Oh Lord, I am here tonight at the alter for deliverance, restorations and manifestations of our destinies, glories and blessings in Jesus name 🙏
@johnakanni628311 сағат бұрын
Arrows of stagnation, in our lives, come out by fire 🔥 in Jesus name 🙏
@johnakanni628311 сағат бұрын
Amen Amen Amen in Jesus name 🙏
@omoleadewoyin738613 сағат бұрын
I and my son are connected to this prayer ijn....amen . More anointing and strength sir ijn... amen
@bolanlenofiu268915 сағат бұрын
Glory be to God ooooo Out of the 3 things I wrote, God has done one out of it oooooo Hallelujah Hallelujah Hallelujah I've PATO confirm ni oooo More anointing, grace strength sir
@adeyemiileaje423816 сағат бұрын
Ni oruko Jeeesu, Emi Mimo ooo, ofa idaduro lara mi ati awon omo mi ba ina jade, gbogbo ofa idaduro ninu aye mi ati awon omo mi, jade loruko Jesu, iwo ofa idaduro ninu ise awon omo mi, ninu ogo awon omo mi, ba ina jade loni loruko Jesu
Ohunkohun ti aye se lati da mi duro tomotomo, ina Oluwa ba je lale yi, ohun elo idaduro ninu aye mi ati awon omo mi, ina ba won je loni loruko Jesu
@adewloeelijah594615 сағат бұрын
Myself and my children are connect to this altar of mercy ijn amen
@adeyemiileaje423816 сағат бұрын
Oluwa mi ooo, gbogbo ohun ti ota lo lati da mi duro, ti won lo lati da awon omo mi duro, Oluwa ki ina bo, Oluwa ba mi sun won danu, ohun ti ota lo fun idaduro aye awon omo mi, Oluwa ki ina bo won lara loruko Jesu
@adeyemiileaje423816 сағат бұрын
Gbogbo irin ise daduro ninu aye emi ati awon omo mi, Oluwa ba won loni loruko Jesu, gbogbo ohun ti ota se lati da mi duro tomotomo, Oluwa ki ina bo, Oluwa ba mi sun won deeru, irinse idaduro e gbina loruko Jeeesu
@fatimalassissi641516 сағат бұрын
Amen 🙏🙏 Amen jesu thank you jesu ogoôoooooooôogoooôgoôoo thank you daddy 👍👍🥰
@adeyemiileaje423815 сағат бұрын
Oluwa mi ooo moju to mi, tori awon to fe fi iya je mi, Oluwa bojuto awon omo mi, nitori awon to fe fi iya je won, Oluwa se amojuto mi tomotomo, ma je ki aye fi iya je mi tomotomo, baba bojutomi
@adeyemiileaje423816 сағат бұрын
Ni oruko Jeesu, Olorun Alagbara ooo, ohun ti aye ni ko se to n se, to n se awon omo mi, Oluwa ni ale yi ni ki o ba mi gbe, ohun gbogbo ti aye fi se mi tomotomo baba mi gbe mi loni, Oluwa gbe ogun aye mi mi patapata
@AmudatFunmilayo16 сағат бұрын
Hallelujah hallelujah hallelujah
@BukolaToluni16 сағат бұрын
Thank you Jesus
@abimbolavictoria830615 сағат бұрын
Oluwa Tina bo gbogbo ogun to dami ati omo duro loruko Jesu
@AmudatFunmilayo16 сағат бұрын
Aamin loruko jesu tomo tomo toko toko
@adeyemiileaje423815 сағат бұрын
Amin Jeeesu
@BukolaToluni16 сағат бұрын
Daddy e ku ise oluwa akotun agbara loruku Jesu krist