Alaroye ,ewo tun ni "ategun alafia ni ogba ewon😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂
@ojlinksglobal16164 ай бұрын
igboro ni Lara osi fe lo gbategun lewon
@idowuibosiola86634 ай бұрын
You guys are calling him thief what about our leaders 🥲
@olanrewajusheu70424 ай бұрын
Let him go and explain about that uniform in soldier barracks
@meciboqueaanuoluwapo13674 ай бұрын
Hhhhmmm 🙄
@Ire...68384 ай бұрын
Ori e ti baje iwo ole jatijati! Eewon gbere ni ke fi si
@olanrewajusheu70424 ай бұрын
Their type na im dey take girl do bad things for Ogun State
@akinleyeolushina4 ай бұрын
Omo aale ijagbo nieee
@derekajisefini25614 ай бұрын
You tis media need to be checked, why you veil & unveil some suspects?
@Alaroyeonlinetv4 ай бұрын
Ti iwadii ba ṣi n lọ lọwọ, to ni awọn eeyan mi-in ti afurasi yii darukọ, wọn ko ni i sí oju rẹ sita
@abbeylove49344 ай бұрын
@@Alaroyeonlinetvotito oro leso, ise opolopo ni eku ise takun takun 👏👏👏👏👏
@amooponle85514 ай бұрын
LoL 😂😆😂 clone soldier
@estheresthersamuel90694 ай бұрын
Oju oooole ree Oooooooole
@AbiolaHawanat9 күн бұрын
Dariji e ko, dariji e ni 🤪
@mariamasie93294 ай бұрын
419 Ogun state
@iyaboadeyilola63944 ай бұрын
Ewon lo ma ku si ole aye e ti bajee
@lalaoluwasegun63274 ай бұрын
Omo werey 😂😂😂😂
@elstonmartina68424 ай бұрын
Omo kwara wa jale nigboro egba thanks God your name is not LEKAN
@olaoluwamuda37644 ай бұрын
Nkan ti o ma ndunmi nipe awon amajale ma se nkan tiko dara kaa kiri. Eni ranti pe ba se nyoso bee naa lanyogbo. Ejawo kuro nibi iwa aida
@oluwaseunadebowale35044 ай бұрын
Haaàaaa, Omase o... Okete boru mo l'owo Owo Palava segi, kosi sise kosi aise ki won gbe lo so ile ejo
@AlfaAbass-if8wb4 ай бұрын
Ofo lomi efo se Omo okunrin yi yo sofo danu bi omi efo ni
@AlfaAbass-if8wb4 ай бұрын
45k ni oloribuku ee gba lowo Omo ise mi
@Ire...68384 ай бұрын
Egbon e na tose soja ori ko pe, o jeki awon oga won na fi ohun sinu eewon fin odun meta ni.... Olosi ara e jowo aso pada losi lbise, boys ohun na ti sise lbi Kan ni won se iwadi tie na
@AlfaAbass-if8wb4 ай бұрын
Oloribuku ni emi na ti kosiri koni bo nibe
@Emiola_14 ай бұрын
Alaroye e ku ise, sugbon o wu mi ki e bi leere wipe iru Ogbon wo tabi irufe eroja wo lo n lo ti o fi n fidi e mule lati fi se afihan wipe Oun ti se transfer gege bi (fake transfer)! We need to know the trick/app he used to confirm to the pos operators to trick them that the money is sent/transffered
@adebayophilip60114 ай бұрын
You want to join him Abi ? Oleeee
@oriyomiokunoye77724 ай бұрын
Alaroye ekun ise takuntakun oo
@amudatdupe29734 ай бұрын
😂😂😂😂😂😂
@questionandanswer64654 ай бұрын
Civilian is using my uniform to steal chai!!!
@questionandanswer64654 ай бұрын
God bless you I catch you with that uniform
@MichaelMacInnisАй бұрын
@@questionandanswer6465Something is definitely wrong with your head. Look at the way you mentioned the word civilians so derogatorily. You are not superior to the next Nigerian, because you are on uniform.