa kuku GANU kiri bayi😂😂
@monsratabiodun4907
@monsratabiodun4907 Күн бұрын
Long life for you k 1, bi eyin eniyan se nbinu re ni o se nni Ola si.
@akindelegiwa5874
@akindelegiwa5874 17 сағат бұрын
@@monsratabiodun4907 be e ni won hun binun ori ni sugbon eniti ori bati da ori ti dayen naa
@hanahussin3015
@hanahussin3015 Сағат бұрын
Eni Opolo ede pe ara yin ni muslim
@cordeliapeters765
@cordeliapeters765 Күн бұрын
Wasiu is not a Muslim, awon babalawo lo gbokan le. And God will bring him down bcos of his proudness. Omo ale ni Wasiu, ole ni, apayan, hire killer. Shame on him
@atakansherifat
@atakansherifat Күн бұрын
Let him apologize in the public
@hanahussin3015
@hanahussin3015 Сағат бұрын
Gud of u mio ni wa eti
@yusufbabarundekolawolealabi
@yusufbabarundekolawolealabi Күн бұрын
😅😂
@MustaphaRauf
@MustaphaRauf Күн бұрын
Onifuji melo leri lojo fridaus leyin paso tiri taiye ati sefiu Alao. Awon merin tiwon ganu ninu onifuji niyen Asiweere
@MustaphaRauf
@MustaphaRauf Күн бұрын
Bibi ire kosefowora. Agba kokan ogbon. Emafi saheed osupa tabi pasuma we. Wasiu now. Iyato be gborogboro ni now
@olasunkanmiademola6309
@olasunkanmiademola6309 Күн бұрын
Does it simply means that both Alfas and K1 are essentially professional beggers?
@abiodunatoke9529
@abiodunatoke9529 Күн бұрын
Hmmm🤔🥺Innama Duniyan Balahu Lamyakun Fiha Subutu🤦‍♀️
@titilayosotiyo2742
@titilayosotiyo2742 Күн бұрын
Ganukirian 😂😂😂😂😂
@Ire...6838
@Ire...6838 Күн бұрын
Oko osho alfa jabaru... Bo seni owo to nigba tose igberaga si ... Awon alfa gbogbo ikan loni pare loju e ko toku.... 🚔🏠🚢 Koda awon Omose tun ba iyawo e sun dada 🤔
@Ire...6838
@Ire...6838 Күн бұрын
Orisha ijebu lo gbe oju le... Emo pe igi ofo lomu kiri lojo loju... Si o e wasiu...
@Ire...6838
@Ire...6838 Күн бұрын
Tunde Ojurogbe, Tunlapa lati igba ti bobo ye ku, ko tun awon Omo bobo ye ni kobo de bi iyawo tunlapa.... Awon ti wasiu tiba aiye je lo poju....
@Ire...6838
@Ire...6838 Күн бұрын
Alfa se e fe gbon kosi eni toni owo ati ola to Olorun Oba toda wa... Eni yeye ni wasiu ole ni nla.....
@Ire...6838
@Ire...6838 Күн бұрын
Eranko enia ni wasiu.. ole ni ati oba 419.... Ejowo se ohun nikan ni iya e bi ni, awon egbon nko ati aburo e... Ari won... Abiola toni owo ju lo da...
@Awake_Africa
@Awake_Africa Күн бұрын
Abeg stop this we have more issues in the land. What good has you Alfa's done for us. Pond of correction Alfa is not eeyan Olorun. Who are you gann .
@olabisifasoro983
@olabisifasoro983 Күн бұрын
Ododo oro oun lo toro wa oro oro l'omo eleti nje
@olabisifasoro983
@olabisifasoro983 Күн бұрын
Igberaga lo nsiwaju iparun 😮
@olamideola530
@olamideola530 Күн бұрын
❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤
@supoolawoyin6037
@supoolawoyin6037 Күн бұрын
See K1 ati Babalanku lee durolegbe DAVIDO. Davido tin loo Rolls Royce ki iyalaya K1 tora
@BR-tc8wo
@BR-tc8wo Күн бұрын
You are right Alfa. Wasiu Ayinde is the Chief of Ganuologist before he became Kwam 1. 😂😂😂
@aareadeotijideebenezer7467
@aareadeotijideebenezer7467 Күн бұрын
K1, has been an arrogant human right from time, in so many ways.
@mojimohammed5365
@mojimohammed5365 Күн бұрын
Sise sise tin baa wasiu ayinde.
@timmyrichard1670
@timmyrichard1670 Күн бұрын
You guys are really boundless fools. Let's call a spade its name. If you guys had gone to his parental homes, K1 wouldn't have said that. Even you, you are rude for calling President Tinubu by name. And if K1 to you can't say, you "Ganu", I hereby say; you're one, Ganuganu Alfa ni e. Whatever anyone acquires as well on earth would be left behind and thrashed one day. Alfas, I advise you to get something doing . K1 is blessed already. Stop the envy and take out the specks off your eyes before procrastinating K1s'. Awon Alfa LASANLASAN, GANUGANU ALFAS, E LO WASE SE.
@LawalOmowunmi-u6z
@LawalOmowunmi-u6z Күн бұрын
Sorry goes a long way, he should have just say sorry 👌
@OkunadeMusbau
@OkunadeMusbau Күн бұрын
Asiso oro gbaa ni. Eleyi si tokasi pe bi iparun se nba eda niyi. Ni iwo nikan ni ki o toro aforiji lodo olohun ki ojo re le tubo pe lori ile. Aseju re ti npo ju. Ki o ya dekun e..mo gba e ni imoran ni.
@kunmimarvelous5795
@kunmimarvelous5795 Күн бұрын
But you are a begger.