Kabiyesi o! Ile Oduduwa koni baje ni asiko tiyin o.... AmiiiiiiiiiiN..... ikan ti àwon Oloro se yin koda rara o......
@godwinayoola5808 Жыл бұрын
Oloro kole wo inu masalasi lo, inu masalasi kise igbale oro, akole pin itan aja ki owa kan lmam, laye laye. Moranti lbadan nigbati awon imale lo ba ololu ja, emi kise oloro sugbon lati ayebaye ni elesin ibile tiwa, imale wa, onigbagbo siwa pelu, sugbon nigbati opin aye bati nsunmo diedie orisirisi isele loma sele. Sugbon nigbati awon agbofin ro wa ni ilu kini idi re ti awon eniyan mi fi losi afin Oba wa Oni lati lo ba ibe je tabi lati pa. Omase o awon eniyan mi segbe nitoriti odo won ti fe gbagbe orisun re patapata.
@cashlegitimate4283 Жыл бұрын
Thanks baba wa oni ife
@oluyemitobi5463 Жыл бұрын
Very good nice one good to hear that
@oluyemitobi5463 Жыл бұрын
Isese lagba
@omooluabiyoruba104 Жыл бұрын
Muslim people beg Yorubas and IFA ,before they came to Yoruba land and they knew Yorubas have their own religion before Muslim people came and Yorubas welcomed them just like the igbos and now the only pay back for our good is , calming our lands,destroying Yoruba religion by both Muslim and Christens….. we must start fighting back
@bamidelefestusoladimeji3358 Жыл бұрын
Muslims respect Ile ife culture, they don't need Islam.Respect the ile people's culture. Is not possible for Oro people to attacks innocent people.
@ifapriestoluwoefuwapeakomo4629 Жыл бұрын
Its not possible to not do nothing and going there to attack then. And we doing oro festival here to and Muslim going to they way and must of them join to celebrate oro festival. This story not clear. Something going on that they not saying the truth about
@bosederachealomole3356 Жыл бұрын
Se OLORO ni won ni abi THUGS? E ko koju ORO si Fulani agbenipa, omo Yoruba egbe yin ti oun gba adura si Olorun ki iyi pada rere lee ba ara ilu ni iwa buruku owo yin to si. Iwadi ti o daju gbodo wa ye, ki won si fi iya ti o to je awon odaluru ti won fe ma bo si idi oro lati fa ogun si ilu. Akoko ti to ki iya ti o daju maa je awon obayeje .