AARE LAJI ABAS SE AWON AFOBAJE YI KOLESE AIDAA FUN OBA YEN NINU IPEBI O
@MikhailAwolowoКүн бұрын
Itan miran titun ti bale si ilu Oyo. Itan gbogbo iwa buruku awon Basorun ilu Oyo ati awon Oyomesi toku, pelu ti eyiti o soju wa. Iyen ni ti Basorun ati awon Oyomesi alalubosa to nja yodoyodo lenu won, ti orun re si nta sansan kaakiri gbogbo agbaye.
@MufutauSulaimanКүн бұрын
😂 alubosa n run de ibiyi naa.
@suadahitv16844 сағат бұрын
Al hamdu lillahi 💖
@TopgistWorldwide-o9i21 сағат бұрын
It appears we now have the Governor's Oyomesi And The Selection Of Alaafin Of Oyo for students of History to study
@MufutauSulaimanКүн бұрын
Awa n gbadun yin, net work Dara Lori KZbin
@comfortadeleye128Күн бұрын
OPE FUN ELEDUMARE IGBA OBA TUNTUN ASAN GBOGBO WA OMO OODUA
@jimohnasiru819Күн бұрын
Congratulations.
@folorunshoolanrewaju591420 сағат бұрын
Congratulations to us! Se Oba Rasheed ti ilu Iwo wo IPEBI sha? Bcuz that man doesn't respect Isese at all.
@oyebamijimuhmeen181615 сағат бұрын
Yes, but he doesn't complete his days in ipebi ilé Òunto, according to reliable source.
@FadekeSanyaКүн бұрын
Aare congratulations ooo. Amo Eki Olota Of Ota o. Kilode?
@raoufmoustapha3649Күн бұрын
Are the same betrayers oyomesi who will organize the ipebi? I wish he is not under threat in ipebi.
@adeniyitemilola2560Күн бұрын
No oo the ipebi will be organised by baba lawo and awon afobaje
@raoufmoustapha3649Күн бұрын
Oyomesi are the afobaje
@ZiegboLafiabiliteКүн бұрын
@raoufmoustapha3649 Yes, oyomesi is afobaje, but they are not the one who will conduct the ipebi
@sangodipetope3683Күн бұрын
Awọn Afọbajẹ kọ ni yóò ro kabiyesi ni ipẹbi o, Awọn Alawo nla, Onisegun, Awọn iya mi Ọpaki, Ọlaki, Afinju niyẹ, Arogba Asọ ma balẹ, Oníṣàngó, Ologun, Oloogun, Oluọdẹ etc... Awọn Afọbajẹ gan yóò soro diẹ láti máa rí Kabiyesi ninu ipẹbi lai gbasẹ lọwọ àwọn tí o n SE ètò Ipẹbi ..... Isẹ Afọbajẹ ti tan lẹyin ti wọn ti yan ẹni tí yóò goróyè.
@raymytech17 сағат бұрын
Una go always find a way to defend rubbish. Hes not the chosen one. He's imposed