Thank you sir. Se egbo akọ ibepe Abi ìbépe ti o ma n so.
@FausatSalami-x9f7 ай бұрын
Oba oke yoo maa fun yin se o , omo araye ko nii ko ohun yin o .
@fg1698 Жыл бұрын
Baba wa , ése gan ni sir. Agba yin adalé insha Allah Amin Kunfayakum. Éjo sie, gégé bi a se mo pe Ibeji ko lélo Adi-Eyan. Ejó sir, se oni inkan miran to a le fi rópó Adin Eyan yi? se a lé lo Anointing oil tabi inkan miran sir?
@mainoprah8346 Жыл бұрын
Thanks you sir
@LordlandAcademy-yo8hu Жыл бұрын
Agba ko ni tan lorile. Thanks
@OpeyemiOladele-qe2dt Жыл бұрын
Adupe gidi Gan ooo
@OpeyemiOladele-qe2dt Жыл бұрын
Yio MA juyin se...
@mark8923 Жыл бұрын
❤️❤️❤️❤️❤️🙏🙏🙏
@bellosulaimon192 Жыл бұрын
Thank you very much sir
@amaajanaku584 Жыл бұрын
God bless you Sir ❤❤❤❤❤
@badmusolalekan2502 Жыл бұрын
Eseun pupo Baba O
@aderemiosho1342 Жыл бұрын
Ibepe ako tabi abo
@ajattabolanle61610 ай бұрын
A dupe sir
@WumiLarbi-vo3tc Жыл бұрын
Baba wa idamun o ni bayin, ofa aye ko ni ba yin tomotomo. E seun Olorun oba lol le bawa dupe lowo yin sir. Mo se ise ofa ti oni efo yanrin ati orombo, Koda, mo ba ju be se royin re lo. Awon omo yin naa o ni damun o won o maa pade alaanu. Emi yin o gun. I were mi ni wipe edakun se adieyan nikan la le lo lati Fi re agbo Yi ni sir? Nje a tile le lo omi orombo bi?
@adebayofataiadetunji6257 Жыл бұрын
Ekaa funmi pls.eleyi ati oniyanrin tee so. Esee
@WumiLarbi-vo3tc Жыл бұрын
@@adebayofataiadetunji6257 E maa ja efo yanrin, e for dada, e maa lo Kuna, e wa fun omi orombo si, e ro Po e maa mun.