Ògbójú Ode : Iwin wá nínú Igi to wá leyin Ile mi títí di oni| Lọ́jọ́ tí age igi ni Ilu Eko Ende.

  Рет қаралды 7,600

Bikear Tv

Bikear Tv

2 ай бұрын

Iwin wá nínú Igi to wá leyin Ile mi títí di oni/ Lọ́jọ́ tí age igi ni Ilu Eko Ende, Isaasu Ọbẹ̀ wá nínú Igi tí age Àṣírí bí mo ńṣe nlo ẹran ETA láti ṣe iṣẹ́ bibo àṣírí fún àwọn alaini

Пікірлер: 35
@adebisiadedoyin8570
@adebisiadedoyin8570 23 күн бұрын
Eko Ende, Eko Ajala, Inisha, Okuku,. I remember back in the days.
@FolorunshoRonkeolufemi
@FolorunshoRonkeolufemi 19 күн бұрын
ASE ASE Ase
@ojojulius191
@ojojulius191 Ай бұрын
Please akika is pangolin if I’m correct right? Well done sir Eku eto We really love your program
@BikearTv
@BikearTv Ай бұрын
We love you too sir. Eledua yo tẹ yín siwaju
@olawaleakanbi3099
@olawaleakanbi3099 Ай бұрын
Iwájú Iwájú lopa ebiti resi Iwájú Iwájú ni bikear tv yíò ma lọ
@BikearTv
@BikearTv Ай бұрын
Ase wá! Eseun lopolopo sir
@TheAyanrinde
@TheAyanrinde Ай бұрын
Onì igbà Kan Nnà tì mò babà Kan sorò nipà igbinyanjù Orò ilè aiyè mì.. Amò Owò tì woñ bèrè fun nù tì pojù..
@BikearTv
@BikearTv Ай бұрын
Ok.May be the challenge is also big ma
@AKTVChennel
@AKTVChennel Ай бұрын
Bikear Tv i always proud of you
@BikearTv
@BikearTv Ай бұрын
Eseun Baba mi, Eledua kọ́ni fiyin sile sir
@opeyemioluseye3934
@opeyemioluseye3934 Ай бұрын
I like the Baba Oluode, he is soo confident... We want more from him. Weldone sir 🙌
@BikearTv
@BikearTv Ай бұрын
Eseun fun Ife yin sir
@SamsonMoses-wf3fv
@SamsonMoses-wf3fv Ай бұрын
❤❤Eku e,to iwaju iwaju ni I lese bekia television yio ma lo amin
@BikearTv
@BikearTv Ай бұрын
Ase wá! Adupe lopolopo fún Ife yin sir
@user-mi5lw8sj9v
@user-mi5lw8sj9v Ай бұрын
Hello, Oro Oluode Yi Lo Jeki N'mo Wipe Mo Ti Sunmo Iwin Ri, Ni Owo Ile Su Ferefe Mo Gbo Orun Re, Ori Mi Wu, Otutu Si Mumi, Oku Ni Mo Koko Ro Si O Nkoja Lo, Ara Mi Rewesi , SUNGBON Oro Baba Jeki O Han Simi Wipe Iwin Ni Ki Ise Oku Eniyan ... Kabiyesi Eleda Ohungbogbo.. Iba Re O To Komiyo. Ni Burkina Faso Ni O... Awise, Aminase 🙏.
@BikearTv
@BikearTv Ай бұрын
Aba yin dupe lowo Eledua, Oba to ni Aye kọ́ni pada leyin yin.
@TheAyanrinde
@TheAyanrinde Ай бұрын
Òlòotu eli isè ekù gbògbò làlà koko janjan lori Ishè atì ashà ilè yorubà..tì è ò fè è kò pàrun un Eledumarè yiò mà à fun yin sè. Mòfè pè e yin sì aki e kàn pàtaki nì ò
@BikearTv
@BikearTv Ай бұрын
Thanks . You may send such to our WhatsApp number 08075633424. Message only sir.
@adebisiadedoyin8570
@adebisiadedoyin8570 23 күн бұрын
one man catch Maagun(thunderbolt), it was in this Eko Ende that they separated them after all other voodoo peoples can't do it
@olayiwolaabiodun2754
@olayiwolaabiodun2754 Ай бұрын
E ku ise takuntakun
@BikearTv
@BikearTv Ай бұрын
Adupe lowo yín sir
@Mathew59
@Mathew59 Ай бұрын
❤❤❤❤
@BikearTv
@BikearTv Ай бұрын
Adupe fún Ife àti ifowosowopo yín. Àjíǹde ara yo ma je yín o
@emmanuelwakanda8360
@emmanuelwakanda8360 Ай бұрын
😊 ASE waa
@WeAreTrueAfrican
@WeAreTrueAfrican Ай бұрын
Eku eto. Ewa ati esin Yoruba ko ni paru. Thanks bro love your program. Will definitely support soon.
@BikearTv
@BikearTv Ай бұрын
Adupe fún oro iwuri yin
@AyotundeOlaoye-wg4bi
@AyotundeOlaoye-wg4bi Ай бұрын
Eku eto sir
@olusegunajibade2024
@olusegunajibade2024 Ай бұрын
Kudos❤❤❤
@BikearTv
@BikearTv Ай бұрын
Ibà yín sir, Eseun lọpọlọpọ
@truthsquestions1532
@truthsquestions1532 Ай бұрын
❤❤❤
@BikearTv
@BikearTv Ай бұрын
Ibà ńlá fún yín sir.Eledua kọ́ni fiyin sile sir
@TimileyinJohnjimoh-fm8lt
@TimileyinJohnjimoh-fm8lt Ай бұрын
Bikear kabo se dada le de se nkan se Omo re
@BikearTv
@BikearTv Ай бұрын
Lol.. Adupe ó, Layo lade ó!
@iteoluwa5198
@iteoluwa5198 Ай бұрын
❤❤❤❤
@BikearTv
@BikearTv Ай бұрын
Aki yin fún Ife yin.Eledua yo gbo Àdúrà yin sir
I Can't Believe We Did This...
00:38
Stokes Twins
Рет қаралды 95 МЛН
MEGA BOXES ARE BACK!!!
08:53
Brawl Stars
Рет қаралды 36 МЛН
Ogundigbaro akoni ode igba awase ni Iwo (Laji Abbas)
25:41
Itan Yoruba
Рет қаралды 51 М.
IFIOROWERO PELU AGBA OSERE 'OLOYE AJERE'
59:35
NigbatiTV
Рет қаралды 11 М.
1000000❤️ #shorts
0:18
北出 大周 Kitade Taishu
Рет қаралды 24 МЛН
Поймал редкий кадр🤨
0:22
FERMACHI
Рет қаралды 3,3 МЛН
Сын вернулся с войны и сделал сюрприз 🤯
0:17
Фильмы I Сериалы
Рет қаралды 4,7 МЛН