Hmm, ọpọlọ pọ. Mo ni gbádùn yin ọ. Ẹkọ yin máa n jinlẹ̀ gan
@olaitanayinde-tb2od5 ай бұрын
Mo fẹ mu àbá kan wa wipe ki e máa gbiyanju lati máa kọ orúkọ awọn àpẹẹrẹ nkan ti e ba n dárúkọ sí oju screen yin. Eleyii a tun máa fa awọn oluworam mọ'ra ati lati ma le gbagbe awọn ẹkọ ti e n kọ wa. E ṣeun. A dúpẹ o
@olaitanayinde-tb2od5 ай бұрын
wow, e ku iṣẹ o. Mo gbádùn yin gan-an o. Àlàyé yin kún gidigidi gan-an ju awọn ẹkọ ti mo ti n gbọ lórí KZbin.
@BolanleAdesola-h7y6 ай бұрын
Ejowo sir ebawa ki oke
@rachealsoladoye72638 ай бұрын
Ẹ kú ètò sà
@pretty_zee0019 ай бұрын
Edakun Kini oriki olugbodi , Kilode ti Eni kankan o Soro nipa re
@ThomasIlelabayo10 ай бұрын
Your program is good but prolonged and repeating
@ThomasIlelabayo10 ай бұрын
Ajayi nko se ki n se oruko amutorunwa
@debodebo963011 ай бұрын
Mo gbadun channel yi
@BradHamigo Жыл бұрын
Thank you sir
@larkimolorin Жыл бұрын
I am loving this ❤
@OpebiyiOluwatobiloba Жыл бұрын
ko Orisi alo apamo mewaa 10 pelu idahun Okookan won
@OpebiyiOluwatobiloba Жыл бұрын
Hi
@oresanyamary4362 Жыл бұрын
Thanks so much. Is Osun pipe ewi alohun ?
@adenugacaroline3339 Жыл бұрын
Oga mi mi mi ibeere Lori Didi oku, ibeere mi nipe oku ti won wọ asọ odi fun jinni itumo re.
@funmilayotaiwo8931 Жыл бұрын
Eku irole sir ejowo sir ti o ba mu idi waye nko sir
@Jide0001 Жыл бұрын
These videos should have more viewers, comments and likes. What am I missing? Okunlola, omo Amao, la ti ilu Fiditi, e joo, e gba ope mi o. Olodumare a bukun fun yin, rere le ma ri. Ase.
@ogunolaadeyemi5894 Жыл бұрын
Nice one my brother
@dupzyhairandcare7125 Жыл бұрын
Moki yín pupo olootu
@teejayahmed65172 жыл бұрын
Ese fun imo ti nfun wa
@sherimango38682 жыл бұрын
🎉🎉🎉
@sherimango38682 жыл бұрын
Bẹẹni 👌
@harbeylardontop2 жыл бұрын
Adákun ẹbáwa ki Àìná àti Àlàbá 🙏🙏
@idowusegun54712 жыл бұрын
Ki se gbogbo eyan lo mo oriki ile baba re
@ikokoasatv2 жыл бұрын
Ẹ kú ètò
@asayajaya2 жыл бұрын
How come these videos don’t have millions of followers? This kind of teaching is simply priceless. E ku ise takuntakun, baba wa!
@ojophilipokunlola14472 жыл бұрын
Ẹ ṣeun mo mọ rírì yín oooo
@asayajaya2 жыл бұрын
listening to teachers like this is more important than shouting Yoruba National, Yoruba Nation. When you don’t even understand the culture of Yoruba which nation are you trying to create. If we following these teachings diligently we would be ruling Nigeria and other tribes would be converting to Yoruba like people convert to religion. Eku Ise ojare Baba wa. E o ni s’asedanu e o si ni gbere itiju.
@ojophilipokunlola14472 жыл бұрын
Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun mo dúpẹ́ o
@Jide0001 Жыл бұрын
Yoruba is the best culture while you're typing in a germanic language, using a latin script, on a platform with European engineering roots? Baba, e jo, e tun ro. The beauty of Yoruba culture has nothing to do with its being better or worse than any other culture.
@asayajaya2 жыл бұрын
How come only 78 views?🤷♂️. Every Yoruba child should be learning this. Not learning this rich culture of ours is why we are being ruled today by bastards. Thank you very much. . Ahun kii hun òsà, èhun isu kii hun iná, ekúkú isu kii hun òbe. Èèyàn ní ńhun agbòn, agbòn kii hunni. A máa jú yín se o!
@ojophilipokunlola14472 жыл бұрын
Àwíṣẹ àfọ̀gbohùn
@silasmaxwell10042 жыл бұрын
I really enjoyed it .You have a great presentation skill and delivered it nicely.