Ha! Saminu tun de, se alaba o ni pada si ese aroo e bayi 😮, hmmmm 🤔, e ku ise opolo baba opele oro, e ku ijo isimi, olorun a tubo ma ro eyin ati gbogbo sise yin lagbara, e ma je ko pe oo, ki episode mi to jade, o dabo 👋
@ominiradavid73103 ай бұрын
Ona saminu o dara oo Ologbon buburu ni Alaba fura oo Baba opele oro, episode yi o gun rara E jowo e ma se je ko pe rara ki e to fi episode to kan sita. Olorun a ma fun yin se o