Gbogbo won EKE! Awon ODE die si se gbekele. Nitori nwon mo gbolohun. EKE lo kun igboro bayi, afi ki Olorun gba wa lowo won. Ati awon pelu ti nbawon polowo lori Social Media. Awon ara Okere lo daran lowo won. Owo ribiribi ni nwon ngba lowo won. Sibe IRO la nba nbe..