Eledumare yo fi Alekun ogbon kun ogbon abeni agbon
@LewisMuturi-b7u9 ай бұрын
KI OLODUMARE DURO TI ABENI AGBON ATI GBOGBO AWON OSERE OJULOWO OMO OOTU (YORUBA) TI WON KO IPA PATAKI NINU ERE ALADUN IBILE YORUBA YI NI ASE EDUMARE AWON ERE ALADUN YORUBA TI O YE KI AWON OJULOWO OMO YORUBA ODE ONI YI MA WO RE OOOO,SUGBON IRO NI, A FI KI WON MA WO ERE YORUBA IGBALODE TI AWON AJEJI OMO YIBO KO`PA NINU RE TI WON KO SI LE RI EKO KAN TI O DAN`MORAN KO NIBE, AYA`FI, ERE AWON ASEWO TABI AWON TI WON N`JALE