Asise ti otami yiose ti yiofilo ganu si ogba ewon olorun jekio ose loni 🙏🙏🙏
@akindelegiwa58743 күн бұрын
Amin ase wa❤be e ni ki o ri fun gbogbo awon ota emin naa ni agbara olorun olodumare ✌
@shorinolabayor1673 күн бұрын
Ashe o
@abiodunadekunle75424 күн бұрын
This is a great lesson to all our yoruba leaders that are in higher authority.
@abijoakeem30084 күн бұрын
This is pure Yoruba news per excellence ❤
@Ifaṣésin19735 күн бұрын
😂😂😂 Maa ran ẹ l'ẹwon, mo maa ran ẹ l'ẹwon ti padà ganu s'ẹwon ooo 😂😂
@oluwafemijohnmiracle98775 күн бұрын
😂😂
@adefioyeadebayoojudale37443 күн бұрын
Oloriburuku ni oba yi Infact kudos to you I love ❤❤❤ your news 100%
@SolomonAdegbenle5 күн бұрын
Omo ole Ifo, Eto ni kolo si ewon 🤣🤣🤣.
@Rashidi-en6ge5 күн бұрын
Hmmmm, ori ja jogun lo, All our kabiesi should be a good example to the citizens God is great
@oyeleketijani8475 күн бұрын
Oba oloriburuku koni jere omo lagbara olorun gege bi o se sepe fun baba yen oun lo ni epe re were oba
@beejayking4real4 күн бұрын
Hmmmmmm ! I have written quite a lot about this unfortunate incident on other platforms. However, your fantastic investigative journalism has really beamed a lot of light onto what is really happening. Kudos to you. Please dig deeper. God bless you. See, this year 2025, many supposed giants troubling the peace of this Country will fall from grace to grace. Mark my words. I write from Lagos , Nigeria. 👍🤝.
@adenikeopadara75615 күн бұрын
Can you imagine? He has no one to bail him, agba ofifo..... He just down graded himself 😂😂😂😂😂
@CassaJibola5 күн бұрын
Kosoba bi re Oluwa.
@ajewoleseunsunday4 күн бұрын
Thank you OGUN STATE GOVERNMENT ❤ GOD FIGHT FOR THAT BABA 🎉
@folasadeolayinka70874 күн бұрын
Oba awon were, ewon ni yio ku si, oba elewon.
@somidechristycole21114 күн бұрын
Gbogbo won o ni dagba lagbara Olorun 🙏
@aladjimoustaphaiguewassiou95765 күн бұрын
Eleyii kuro ni Iwadi ránpẹ́ óò,, iwadii kàn kò tún gbọdọ̀ ju èyí lọ mọ,,mo n gbádùn yín gbogbo yín ko ní ṣíṣe ní agbára ọlọrun ọba,, ilé iṣẹ yíì ko ni bajẹ oo
@BabalolaWahab-j5c2 күн бұрын
Ejowo ki ijoba wa gbawa Nan ilu Ife gbogbo awon oba Keke too wa ni Ife iwa ti oba ifounwn Nan ni won Wu ni ilu Ile ife
@gbemisolafakoya7663 күн бұрын
Wow this a pure yoruba news I really love this but this oba needs to be teach some lessons pls this man is not good to be king in my country at all ❤😂🎉😢😢😮
@AlayerogunOlusola4 күн бұрын
The man is full of pride .
@YusufMoromoke3 күн бұрын
If you do good you do it for your head and if you do bad you also do it for your heart 😂
@AkinsunlolaAkinlayo4 күн бұрын
Ojoba tan oun we awure,se fe di Olodunmare ni,ranti pe awon eniyan ni o joba le lori, Olorun loun fi eniyan njoba, pelu awon eniyan ilue toni imo to tu loye lati dari ilu fun ifokan bale awon ara ilu ati alejo to wa nilu, fun itesiwaju ilu ti yio mu idagbasoke wa,sugbon loni awon alaparutu ni awon ole afoba je ma nwa kiri tori ohun ti awon naa yio je,se eri oju yin bayi eyin oloba igbalode sio yin
@Funmat-n1x4 күн бұрын
Igboro ti su kabiyesi ni ooh
@omoshewayinka25815 күн бұрын
This is a lesson to other Obas
@salamititilope1375Күн бұрын
Beeni oro kabiesi ti se, sebi oko ti aba so mo ope, ouni ope nso moni pada.😂😂😂😂😂😂😂😂 Oluwa seun pupo. Ori Baba na kogbode rara ati rara.
@OlaOsunAbiodun5 күн бұрын
Ejoo ejekomaase faji lewan oba abu
@odunolaalli67735 күн бұрын
Beni o, faji gba ni
@oyeyemioluwatoyin24844 күн бұрын
That serves him right,I believe he will learn his lesson
@omisanmiolayinkaadesoji79855 күн бұрын
He did exactly like Oluwo but Oluwo can't video it like this, Oluwo have done something like this more than 5 times.
@AbeniTitilope4 күн бұрын
you are bloody liar
@qwertyi82824 күн бұрын
Bi gbogbo awon ọbayejẹ ti wọn pera ṣe hun se nìyẹn
@josephadebiyi81344 күн бұрын
Good job sir ❤
@ogunlanaolumike56984 күн бұрын
Thank God. My able and competent Gov. Dapo. God is with you
@rasheedalimi23322 күн бұрын
😂😂😂😂😂😂 Kabiyesi a pe lewon o.amin.
@OrigbemisoyeOluwaJenyo5 күн бұрын
Ibe lo ma ku SI lagbara olorun ko ni de
@labakefunmi73195 күн бұрын
Aye ti awon kan n yo o je, ni awon kan nje suuha bi Eni je isu
@seyioluwaseyin832319 сағат бұрын
Ogun state is not Osun state where Oluwo has taken a whole Yoruba race for ransome without any governor calling Oluwo to order. God bless governor Dapo Abiodun for his decisive action against Olorile of Ifo.
@leahayodele25265 күн бұрын
ARANSI NI KISE OJULASAN. . EYOLOYE .
@odunolaalli67735 күн бұрын
Gbogbo ikan ko ni aransi, ipo ma gun opo eniyan.
@ayodejiayodeji85065 күн бұрын
Ori Ade ti su ita niyen o.
@oyewole55305 күн бұрын
Unbelievable 😮😮😮😮😮
@ajisebiolaabiola54414 күн бұрын
Oba awon oba lo fi agbara re han oba yi, ko si eniti olorun ko le mu ati pe Baba JP to gbalori yen omo ile oluji ni Ondo state ni Baba yen, ki se gbogbo eniyan ni won maa gba lori , O lewu. oo
@Otitodamilare4 күн бұрын
Ori ade eleyi ti sun ita oooo. Eledumare gba wa ooo
@olatunjiakinpelu77995 күн бұрын
Oluwo partner. If the criminal becomes King.... Beru ba joba eeyan ibati kenikan.
@dorcasadeniyi80675 күн бұрын
Please ijoba emaje ko pada si afin oooooo
@anthonyadelakunadeyemi22904 күн бұрын
Amin
@akindelegiwa58743 күн бұрын
Odaju aloku olopa,, ere ise ti o fi aaro re se ni o ri gba ni osan re
@NoraJozy5 күн бұрын
This is a big lesson to Oluwo of Iwo land and to those that believe that they above the law of the land
@alliuibrahim7705 күн бұрын
Has Oluwo ever done something like this before now? If yes, kindly bring out your evidences to the world. Don't let your hatred for someone makes you look stupid before the world.
@TonyFulk-tv5 күн бұрын
Alafin of oyo has done worst than that he killed someone in oyo state and nothing was done so whats your point
@odunolaalli67735 күн бұрын
@@TonyFulk-tvthat was then o, not this social media era
@ibrahim250624 күн бұрын
What has this got to do with Oluwo of Iwo?
@OVERALLKING-x9f4 күн бұрын
Try to use ur sense once in a while
@adenikeopadara75615 күн бұрын
Radarada oshi 🙄 won ti se epe fun ni igbati on se olopa, iwa re ko le dara iru won ni o maa n ran alaise lo si ewon, abajo ti o fi so wipe oun ni o ni gbogbo olopa Nigeria😂 apaayan buruku ,ika
@akinolaoguntuase41845 күн бұрын
Ebiti to de sile fun okunrin yi ti yin le lori.
@adefilaadeyemi21304 күн бұрын
All his crazy boy should arrested, especially the one that slapped the old man from the back 😢😢😢 Once the police arrest the video man, believe me he would fished out the rest 😢 Thanks for the update
@rasheedalimi23322 күн бұрын
Awon afobaje lo da wahala sile nilu, nitori owo won fi were joba.
@FATIMAHZAKARIYAH5 күн бұрын
Back to sender ni olorun fise baba agba yen,oba olorile ifo ewon le maa kusi
@IbrahimTijani-il8mf5 күн бұрын
Amin
@oluwafemijohnmiracle98775 күн бұрын
Asè Asè Aseedumare
@adesegunadeleye44193 күн бұрын
Madarikan.
@adesegunadeleye44193 күн бұрын
Madarikan.
@elizabetharemu92294 күн бұрын
Ajuni lo e Fi eso se nitori Ile n yo eniyan.
@NasirAzeez-u4k5 күн бұрын
This kind of oba's are still many outside there, they believe when they are on Tron they are over everything, i have experience such from one oba like that which he was using ''IRUKERE'' to pursue me inside site😅😅😅
@adenikeopadara75615 күн бұрын
😂😂😂😂
@oluwafemijohnmiracle98775 күн бұрын
😂😂😂
@JamesWale-y1i4 күн бұрын
Mo ki Gomina lpinle Ogun state wipe won ku ise
@AdemolaShittu-iu7Ct12 сағат бұрын
Omode ojoye agba o jobi niwon fi se
@onigbindewale6351Күн бұрын
Yes tinse otipe, let others King call there self to normal and adjust there behaviour agbara just agbara lo .agbara of in si wa sibe , afield ti won ba fee lo asa loku
@MarkFolorunso-z3c4 күн бұрын
Let governor Abiodun dethrone him. Simple!
@akindelegiwa58743 күн бұрын
Awon iru eniyan bayi, ni igbati won ba wa ni enun ise ijoba pelu pelu ati pe aloku olopa ni won pe oba yi i haaaa, won ti ba aye awon eniyan je jina
@adeonaolafunke46494 күн бұрын
Asa si kan Kan ok. Osu won e kun. Bi osen selel ni ilu tiwa niyen ni Odokoro Gbede Ni ijumu local government of Kogi state..egbawa o
@ajibikeajibike41535 күн бұрын
Ajewipe sisesise ni won fi kan ye 😂😂😂
@FUNMIODOLE2 күн бұрын
THIS IS A VERY BIG LESSON TO EVERYONE IN THE CORRIDOR OF POWER TO TREAD SOFTLY
@FemyJudun4 күн бұрын
Olorun Alagbara lo sin de end of his era, Ewe ja lori Igi odi gbere, igberaga ni o siwaju iparun. He must be impeached.
@labakefunmi73195 күн бұрын
Tani to olorun, kosi ooh
@semiatsanni-mn5he3 күн бұрын
Asise ti gbogbo awon otami ati ota awon omomi yoo se ti won a fi fi ese ara won rinlo si ogba ewon niyen,ani se sise sise tinba aja to fin gunya sise sise tinba eran tofin gun iya e,ki o ba gbogbo awon otami ni oni ojo nla ojo jimoh oloyin Ase gun
@AdeyeyeGrace-kd6yuКүн бұрын
AMIN!!!!
@christianahogundele24274 күн бұрын
O ye ki won ko awon omo eyin oba na
@HammedSanwiyu3 күн бұрын
Dat is good for him
@Otitodamilare4 күн бұрын
Oba ti ko ni ase lenu,
@AdekanyeOlabisi3 күн бұрын
Apaniyan ni oba orile ifo ediko asasiko olorun lomun otimansetipe
@jonhsonakinbule35114 күн бұрын
Oba ori ade wọ cell !!! what an embarrassment,he should never return ho that throne again.after the six month suspension.
@mustaphafabiyi76774 күн бұрын
Ase agba ofifo ti e ni. Ko si eni to fe duro fun pelu gbogbo gira gira e. O maa pe lewon bi obo. Ohun to maa daa ju ni pe ki ijoba roo loye. Ko ye loba rara.
@itunuoluderu49114 күн бұрын
Abeg no call am kabiesi again jo call am semiu
@estheradeyemi17843 күн бұрын
A lot of tugs are now made kings. In fact, the entire Nigerians usually excise evil authority over the poor people they rule over. This will serve as a lesson to him and other power drunk Kings.
@kehindebellosikirubello9893 күн бұрын
Awon ile Yoruba ninuwon agbero lopo ninuwon biwon see ngba ile onile pelu ajagun gbale niwon see huni Ara ilu Lara wonpobe pelu iwa Buruku Nile Yoruba kakiri. awon oba north Joni iwaburuku bayi.
@iyaboadeyilola63943 күн бұрын
Semiu oshi tio ni ajeseku awon alale ti binu sii
@labakefunmi73195 күн бұрын
Hmmm, olorun mo be o maje ki nsise laye .
@Iyabode-Kaykay4345 күн бұрын
Ki kabiyesi ma Jaye oba ni ogba ewon ni ilaro😂😂😂😂😂😂
@angievarona11815 күн бұрын
Haaààa Olorun mo be ma je sii waa hun
@OlaideOlajide-e5fКүн бұрын
Ema dawon loun
@olasupojimilehin24772 сағат бұрын
This is the reason we against being crown any young nd reach guys as kingi think the king is arrogant, maybe because he have money or what he will also see rederede i his life too,if he did not go to prison for all his activities the remaining ones will not learn.the world is really going to an end seriously.i don't know while they will give them king in the first place what a greedy life.Our Governor should retrieve the OPA ASE from him nd detrone immediately
Kabiesi olosi yen loni gbogbo epe e lagbara olorun.
@IdowuIsaiah-q3l2 күн бұрын
Dis must be a to others, pls be causion because of tomorrow.
@FunmiAjayi-vy5sf2 күн бұрын
Eleyi kii se edi rabi asasi rara iwa re ni
@TobaBolarinde4 күн бұрын
Oba eranko
@oluwakemisola-s1o3 күн бұрын
Oba orile ifo ti lo ganu si ewon
@salakoolasunbo10855 күн бұрын
This is not the first time, what about Rasheed of iwo, sebi ohun papa gba Oba biti e ni eti ri
@dhanielstravelsandtours6731Күн бұрын
Yoruba new sweet pass English normal
@OniyideAbidemi-z7u5 күн бұрын
Amugbo
@genesisworld-zc5imКүн бұрын
Good example. He's not above the law, but in benin, they'll keep supporting their Oba upon his wrong and evil deeds. How would that place develop when the majority are ignorants? I know they will rain insult here in the comment section 😂😂😂.
@SakariyaRidwan-oc2fj5 күн бұрын
It's well 🥲
@Omoobaadekunle5 күн бұрын
Ese ooo ni iwoyi temi ki won je ko fo oju be e won odun meta pere ako awon oba alabi ki ta Lori ilu
@moriyamooyenuga66564 күн бұрын
O better ki won yo oba yi danu. Ki won
@adenikefayose98783 күн бұрын
Oloriburuku ni oba yi. Thugs ni. Ki won kuro lori oye. Awon Iran jati jati
@Youtuber-ux2og3 күн бұрын
Na retired police Sargent
@monisadeadegasoye11675 күн бұрын
Abraham Areola omo Ile-Oluji in Ondo State
@monisadeadegasoye11675 күн бұрын
His name is not Aarinola
@JamesWale-y1i4 күн бұрын
Mo ki Gomina lpinle ogun daradara wipe won ku ise o
@Criticalthinking015 күн бұрын
Kings as of today's Nigeria are the custodian of our culture and nothing more. No Nigerians is a subject of any King. Nigerians are citizens not subjects. If you know that, report any misbehave King or Kings to the authority.
@oe65265 күн бұрын
It's not possible! Police don't arrest the day, ojo ko se so lokun. The wind doesn't go to jail (ategun ki nsun cell 🛌) Eyin ara orile kabiyesi alashe igbakeji orisa ma pada si afin in 24 hours; awon alale ma gbe marafoka jade in 24 hours! Oba olorile ma ni, kabiyesi alayeluwa to ba lori IG of police and his boys 👮♀️ bi adiye 🐓 saba lori eyin 🐣
@odunolaalli67735 күн бұрын
Dey play
@adenikeopadara75615 күн бұрын
😂😂😂😂
@foyekealawode49635 күн бұрын
Igberaga ni
@AkinleyeIssa-qm3cx4 күн бұрын
Sebi asofunyin Kosi oba Nike Yoruba Dry iyp iyawa module onitiri Abiola ati akinola omokore eku ise Iran wa awon oloribu gbogbo