Obirin loma nba Ogun opolopo awa Alagbara je.Idi ti amanfi nlo eyonu lo inu Igbo
Пікірлер: 49
@oludjobimuhammad16548 ай бұрын
Olotu eku eto olorun yoso agbara dotun ❤❤❤🎉🎉
@BikearTv8 ай бұрын
Ase wá! Ojú kọ́ni tiyin lagbara Eledua
@wurageneralmerchandise69357 ай бұрын
Ogun nan ni Ori sebe ati owu dudu ATI owu fun fun that stuff confirmed I tasted it in secondary school
@BikearTv7 ай бұрын
Agba yín yo dale lagbara Eledua sir
@Mathew598 ай бұрын
Good morning it’s has been a long while I seen your video welcome back ❤❤❤sir
@BikearTv8 ай бұрын
Adupe sir
@olawaleakanbi30998 ай бұрын
❤❤❤❤ekuse oooo yio ma juyin se oo
@BikearTv8 ай бұрын
Adupe sir
@TheAyanrinde8 ай бұрын
Olootù ekù Oduñ.uñ akù iyèdun ajindè aarà yiò mà à jè fun un yin atì emì nà..e fun un wà nì apà kèjì etò yì ò..làì pè è
@BikearTv8 ай бұрын
Ibà Ọlọ́run, Ibà yín sir.
@dadaabraham50638 ай бұрын
Well done Sir
@BikearTv8 ай бұрын
Eseun lopolopo, sir
@OmidijiOdunayo8 ай бұрын
Eyin Oniroyin Iwonba Lo Ye Ki E Ma Se Iwadi Ba Awon Asiri... Gbogbo Bi Iwo Naa Ti Nbere Asiri Yii, Gbogbo Asiri To Wa Lara Re Ti N'baje.. E Sora Fun Awon Ibere Yin..{Olorun Oba Eleda Ohun Gbogbo Lo Ma Nfi Asiri Ikoko Han..
@BikearTv8 ай бұрын
Eseun sir
@phoenixabbey92038 ай бұрын
Mo feran ogun Oni ito fun idabobo ara ni orileede taa wa yi ooo
@BikearTv8 ай бұрын
Odara sir
@phoenixabbey92038 ай бұрын
@@BikearTve Jowo Bawo mo se leri yin basoro labe aso
@johnajanaku8 ай бұрын
i love your program
@BikearTv8 ай бұрын
Adupe lowo yín sir
@thesleepingbeauty-ts8ey7 ай бұрын
Eku ise takuntakun, olootu. Ejowo, ti e ba n s'oro nipa awon eranko won yi, e maa fi aworan wan han ki awon omo yoruba le mo eran to n je bee.
@Sterling988 ай бұрын
❤❤❤❤
@BikearTv8 ай бұрын
We love you too, sir. Ojú kọ́ni tiyin lailai
@olusegunajibade20248 ай бұрын
E ku ise o, Olorun Oba a ma fun yin se
@BikearTv8 ай бұрын
Ase wá Baba mi
@josiahadeleke51518 ай бұрын
Mo gbadun itan elegbede ti eso fun wa. E ku ise
@BikearTv8 ай бұрын
Adupe lowo yín sir
@isaacmax88018 ай бұрын
Eku eto olotu. Sugbon, you could have let baba skip where he had to described how incision with voice commands are used. Gbogbo aso ko la sa loorun. Once you let the enemy within Yoruba land aware, they will go and look for the antidotes to subdue the effect of the voice commands.
@BikearTv8 ай бұрын
Eseun
@olalekantenten45223 ай бұрын
E jo wo mofe ogun oni to...plz i need his number
@BikearTv3 ай бұрын
Visit Bikear TV on WhatsApp on 08065633424 for necessary steps
@PopoolaFaruq-k2z8 ай бұрын
Edi de fun Ile ekiti 😢
@E.wakanda.U-S-Afrca8 ай бұрын
Eku ise Eku igbiyanju
@BikearTv8 ай бұрын
Adupe fún Ife yin fun ikanni yi
@JoshuaGabriel-i1y8 ай бұрын
Eku ise opolo eledumare ama Fun yin se ASE
@BikearTv8 ай бұрын
Ase! Oba Oke kọ́ni fiyin sile. Eseun sir
@yekeensamad93198 ай бұрын
Se looto ni ti ara ba so kulukulu ogun ti baje niyen sugbon awon aisan kan na wa ti mon mu ara so kulukulu
@BikearTv8 ай бұрын
Ifura logun Agba
@LewisMuturi-b7u8 ай бұрын
E KAARE EYIN OMO YORUBA ATATA
@BikearTv8 ай бұрын
Kabiyesi o!
@olurantiomolara7 ай бұрын
Ibeere yi ti npoju
@BikearTv7 ай бұрын
Odara sir
@BD-nn3fq8 ай бұрын
Point of correction 'Agbara Satani" and not ESU
@BikearTv8 ай бұрын
Odara sir
@odunayokawojue4262Ай бұрын
Eeyah 😂😂😂
@sundayolowoyo9178 ай бұрын
Stop disturbing Baba jare, why are you pushing him to expose his secrets?