Aisan koni je tiyin lashe ELEDUMARE 🙏🙏🙏. Oodua nation lanfe. OLUWA ALLAH SWT bawa se oooo asheeeee
@margaretibijoke49734 ай бұрын
Olorun yoo fere si ise takuntakun ti eyin omo Yoruba atata n se.🙏❤️
@adekunleezekiel29014 ай бұрын
😂 They are joking YORUBA NATION NO GOING BACK OOOOOO
@comfortfamiwagun6714 ай бұрын
E see eee
@mamaeso77054 ай бұрын
God would protect all of us and deliver us all from the wicked law in Nigeria by the grace of God.
@bisolawe19964 ай бұрын
It is well with you mr omiyale eo ni se lasan Almighty God will have his way for yorubas inJesus name l pray for your quick recovery you are heal in Jesu Jesus name amen we shall triumphs No weapons form against you yorubas shall progress 🙏 amen
@veronicaaduVBA4 ай бұрын
Amen and Amen
@christianahogundele24274 ай бұрын
Yoruba agitators will not die IJMN 🙏
@estherewetuga82454 ай бұрын
Iku kan o ni pa enikeni ninu yin A yunlo A yunbo ni owo yun enu Amin 🙏 Abo Oluwa ti odaju a wa lori gbogbo yin ni oruko nla ti Jesu Amin 🙏 E ku ise, r ku ifi ti omo enia se Thank you all for everything God bless 🙏❤️
@mamaeso77054 ай бұрын
UP YORUBA NATION NO GOING BACK
@afusatarowolo22684 ай бұрын
AMIN AMIN AMIN OLOHUN OOO
@margaretibijoke49734 ай бұрын
Iwa ni baba awure, iwe ti opo omo Yoruba ka, itunije ati ika ni won fi n se si awon yoku😢😢
@christianahogundele24274 ай бұрын
Yoruba Nation no going back IJMN 🙏❤️
@MaryOdunuyi4 ай бұрын
Eku ojo meta oo, baba wa omiyale, eku eto ko ni re yin oo
@afusatarowolo22684 ай бұрын
OLOHUN ASE ALLAYKUN ALAFIA OOO SORRY
@modurodeoluwa4 ай бұрын
Awon oloselu Ole, Awon ika eda, gbogbo yin ati gbogbo awon omo yin ni olorun ma fi Iya je bi e se nfi Iya je wa,gbogbo yin ni olorun ma mu lase edumare amin
@estherewetuga82454 ай бұрын
Ademola Omiyale e ku ohun, r ku ise takuntakun Pele omo mi Oluwa a fi okun Sara ni oruko Jesus Amin 🙏 Yoruba Nation no going back Yoruba Nation is the only Solution Yoruba Nation ni awa nfe ni kiakia Ibukun ni fun Orile Ede Yoruba God bless Yorubaland Ago lo ma de Adie ni igbeyin
@ibrahimbadamasi12114 ай бұрын
I wish you quick recovery Omiyale inshallahu
@SolomonOjonla4 ай бұрын
Ko si iku kankan loju Baba wa Dr Sunday ADENIYI ADEYEMO lgboho Oosa Alafia ni oo ni oruko Jesus Christ.Amen.
@veronicaaduVBA4 ай бұрын
Amen and Amen
@veronicaaduVBA4 ай бұрын
Àwọn Awúsá ò lè dá dúró, Olè ni wọ́n. Ìdí nìyẹn tí wọn kò fi fẹ́ kí Yorùbá bọ́ kúrò l'óko ẹrú wọn.
@kabirballey34284 ай бұрын
Gbogbo ęda kęda toba ri Iran iro si Sunday Adeyemon Igboho osha tio wa so isokuso nipa Sunday Igboho osha,Ori arawon ni lo ma sęlę si , Ori arawon ni won fi ru ete ti won ba ro si Sunday Adeyemon Igboho osha ni titobi Olohun Oba Alaye to se ęda kowa wa odi ti Olohun Oba fi Di ile Aye ro oti di egun aye ati orun
@afusatarowolo22684 ай бұрын
SORRY OOO
@brightligan5194 ай бұрын
Awon ole, won gbagbe iran won,
@comfortadeleye1284 ай бұрын
You’re healed in Jesus name PIRITON LOROGO NJI AKI ROKUNRUN EIYE LORI ITE
@alabithomas19024 ай бұрын
Mo ri wipe national anthem eya meteta jade sowo kanna . Ijoba Nigeria si fo bi eyin tofo lai le se kojo
@henryidonije4 ай бұрын
Iro ni kii se iru ijoba ole lo ma a se iru of in be nilu yi.
@OmoleckJames-wz7od4 ай бұрын
Tobamato ogun odun si ogoji odun, eoripe Iran Yoruba, yiodeni abuku ninu Nigeria, Tori awon hausa ati Ibo pelu faulani, yioparapo, so Yoruba di eni ehin ni Nigeria, elokoosile