O ye ki Ijoba SE idajo to ye fun Yahaya Bello nitoripe ole ponbele ni o .
@loladeakanji897112 сағат бұрын
Gbogbo eyin Oloselu Nigeria bi eni kan ko ba le mu yin. Olorun ma mu gbogbo yin
@loladeakanji897112 сағат бұрын
Ko si Idajo ododo kankan ni Nigeria. Olorun lo ma se idajo gbogbo awon Oloselu Nigeria.
@thankgodlee607017 сағат бұрын
Omo nawa ooo Person commit crime, he still dey laugh like this for court imagine Nigeria my country Tuale 🙌🙌🙌 ooo
@princebello80718 сағат бұрын
Esee eku ise' 'odara awon customs ogun state se won KO le pe fun iranlowo ni
@Ire...683818 сағат бұрын
Ewo Oju oleeee 🥴👏
@Ire...683818 сағат бұрын
Madam kazeem... E kaaro ma 💯✅
@Ire...683818 сағат бұрын
E wo Ile Aiye awon ojelu Nigeria.... EFCC 🥴👈 lbiti eba tan wa de ema so funwa toba ya.....
@tayoadedara910019 сағат бұрын
Very fascinating news cast! Thanks.
@raytopson282820 сағат бұрын
A country where criminals are celebrated!,,,,,,shame on Nigeria,
@olabisiayodele332221 сағат бұрын
Omode ni baba Obasanjo o ema ro iku ro baba o
@olabisiayodele332221 сағат бұрын
Yes better be ogbologbo ole
@olabisiayodele332221 сағат бұрын
So akin ma jebi lodo Olorun
@olabisiayodele332221 сағат бұрын
Olori ole leyin nba sere Yahaya Bello ole ni eyin we’re tun ngbe leyin e
@olabisiayodele332221 сағат бұрын
Se ijoba lo ngba ibe ni abi awon ara ilu
@princegabriel.97522 сағат бұрын
Oloriburuku Awon lonba Nigeria je. Olorun ma bawon je Amin. Won gbe seyin Ole!! Yaya Bello is a Thief but look at Nigeria's judicial system. Awon sets of illiterates!! I'm really really sorry for the Country fighting Corruption!!😭🥶. O ma seooo!!😭
@bellomodo3184Күн бұрын
Éku ise takuntakun niigba gbogbo
@loladeakanji8971Күн бұрын
Eyin Ara Ondo, e ti gbpwo e ti dibo. E ko iti ri ohun kohun. Yoruba Nation ni awa n fe.
@sundayemmanuel703Күн бұрын
May God take control
@Ire...6838Күн бұрын
EFCC 🥴👈 E mura si iro nyin ti poju, idajo Oluwa Olorun Oba Jehofa ☝️ ma de ba gbogbo nyin pata
@Ire...6838Күн бұрын
Eyin Omo ilu Nigeria.... Se eri aiye nyin lode, awon oloselu yii mo iwa ara won daada Olowo ba Olowo se ni oro gbogbo won pata.... Eyin Omo ilu Nigeria ema ba arayin ja nitori awon ojelu yii... 🥴🥴🥴
@Ire...6838Күн бұрын
Mr Tokunbo eku ise nla naa o!
@Ire...6838Күн бұрын
Madam Olayemi Owurubutu Orobo, Oju nyin da ma.... Se alaafia ni ewa ma
@Ire...6838Күн бұрын
Eyin Omo ilu Nigeria taba Oruko ilu Nigeria je.... Oluwa Olorun Oba Jehofa 🙏 ma ma mu yii
@Ire...6838Күн бұрын
Mr Sanni Abiodun eku ise nla naa sir 👍💯💯👏
@princegabriel.9752 күн бұрын
Well done 👍
@princebello8072 күн бұрын
Eku ise takuntakun'ODARA AIRPORTS NIGÉRIA GBOGBO KO SI CAMÉRA KANKAN NI?
@sundayemmanuel7032 күн бұрын
May God take control
@Ire...68382 күн бұрын
Gbogbo eyin osise ilese YBN lroyin kakiri Agbaye... Eku Ojomo rere oni yii sir/ma....
@Ire...68382 күн бұрын
Eyin alapa ma sise ole, 419, yahoo+... Asiri yii ma ma tun ni lagbara Olorun ☝️ Oba... Eyin Omo aale ilu Nigeria yin
@Ire...68382 күн бұрын
Ijo wo ni eyin Baba ati iya nyin Jo Kiri... Ki Oluwa mase yii ni onijo osin... Eto yin le gba lowo won.... Abajo tan fi ma woyin ni elebi 🥴
@Ire...68382 күн бұрын
Eyin Ojelu Oselu Nigeria pata, Ole nla ni gbogbo nyin pata Ole fe mu ole... Radarada lese....
@Ire...68382 күн бұрын
Eyin Gov yii sha, kosi iberu Oluwa Olorun Oba Jehofa, lokan yin rara. Awon tan dibo funyin e kan fi iya jewa ni....
@Ire...68382 күн бұрын
Okunrin towa ninu car yii, mo kie Ku orire nla naa sir! Oluwa Olorun Oba Jehofa 🙏 E se o
@Ire...68382 күн бұрын
Mr Seyi lpadeola ❤
@olajuwontosin59233 күн бұрын
Nigeria my country,they want too prosecute stealing of chicken what about all this rit@ulist they arrest and others ki@lling they did not prosecute them till now hmmm may God help us
@princebello8073 күн бұрын
Eku eeto'
@islamiathadenikeadeleye11173 күн бұрын
Nigbati won da ejo iku fun eniti oji adie ati eyin , what he did it not good but se adajo toda ejo naa , se ko bimo ni ati pe boya ebi ati iya losun lo jale, ibere ni nipe gbogbo awon to nko owo gbogbo omo orile ede ilu je , idajo wo loto si gbogbo won , hunnnnn olagbara o
@Ire...68383 күн бұрын
Madam Olayemi Owurubutu Orobo... Eku ojo meta ma se kosi ma.. ari yin ma
@Ire...68383 күн бұрын
Eni toba bi Omo e ko to daada... Omokekere tan da e joo iku fun 😮... Nitori adiye to ji, Yahaya Bello nko eni topa gbogbo state lekun... Ati awon olopaa tan ta ibon fun awon ole, e joo kini e da fun won... Sugbon gbogbo idajo wani iwaju Olorun Oba.... 🕊️☝️🕊️
@Ire...68383 күн бұрын
Olorun Oba Jehofa Oju yin da... E sanu wa ni ilu Nigeria o! E wo eba ati obe tiwon fun awon Omo ilewe je... Hahaaaaa
@Ire...68383 күн бұрын
Mr Sanni Abiodun... E kaaro sir ati gbogbo eyin osise ilese YBN lroyin kakiri Agbaye.... Mr Kenny. Madam Olayemi Owurubutu Orobo. Madam kazeem. Mr Seyi lpadeola pelu awon osise toku pata....koni baje funyin tomotomo lagbara Olorun Oba Jehofa 🙏 AmiiiiiiN
@olabisiayodele33223 күн бұрын
Sebi ijoba apa po nri awon ile iwe ni ile o kere ti won nlo bi ile won se ri Bose rewa to je pe Ko si omo ti won ma Ko ti iwe Ko ni wun
@olabisiayodele33223 күн бұрын
Oloriburuku ni eyin ti e nda jo iku idajo wo le se fun awon to ji owo nla ti Yahaya ati awon to nji owo ilu lo si oke okun
@haynehifanny80064 күн бұрын
Ọpọlọpọ awa ololufẹ Iroyin yin ti kìlọ, kìlọ, kìlọ fún yin wipe arakunrin yi nṣi awọn ọmọde ati agbà lọna bi Yoruba ṣe npé lẹta "R". Ṣugbọn ẹ kọ jalẹ láti gbé kúrò fún iroyin kika. Emi nitemi ti unsubscribe lọdọ yin. Awọn ọrẹ mi mẹjọ ati ẹbi wọn yóò kuro laipẹ rara. Ayafi ti ẹ ba paarọ ẹ sí ẹnití o le pè lẹta yẹn bi o ṣe tọ ati bi o ṣe yẹ. Ẹ lọ wa iṣẹ fún ni Republic of Benin jàre Koye ba ìròyìn yin jẹ
@Ire...68384 күн бұрын
Fake police 🚨.... Ewon gbere ni ke da
@Ire...68384 күн бұрын
Awon to sise nibe naa ni won ma jale nibe.... 😆
@Ire...68384 күн бұрын
Kabiyesi O 🙇 Happy birthday 🎈🎂🎈 sir.... Emi mase opolopo odun laye tomotomo 🙏 AmiiiiiiN