In Abeokuta, igba is the green garden egg while the white one is ikan.
@tiwantiwahub18 күн бұрын
@@loveandloyaltytotruth thanks for your contribution
@MariamMotunrayo-nr3vo19 күн бұрын
Igba call garden egg from Abeokuta
@tiwantiwahub19 күн бұрын
@@MariamMotunrayo-nr3vo ẹ ṣeun
@oladimejirasheedat845614 күн бұрын
Ikan, Osun
@timilehinajagunna293416 күн бұрын
Ikan is the real Yoruba word for it.. I am from Ikare Akoko, we call it Akan
@olawuyiolawale857319 күн бұрын
Igba la n pe ni'badan
@tiwantiwahub19 күн бұрын
@@olawuyiolawale8573 ẹ ṣeun
@LateefAyoola-s4b19 күн бұрын
Egba- Igba lanpe
@tiwantiwahub19 күн бұрын
@@LateefAyoola-s4b ẹ ṣeun gan-an
@minilo293517 күн бұрын
Ikàn ni won npe ni gbogbo Ọṣun.
@olamideamoke143419 күн бұрын
Egba - igba
@tiwantiwahub19 күн бұрын
@@olamideamoke1434 ẹ ṣeun gan-an
@adebiyiadeolu899819 күн бұрын
Ẹ kú ìfọmọ-nìyàn-ṣe, ẹ kú ọgbọ́n inú. Kò ní sú u yín láṣẹ Èdùmàrè. Àṣẹ Ìgbá làwa máa ń pè é ní ìlú Ìjẹ̀bú-igbó, ẹ ṣeun ṣeun. ÌYANU CHANTER ❤
@tiwantiwahub19 күн бұрын
@@adebiyiadeolu8998 ẹ ṣeun gan-an
@DawnScion18 күн бұрын
Ìgbà ni garden egg
@tiwantiwahub18 күн бұрын
@@DawnScion ibo ni ìlú yín
@adamabdulwasiu781614 күн бұрын
Ikan, Oyo
@mudathirsulaimankunle19 күн бұрын
Oyo: Ikan
@harunasalaudeen197619 күн бұрын
From ọ̀wọ̀ in Ondo State, we call it Ijẹgun (do-re-mi)
@tiwantiwahub19 күн бұрын
@@harunasalaudeen1976 ẹ ṣeun tí ẹ bá wa dá síi
@nnikkyharkengbala722818 күн бұрын
I rep Ibadan -igba
@tiwantiwahub18 күн бұрын
@@nnikkyharkengbala7228 ẹ ṣeun
@FadeyiOlaniyi18 күн бұрын
Ikan ni awa pe ni ilu temi o ilu ipapo ni mo ti wa ni itesiwaju L G
@tiwantiwahub18 күн бұрын
@@FadeyiOlaniyi ẹ ṣeun
@DawnScion18 күн бұрын
Mo ti kọ ẹ̀kọ́ tuntun loni
@DawnScion18 күн бұрын
Mi ò tí ẹ gbọ rí pé wọn ń pè garden egg ní ìkan
@bashirubaraqat21618 күн бұрын
Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà - Ùgbá
@tiwantiwahub18 күн бұрын
@@bashirubaraqat216 ẹ ṣeun
@mustaphahammed744219 күн бұрын
Igba la ñ pé ni ilu eko
@tiwantiwahub19 күн бұрын
@@mustaphahammed7442 ẹ ṣeun tí ẹ bá wa dá síi
@oropohafsoh19 күн бұрын
I know it to be igba
@tiwantiwahub19 күн бұрын
@@oropohafsoh ẹ ṣeun tí ẹ bá wa dá síi
@olaxalam19 күн бұрын
ikàn la máa n pè é ni Ikirun Agunbe
@tiwantiwahub19 күн бұрын
@@olaxalam ẹ ṣeun
@abbeylove493417 күн бұрын
No, is not igba is ikan, but in Lagos they use to call it igba, igba is different to ikan if you go to Oyo state and Osun state, igba ni eso igi kon tama nje Koro re lanpe ni iyere, iyere yan lafi ma nse iru tiwon npe ni Eegbon ni Ondo
@tiwantiwahub17 күн бұрын
@@abbeylove4934 ẹ ṣeun gan-an
@abbeylove493417 күн бұрын
@@tiwantiwahubolotu eku eto Olohun onije kobaje 🙏🙏🙏