ASHIRI BI AWỌN ALFA NIGER!A SÈ LỌ LU JIBITI NI SAUDI ARABIA TU.

  Рет қаралды 4,391

Lady k News Carrier

Lady k News Carrier

25 күн бұрын

ASHIRI BI AWỌN ALFA NIGER!A SÈ LỌ LU JIBITI NI SAUDI ARABIA TU.

Пікірлер: 38
@titielias8600
@titielias8600 22 күн бұрын
They forgot the day that they will sleep that they will not wake up. The Almighty Allah is waiting for them. The time is coming.
@florenceadedeji3858
@florenceadedeji3858 23 күн бұрын
Mufti lwo gbo oro ase lenu mi gbogbo awon omo ile Kewu re mo tu won ka ni agbara Olorun amin ase Edumare
@adijatadesegun6879
@adijatadesegun6879 22 күн бұрын
❤11
@maryogunkuade2560
@maryogunkuade2560 23 күн бұрын
Lady K, Weldon. Please let this video go viral. This kind of thing should not be kept under the carpet any longer. We must deal with them so that we can move. God bless you. Happy weekend dear sister.
@johnbakare6702
@johnbakare6702 23 күн бұрын
Alfa alsunaa??????😅😅😅😅😅
@graceolushoto7115
@graceolushoto7115 23 күн бұрын
O sèun ni gidigidi ganni Oluwakęmi Ifęoluwa a.k.a LadyK to gbaski 💞💋💞
@estherewetuga8245
@estherewetuga8245 23 күн бұрын
Awon Oleeeee Afa asiri yin ti tu Eyin Oleeeee gbogbo yi Awon yahoo Afa Olorun ti mu yin asiri yin tuuuu Gbogbo yin ni e ngba iwo lowo awon Larubawa no ire ti pe e fr so gbogbo Yoruba di Musulumi Iro le la asiri yin ma na ti ni , ni Ase Olorun, Eyin Oleeeee nwo yi Yoruba Nation no going back Yoruba Nation is the only Solution
@mamaosun3587
@mamaosun3587 23 күн бұрын
Awon 419 gbogbo.
@johnbakare6702
@johnbakare6702 23 күн бұрын
Awon alfa waaa so wipe. ?????
@olufunmilayooniyo2469
@olufunmilayooniyo2469 23 күн бұрын
Awon Alufa ti won hun lo si mecca lododu OLE ti won ma lo ja ni ohun niyen won amasebi eni wipe awon nikan ni kan ni olorun fi kewu si lenu ase OLE hunla ni won barawo robbery won ama bu awon omo YAWU
@graceolushoto7115
@graceolushoto7115 23 күн бұрын
Gbogbo awón to nfi aye wa ta Ludo game ta card Uno ta awón oniruru ayo olopon ni Aşę gbogbo Orişa Orilę ede Yoruba Olodumare ma mu nwón, nwón mase ęşin aiyeraiye ni agbara Olodumare Aşę Edumare bę lo ma ri fun gbogbo nwón patapata Amiiin
@Omowunmi0412
@Omowunmi0412 23 күн бұрын
Awon Musulumi Nigeria nfi awon Larubawa lokan bale wipe Nigeria ma di Islamic Nation .Awon oloriburuku Afa
@graceolushoto7115
@graceolushoto7115 23 күн бұрын
Emi na ti ngbo oro pe nwón nfi wà gbà owo nla nla ni Saudi Arabia Oju ma ti nwón ni ęyokankan ni Aşę Edumare Amin
@johnbakare6702
@johnbakare6702 23 күн бұрын
😂😂😂😂😂
@olufunmilayooniyo2469
@olufunmilayooniyo2469 23 күн бұрын
Disgrace to Nigeria Muslim
@graceolushoto7115
@graceolushoto7115 23 күн бұрын
Idajo Olorun ti de si yin l'ori ninu odun 2024 yi na ko tun ni pę mo
@maryogunsina5066
@maryogunsina5066 23 күн бұрын
Awon Alfa elebo gbogbo.
@graceolushoto7115
@graceolushoto7115 23 күн бұрын
Abajo emi ninu nwón a ma pa malu 🐄🐂🐃 ati orişirisi ęran ileya bi męrin marun titi de męwa o ma ga oo 🐐🐑🐐🐐🐑🐏 ęnyin Omo yoruba ę dide ki a gbà arà wa silę l'owo gbogbo awón oşinwin arà won 😭😭😭 ikà ni gbogbo nyin koni yę gbogbo yin t'omot'omo t'omo'mo tirantiran nitori ika odaju ni gbogbo nyin ję odaran ęda si ni nyin pęlu ę fi Oruko awón eniyàn gbà owo ęnyin ati awón iyawo ati awón Omo yin ni ę na owo yi eleyi ko daa to
@KehindeoseniSaliman-ou4jt
@KehindeoseniSaliman-ou4jt 23 күн бұрын
Yoruba nation no going back
@graceolushoto7115
@graceolushoto7115 23 күн бұрын
Amiiin
@modupeolotu2918
@modupeolotu2918 23 күн бұрын
The same thing Emir oluwo is doing in Yoruba land in iwo, if we all recalled what his Canadian wife said that he is going to marry one of the Emir daughter from the north that they are one controlling Nigeria wealth and if he married one of their daughter that means he will be accommodated and be given oil wells for him to be wealthy and he will be accepted as one of them. All what mufti iwo is doing it just handwork of oluwo through the Emir of sokoto, that’s why federal government couldn’t handle their case very well, while they are promoting jihadist terroists Islamic war in yoruba lands most especially in iwo, in which I think the governor of Osun state should remove him asap before he causes major Islamic war in yoruba lands
@estherewetuga8245
@estherewetuga8245 23 күн бұрын
Awon Afa Oleeeee oni Dori dede Aduri yin o ni bo
@SolomonOlajesu-ul6zt
@SolomonOlajesu-ul6zt 23 күн бұрын
Ejowo seri opolopo awon odo omo musulumi ti won n gbo oro yi ki Olorun KEJI oye won si ejewo efu wa ni number Afaa olotito yi
@graceolushoto7115
@graceolushoto7115 23 күн бұрын
Amiiin yaa Rabbal Aalamiin
@loantha2996
@loantha2996 23 күн бұрын
Bambialah
@graceolushoto7115
@graceolushoto7115 23 күн бұрын
Kini o nşęlę ninu ilu ika ole odalę olòkanjua kini a se fun nyin nitori ę fę ni oro eyiti ę ko mo ęniti yio lo ni ęhin ti ę ba lo 😭😭😭 iru ęmi buruku wo ni o mba gbogbo awón ęda buruku yi ja na kini ganni se dàndàn ni nki ę ja ole ki ę pa iro ki ę to se reré tabi ni owo 💷 💰 ni aiye ni o masè fun gbogbo ęnyin ti ę hu iru iwa oşi ika ati buruku yi 😭😭😭
@user-fb5wt9uh2z
@user-fb5wt9uh2z 23 күн бұрын
Maami Nigeria is a muslim country in the world history okay. To Saudi Arabia Nigeria is their baby.
@graceolushoto7115
@graceolushoto7115 23 күн бұрын
What's this Alfa's missions and objectives on indigenous people of Yoruba precisely on Nigeria as a whole kini işoro gbogbo ęnyin Alfa ole olojukokoro oniwobiya olokanjuwa
@elizabeth.169
@elizabeth.169 22 күн бұрын
Saudi Arabia makes about $20 Billion from Islam pilgrimage EVERY YEAR, which means in the last 10 years, they’ve made $200 Billion. (Ghana + Kenya) yearly GDP summed together is not up to $200 Billion. Before COVID-19 pandemic, Israel makes about $7.5 Billion from Christianity pilgrimage EVERY YEAR, which means in the last 10 years, they’ve made roughly $75 Billion. (Rwanda + Malawi + Namibia + Senegal) yearly GDP is = $75 Billion.
@florenceadedeji3858
@florenceadedeji3858 23 күн бұрын
Gbogbo eyin oloriburuku Alfa ati lmamu tie lo ngba owo ni Saudi Arabia ofo lomi efo nse ofo ni gbogbo yin ma se danu tirantiran adabi tie ko ba lu jibiti lati gba owo ni Saudi nikan loku ase Edumare
@RemilekunAdeleye-ew4dp
@RemilekunAdeleye-ew4dp 23 күн бұрын
HNNNNNNNNNN
@ditty6828
@ditty6828 23 күн бұрын
Tori e ni won se nse waasi isonu. Ti won fe ki gbogbo southwest di isilamu. Business ni won nfi esin isilamu se. Tori e ni adepoju, jamiu, toliat Ogbomoso, daoodu ati oluwo se nso nonsense.
@warisjinadu6248
@warisjinadu6248 23 күн бұрын
Don't forget how much Yoruba in the diaspora will pump into 2024 ile ya malu. Awon fulani-Hausa with the backing of some oba and hidden Yoruba cow investors Lo ma je re e ju at the expenses of terrorizing and destroying Yoruba farmland In return in question mark 🤔👀
@FataouTidjani-tk3un
@FataouTidjani-tk3un 23 күн бұрын
Oloriburuku omo obirin yi bi ose paromo teni omo ologo ni yan Gbe enure sohun oro re ota. Asewo.
@ditty6828
@ditty6828 23 күн бұрын
🍿🍼 won ti gun e ni kese. 😂😂😂😂
Black Voters For Biden-Harris Coalition Launch
39:33
Roland S. Martin
Рет қаралды 1,2 М.
Como ela fez isso? 😲
00:12
Los Wagners
Рет қаралды 31 МЛН
Тяжелые будни жены
00:46
К-Media
Рет қаралды 5 МЛН
ДЕНЬ РОЖДЕНИЯ БАБУШКИ #shorts
00:19
Паша Осадчий
Рет қаралды 6 МЛН
JAPAJAPA TÍ DÁ WÀLÁÀ SI LE ÈGBÁ WA OO
38:08
Lady k News Carrier
Рет қаралды 1,6 М.
WOTOWOTO GBASGBOS DADDY G.O VS DADDY G.O
44:14
Lady k News Carrier
Рет қаралды 4,8 М.
ÈÈMÓ WÒLÚ AKỌBI DUPE ONITIRI TI SORO SITA ASHIRI TU 🤣🤣🤣
50:45
OGUN OUNMO  TI WON MA FIN SIWA LOJU NI OJU ALA
4:46
BABALAWO INTERNATIONAL
Рет қаралды 4,1 М.
APOTIERI TI LỌ FI ORI JA ILÈ AGBỌN, OTI PA EYAN.
36:32
Lady k News Carrier
Рет қаралды 6 М.
🍪 Compartilhar é Cuidar:  Biscoito que Ensina a Compartilhar
0:13
Músicas Infantis LooLoo Divertidas
Рет қаралды 124 МЛН
Ну Лилит))) прода в онк: завидные котики
0:51
БАТЯ И СОСЕД😂#shorts
1:00
BATEK_OFFICIAL
Рет қаралды 1,9 МЛН
🍪 Compartilhar é Cuidar:  Biscoito que Ensina a Compartilhar
0:13
Músicas Infantis LooLoo Divertidas
Рет қаралды 124 МЛН