Very good message, igbarumole a tunbo maa se alekun ogbon fun yin
@oyatope_alase10 ай бұрын
❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤
@adetutuadegesin711710 ай бұрын
Baba Takutijesu IGBA irumole àà wàá pelu yinnn.Ase Edumare
@olufunkeojeleye720510 ай бұрын
Even d white has odu under Oworinsogbe dat make them excelled l learnt dat today.
@oyatope_alase10 ай бұрын
Orunmila ni o da ifa fun awon oyinbo wipe won ma se ohun ti o ma jo omo ara aye ni oju. Won a ma ko ile rebete ni ori rebete ati beebe lo. Ogbo ato ❤
@Nosirudeenadeleyeadewale9 ай бұрын
Alabosi o ni Jere ise.owo e,opuro koni jere ise, owo e.Islam lo nbi baba taku ti Jesu ninu,igbehin alabosi o ni da
@nurudeenbabanla936510 ай бұрын
🙏🏿🦍💯💯💯💯💯💯
@adebanjoogunsegun421110 ай бұрын
Ko si ikan to jè èmi mimò ni ilè irumòle yoruba èmi oshà egun ilè babanla wa lo gbe uin to ba ti jè òmò karó ajire oooo mose orimòlade baba è babalawo ni ooo ayò babalòla baba è babalawo ni ooooo ègun osha yè lo fi gbe asha ajoji ga oooo ko si ikan to jè èmi mimò ooo ni ara awa òmò irumòle oooooooo to ba ti jè yoruba oooooo
@bunmiadeyinka815210 ай бұрын
More wisdom Ifagelist
@olufunkeojeleye720510 ай бұрын
Owe poju "inu ni inu bibi ti bere ko to han loju"
@olufunkeojeleye720510 ай бұрын
Adupe lowo BabatakutiJesu
@michaelbabson266310 ай бұрын
❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤
@adenijiakinsemoyin940810 ай бұрын
Lakaye re koni baje, layelaye pelu akiyesi to pe wa si. Ase n'tedumare. Isese koni parun layelaye Ase Edumare!
@bunmiadeyinka815210 ай бұрын
Kootu-ojire is not kaaaro oji re
@oluniyiprosper306610 ай бұрын
Hmmm. Odofo oro
@adehamadeham594410 ай бұрын
Ifangelist, Se e si nigbagbo ninu Nigeria ni? Abi e kanse Oju Aye? Nitori gbogbo Atejise(Message) yin si Orilede Adanu Nigeria ni ki se si gbogbo Iran/Omo Alade lapapo rara