E da egungun yi pada si ibi ti e ti gbe o. Egungun ilu mi ni o.
@isedaleabinibiwa2020 Жыл бұрын
Lẹ́yìn ọdún kelòó🤣🤣?
@olalerelukman9120 Жыл бұрын
Egungun ile baba mi kobomoje orowusi
@isedaleabinibiwa2020 Жыл бұрын
Ẹ kú ìmọyì rẹ̀
@igeadubi58833 жыл бұрын
Alapansanpa ni oba egun oloore
@Imctv20223 жыл бұрын
Bẹ́ẹ̀ ni o
@sheyiadesuyi58223 жыл бұрын
Eku eto Ile oduduwa agbe wa oooo, yoruba Nation now,
@isedaleabinibiwa20203 жыл бұрын
Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun púpọ̀ o
@Ire...6838 Жыл бұрын
iro buruku radarada tepa fun rayin... Eeniyan nko lowa ninu e, ten ran aso fun..... Ogun ko Ogun ni.... Eri àwon Boko Haramu mu... Àwon ole eri won mu.... Koma da ki eniyan ma ni Olorun ninu aiye Ooooooo......