Oluwasola, ojulowo omo Yoruba, omo Ijesa o sere , onile obi, o ti gbiyan ju tire ki olojo to de. A fi ti gbogbo eyin omo ale Yoruba ba jawo ninu OTE, ILARA, KENI MA NI, TEMBELEKUN, AGBEYIN BE BO JE, ODALE, KENIMANI ati IBODE GBIGBA NITORI IFE OWO😢ni Yoruba to le ri ominira gba ni owo awon obayeje ati amunisin wa