Baba ogbon awon agba Konibaje fun yin o yio ma ju yin se lase edumare.ejo sir se ti aba ti sare wo inu ojo ti a ja ewekewe ti a ba ri se ama jo ti ojo ba da ni abi lesekese ti aba ti ja ni a ma jo.plssss answer my question sir.
@JackOLOU Жыл бұрын
❤❤❤
@RufaiYakubA. Жыл бұрын
Eseun pupo baba ogbon. Ejo EBA was fi number yin sita ki a le dupe si
@onaolaposamuel4 ай бұрын
Eseun pupo sir
@aleshadekunle52583 ай бұрын
Eku ise sir ejoo se ale ja ewe si sile ti ojo ba ro ati wi pe se a ma gbe si orun ni igba ti a ba ti fe fi pa ara ni sir ejoo ??
@owolabiolushola2994 Жыл бұрын
A dupe pupo, alekun imo ati oye l'ase edumare.
@SundayOrire Жыл бұрын
Bàbá,e ku isẹ igba gbogbo, ọba tó dá ewé àti egbò kò ní sọ yin d'ero eyin lase awọn onile. E jọọ sir,mio mo phone number yin sir.