Baba Laji Abass, Yorubaland and Yoruba people will never forget you. We will eternally be grateful for all you do for us. Thank you for standing up for your Motherland. Yoruba will be free.
@adeyemoademolajammy20022 ай бұрын
TV is amouhun mu aworan ni yoruba re, radio is asoro magbesi.
@ademolaadeleke2002Ай бұрын
Thank you. I wanted to write that. Even though those things are not Yoruba inventions, Yoruba still have names for them.
@Sunkanmifemi-e2k2 ай бұрын
Ani ori awon Alfa kan ti gbale, won ti fori gbale ni kekere, Ni gba ti won jabo l'eyin Iya won.
@Challyboy9132 ай бұрын
Oloye Laji ori yin pe pupo. Ti eo BA si ni IPO ti ewa yii awon eniyan bi ajigini yoo ti te Yoruba mole.
@abebianike40492 ай бұрын
Baba wa laji Abass mo ko Orin fun yin oo baabaa ooo baabaa ooo baabaa ooo oluwaaa daa baba sii fun waa baba oo baba ooo baabaa ooo oluwaaa daa baba sii fun ❤❤❤❤❤❤
@salientabe11052 ай бұрын
One of the few best videos I’ve watched in recent times. Very detailed educative and historical.
@isholakoladesamuel34772 ай бұрын
God created each race on it's own and there is no confusion about it. Yoruba race is very superior to Arab race. Period. God bless you sir Ladji Abass
@felixsaka67762 ай бұрын
Alfa yi kise omo Yoruba ni. Ede Yoruba koiti ye. Imoran mi fun ni pe kolo ko ede Yoruba, kise ara wa ni. Omo tohun rin wa😂😮
@adeyemiadams8392 ай бұрын
OLORIBURUKU PATAKI NI AWON ALFA YII
@kehindejosephkashimawo94102 ай бұрын
Afaa yẹn kii se ojúlówó ọmọ Yorùbá. Bó ṣe nsọ̀rọ̀ pàápàá ti fihàn: ", ẹ̀yin Yorùbá".. Ti o ba si pe orí èèyàn dàrú.. Kí ẹnìkan máa wípé inú Lárúbáwá ni èdè wa ti wá..
@kamorudeenajimobi82392 ай бұрын
Radio is known as 'Asòrò mágbèsì" in Yoruba language and Television is known as "Amóhùn máwòrán"
@babatundeowolabi-l7k2 ай бұрын
Oponu ni awon afa rederede wonyi. Asa arabo ti yi won lo ri. Awon omo ale jatijati.
@yanickgana40282 ай бұрын
Eranko ni alfa yi ooo
@olaniyanadekunle87172 ай бұрын
A ni itumon fun radio(asoromagbesi) ati television (amuounmawonra)
@imamabdulrasaq4012 ай бұрын
Amu ohun mu Aworan ni Yoruba npe Television,,,, Asoro ma gba esi ni Yoruba npe Radio
@OluwanifemiOnafusi2 ай бұрын
Aare, Omo eru ni ogbenni yi ooo, kosi opolo mo oooo😅
@beatricemladipo25712 ай бұрын
Aare Opitan Onibode Onibode ile Yoruba, mo gbe fun yin sir 👊👊👊❤❤❤
@olalerelukman91202 ай бұрын
How can someone hates himself so much like this?Arabs can never denigrate his race the way some Alfa are disparaging our culture, because of crumbs, this is infeeority complex of highest order..I am Muslim and proudly a Yoruba man
@makindeoluwaseun67162 ай бұрын
Waa jere
@KKandu40402 ай бұрын
@olalerelukman9120: God bless you. All these so-called Alfas should just relocate to Saudi Arabia and leave us alone. They denounce their tribe because of money from SA, who will never give them citizenship. These Alfas did not fight it out with the Hausa-Fulani for not allowing them (Yoruba) to LEAD them in islamic prayers(irun) but are attacking Isese people. I hope Isese people ŵll start exposing them when they come for their help in isese ways. 😊
@IsaiahBabatundeOlatunji2 ай бұрын
Omo ale Yoruba ni iru awon Alfa yi. Larubawa je ede lasan bi Yoruba se je ede. Won kan nwa gbogbo Ona lati da ile Yoruba ru. Awon oponu
@KazeemBabatunde-my7ps2 ай бұрын
Amunku meko lawon eniyan wonyi
@Majority332 ай бұрын
Honestly, this is sad that some people are LOOKING for ways to denigrate their language, culture, and ancestors. These people need National Orientation Agency to habilitate their mentality. Many Yoruba Christians don't know what "sakat" or "karamo" is. Thank you Aare Opitan.
@Topdigitc2 ай бұрын
Alabuku, o bu u ku, ko kun oju osuwon.
@abebianike40492 ай бұрын
Beni bi iru iwo ajiginni oni laakaye rara opolo ee ti daru omo Ale omo iran ki ran ile Yoruba ma ba e jaa
@AdesolaOladeji-d8m2 ай бұрын
Gbagbo iran lagbaye ni won ni ede ti won❤❤❤❤
@AderibigbeKabiru-ov4kx2 ай бұрын
Television is call amohun maworan
@makindeoluwaseun67162 ай бұрын
Omo ale ni aringiniginiwoja yi o.
@Taiwo-x3v2 ай бұрын
Esin lo da ede wanu. Expecially esin awa musulumi. Gbogbo yoruba ko lonso asayan ede larubawa. It's high time they bring back history and authentic yoruba language to school.
@ademolaadeleke2002Ай бұрын
This is one of your best presentations.
@Challyboy9132 ай бұрын
Baba pasuma wa lati Edunabon nigbati iyare wa lati Oro, sugbon SA o Oro no opolopo ro pe o ti wa.
@OyewoleAwe2 ай бұрын
Most of these Alfas dey smoke igbo
@romainkoumolou97632 ай бұрын
Baba mo gbe osuba fun yin
@MikhailAwolowo-zm7fr2 ай бұрын
E jeki a bere lati ara oruko alfa yi. Se larubawa ni Ajiginni ti oun lo. Yoruba ni awon ti a npe ni ajiginni, aringinni, aringinni ginni woja.
@alowonlebadoo62452 ай бұрын
Challenge accepted gbe fun
@sikiruoluwasegun68042 ай бұрын
Aree opintan agbaye eku eto .Omo ale ni gbogbo awon atoun rinwa yi ajiginni se oruko larubawa. otun wo aso ofi o de fila abetiaja si.aree Oro eleyi iti ogede ni.koto ohun aloada be .ile toun toro .Omo alebe ni koiti dagba eko ti fi ojumimu han. Omo ale. Ponbele ree o. Aree ori Alfa yi ti daru now . koni lakaye . ko gbo agboye rara . otimu kolos ati ogogoro pelu sepe. Awon asiwere gbogbo wonyi.
@KazeemBabatunde-my7ps2 ай бұрын
Kosi lakaye kankan fun won
@uthmandragovic10102 ай бұрын
Alfa n dojú ti ijo musulumi Kò mọ n kankan
@KazeemBabatunde-my7ps2 ай бұрын
Aare poitan word wide ride on
@kehindejosephkashimawo94102 ай бұрын
Ajigini tòun njẹ́ yẹn, báwo ni ìyẹn ṣe papọ̀ mọ́ Lárúbáwá?? A rìn gìnigìniwọ ọjà..
@ademolaadeleke2002Ай бұрын
He should accept that he is a traditional worshipper (onisese) bcos that word is associated with traditionalists. Otherwise he should tell us the meaning of Ajiginni in Arab.
@adeyinkabenjamin47862 ай бұрын
Thank you, Are. Good lecture.
@mathewonilude37492 ай бұрын
Ajiginni aringinni aringinigini woja also is Larbawa Language ooo😜
@muyideenayinla21522 ай бұрын
God bless you sir
@MikhailAwolowo-zm7fr2 ай бұрын
Ni ede oyinbo awon eda ti opolo won ba ti lo si odi, ti won ko le da inu ro, nipa wipe ede elede ti ko opolo won lo. A npe iru eni be wipe o wa eurocentric. Gege be naa ni alfa Ajiginni, oun ti wa arabicentric.
@JosephAyanwola2 ай бұрын
Aare Opitan gbogbo ile ootu ife.mo gbe fun yin ooooooo.Haa,oga ni o.
@AjuwonOluwafemi2 ай бұрын
Awon alfa tio ni lakayakankan rara
@IdowuOgundaire2 ай бұрын
Edeman jorawon dada ikorira Lonyo bayi lenu ooo
@KazeemBabatunde-my7ps2 ай бұрын
Seria itumon ibawi
@abiodunolawoyin97742 ай бұрын
Yoruba ti shi omo gbe ni ile iwosan,omo eru ni won,eranko koni sai se bi eranko,eru shigidi.
@crownedking25672 ай бұрын
Well done Onibode Yoruba
@temitopeakindele35282 ай бұрын
Thanks you so much
@kehindejosephkashimawo94102 ай бұрын
Gbogbo agbada àti ìlẹ̀kẹ̀ yìí ńkọ́?,, Ṣé ìyẹn kii ṣe itọ́ka sí àṣà Yorùbá.. Oun tó ṣe pàtàkì ni pé kí Ìtàn Yorùbá máa tẹ̀siwájú.. Yálà inú ilé tàbí studio ni..
@beatricemladipo25712 ай бұрын
Aare Opitan, Onibode Ile Yoruba, e Ku ise opolo. Thank you for your efforts sir
@ganiyubadewa66872 ай бұрын
Alafia is equivalent to ilera. "Se alafia ni?" is equivalent to "Se ars le or Ara o le bi?"
@loantha29962 ай бұрын
Larubawa level, iro lasan
@ajibsononline37602 ай бұрын
Olorun a bukun fun yin, iku o si ni payin ati gbogbo ile yin. Bi ese n dabo bo awa omo alade Olorun Olodunmare ko ni fiku toya da emi yin legbodo. Olorun oni payin lekun. Eku ise.....
Which subject are you talking about? Who told you he passed Yoruba in WAEC? Nobody who passed Yoruba in WAEC can speak foolishly like this. Several of these words he is talking about, many Yoruba Christians don't know or use them. So it is foolish of him to say if Arabic is removed from Yoruba language, it is empty.
@AdeoyeAdegoke-i3w2 ай бұрын
This alfa didn't even understand Yoruba language on my own I've answered 90% of his questions
@OlawaleAkoidu-il7hn2 ай бұрын
huunmm baba wa opitan e ku ise takunrakun imoran ni o . e ba paaro. abebe owo yin yen si ti aworan yoruba to je ti Oodua. aworan ile arewa lo wa lara abebe yen . e se pupo.
@isholakoladesamuel34772 ай бұрын
Kindly give us your Yoruba name sir. I love Yoruba names. Thanks
@solabolaji53642 ай бұрын
Aafaa Ajigini je igbalode elesin ti o gba aagbon awon ti o jẹ eka Suuni ninu esin Islam jade wa. Koko ipinnu ti won ni ni pe, jihad esin ni won nṣe. Ìpìlẹ won ni MSS ti won gbe kalẹ nitori itesiwaju esin islam. Notable among the amir of that group is Aafaa Kunle Sanni &others. UI ni ibujoko awon al-sunna yii. Nitori eyi, oye nkan ti won nse ye wa daadaa! Ti o ba seése fun won ni , won i ba so fun wa pe iran larubawa ni iran wa. E seun Aare fun akitiyan yin. Ipa ko ni kun yin o!!! Yoruba dun!!!
@KazeemBabatunde-my7ps2 ай бұрын
Televison moun maworan
@feliciaadejoke2 ай бұрын
Gbogbo ede ti aunpe ni ede larubawa ti aunpe ninu ede yoruba tiwa ,beba pe ni iwaju awon larubawa won oni mo oun ti eunso tori pe biwon seunpe tiwon yato si ti yoruba
@Topdigitc2 ай бұрын
Karamo (Ayesi tabi iyesi).
@olupeters52012 ай бұрын
Gbe fun Aare opitan Oluko agba kaafata Ojogbon Abbas Thanks for accepting the challenge... I pray he accepts you Sir
@makindeoluwaseun67162 ай бұрын
Amen ni iwure
@abiodunolawoyin97742 ай бұрын
Amen means ashee,iwure mean prayer.
@AdesolaOladeji-d8m2 ай бұрын
Se ile yoruba nikan ni Gbagbo orile ede kakiri kosi wahala esin larin ara won
@Challyboy9132 ай бұрын
Abaya ati Agbada😁😁😁😁😁😁
@bashiruadekunle75202 ай бұрын
Mofiimu iseda oro oruko ni edee yoruba.
@Topdigitc2 ай бұрын
We have a big problem in Yorubaland and a serious work needs to be done. We are being attacked psychologically, territorially and culturally. The study of Yoruba language, culture and history should be made compulsory in our schools by including them in our school curriculum. Yoruba is under siege and our administrators need to act fast. Our forests are occupied by Fulani, our commercial centers are being occupied by Igbo traders, people don't mind selling their family compound to them. These charlatans calling themselves alfa are attacking Yoruba tradition, history and culture while our youths don't have a proper grasp of Nigerian politics and their own place in the scheme of things.
@loantha29962 ай бұрын
Well said, but elders will still stay mute
@ademolaadeleke2002Ай бұрын
It is not bcos of study of Yoruba in schools. It is bcos some people decided to accept madness with their religion. This man went to school and did Yoruba as a subject. He just decided to enslave his mind.
@mbayemamadu30282 ай бұрын
Alubarika- orire
@suadahitv16842 ай бұрын
Confirm saw❤
@saheedkolapo63912 ай бұрын
Well done Sir Aare, the question to ask all these Yoruba language antagonists is that: Did they write Yoruba in WASSCE GCE or NECO? If yes, what was their GRADE. It must be definitely "F9" . They all appear to be linguistically kids. Its only Yoruba Muslims use those words the most. It isn't Yorubaland universal words.
@AdeoyeAdegoke-i3w2 ай бұрын
Are opitan please you just wasted my data on this alfa he is even confused
@ARC.benedict-samson2 ай бұрын
You can't expect him to look away and allow him to mess up your language and culture, especially for the upcoming generation of GenZ
@ademolaadeleke2002Ай бұрын
@@ARC.benedict-samsonI don't think that is what he meant. He is just trying to emphasize the depth of the Alfas ignorance.
@uthmandragovic10102 ай бұрын
Àtùpà ni gbogbo babalawo npe
@suadahitv16842 ай бұрын
Ok sir ❤
@jamiuolalekan94422 ай бұрын
Ti o un gan ba mô itunmô orukô ti wôn fi un pé,eniyan gidi kan ki un ję "ajigini"oriki osha ęyô eko niyęn. "Emini ajigini arin ginin arin ginigin wôja....
@lateefbello51272 ай бұрын
Era ko no Akika ( eranko to o ma nfi owo boju)
@leoinfloe75302 ай бұрын
alaafia = ilera, igbadun, irorun,
@AlbarkaTech-d2p2 ай бұрын
Aponpo-Karamon
@KazeemBabatunde-my7ps2 ай бұрын
Radoi asoro magbesi
@imamabdulrasaq4012 ай бұрын
Alfa ti so wipe Kokin Se gbgb Yoruba Awon Elebo ni o nso
@Topdigitc2 ай бұрын
Karamo (Aponle).
@BrainChild322 ай бұрын
OGUN ISOYE FUN ONI CANA YII ⁉️😩🤦🏿♂️🤦🏿♂️🤦🏿♂️
@olawaleolamajestic7332 ай бұрын
KONI BAJE FUNYIN AARE OPITAN,
@isholakoladesamuel34772 ай бұрын
All languages do have "AYALO EDE" Yoruba is a race on it's own and nobody should attach us to the Arabs.
@makindeoluwaseun67162 ай бұрын
Television. Ero amohun maroran
@AdesolaOladeji-d8m2 ай бұрын
Beni kehu akun le ke yio gbo yoruba
@yanickgana40282 ай бұрын
Mo gbefun laji abbas
@lateefbello51272 ай бұрын
Eranko ni o nje Akika
@AderibigbeKabiru-ov4kx2 ай бұрын
Radio is call ero Asoro magbesi
@adewumiola80572 ай бұрын
Ki olorun bawa lora emi Are Laji Abas
@thoa.d34202 ай бұрын
Ofurufu, tabi kururu..
@bashiruadekunle75202 ай бұрын
Baba +oni+ ile=baba onile. A ge kuru re ni ;Baale.
@OlaAkin-zi1oy2 ай бұрын
E she baami
@KolaOgunbona2 ай бұрын
Aiule orun
@KolaOgunbona2 ай бұрын
Ajule orun ni wonpe orun
@imamabdulrasaq4012 ай бұрын
Alfa Jigini Ko palemo Kini yi wa to Kotokoto ni won so
@leoinfloe75302 ай бұрын
adua = iwure
@makindeoluwaseun67162 ай бұрын
How can someone hate his race like this
@azeezbabatunde95422 ай бұрын
I wonder o. Na wa for these almajiris.
@usmanwahab62622 ай бұрын
Eku eto
@yanickgana40282 ай бұрын
Odun wo ni kurani de si ile aye? Se yoruba lagba tabi kurani?