Jazakallah Khaeran Sheik Shakirudeen Okanlomo Adebare Emir Olohun ba wa se ike ati ige fun Baba wa Sheik Muydeen Bello Ajani ati gbogbo awon oku wa Oloriburuku aye ati orun ni o ma so isokuso nipa igbese aye ati iku Baba wa Sheik Muydeen
@issajimoh27013 күн бұрын
Wallahi, Sheik Adam Abdullahi Al-ilory ko kuku se won tabi se Baba ati Babanla Baba won ni ese kankan Ese ti Sheik Adam se won nipe, won ko won ati awon Baba won ni kewu Sheik Adam so awon Baba won di oni mimo Sheik Adam so won di Alfa Sheik Adam so won di eniyan gidi lawujo Sugbon Wallahi alaimore, afi ibi su olore, ota Olohun, oni ilara ni opolopo won
@OlaniyiSikiratou4 күн бұрын
❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤👍👍👍👍👍👍🙏🏻🙏🏻🙏🏻
@ashrafazeez73234 күн бұрын
Emir fitina people no day think like that they are sekiyu caucus