❤😂ko ni dat fun gbogbo Alfa ilorin ati emir ilorin
@fanuel74910 күн бұрын
Pardon .pardon 😔😥que que chaqun connaît son Dieu😇🙏👼.. Une question. Quand les yoruba quittait en Égypte ou bien en Arabi es ce qu il ya la religion ???..ou bien??? Tout le monde doit réfléchir. Profondément.. La divinité es la avant tout choses 😢😢😢😢😢
@AdekunleAdebayo-y5p10 күн бұрын
Ase oo
@KehindeoseniSaliman-ou4jt11 күн бұрын
Esin ABAlaye ni agba ni gbogbo Ile Yoruba patapata ooo Eni ABA LA ba ni babà ooo
@adewilliams811 күн бұрын
This mohammadans keep confusing their allah with Olorun. Olorun is everywhere, but allah is in the kaaba in Mecca!
@YouTubepolice___11 күн бұрын
Emir ilorin dy mad
@SholaOmotosho-r8d10 күн бұрын
Good of you shiek
@GraceMojisola-h9h11 күн бұрын
Awon werey😢
@ajebabs379610 күн бұрын
You for add were proper
@MoyoTaiwo-c4y10 күн бұрын
Koni da fun yin Koni da fun Allah yin Koni da fun emir Illorin Ema shofo tomo tomo
@florencebeauty732210 күн бұрын
Olorun Olodumare wa nibi gbogbo, olorun gbogbo agbaye,sugbon Allah ki i se olorun Orisa Arab ni ,Anobi wa fun awon Arab ,be ni awon irunmole wa fun awa yoruba.
@COYGDE188611 күн бұрын
You see this people, they are the one exposing themselves.. they always claim that the only religion known by God and that will be accepted by God … but God is now omnipresent 😂
@omisanmiolayinkaadesoji798511 күн бұрын
❤❤❤
@YouTubepolice___11 күн бұрын
Werey ni emir ilorin
@usmanwahab626211 күн бұрын
Awon alfa Omo fulani, awon omo omo Usman danfodo fefi Ogun esin gbale Yoruba ni, Awa taje Musulumi omo Yoruba, christen ati onishese agbodo wa ni isokan fun itesiwaju Ile Yoruba
@kehindeodumuyiwa418611 күн бұрын
Amo ale ni awon Alfa elebi. Iya lonje yin. Edewo ni awon olori buruku nse ni ile Yoruba. Awon eru aiye. Elo ku danu.
@BossaFola10 күн бұрын
GBOGBO EYIN ALFA TI E GBOGUN TI ILE YORUBA ADABI LO MA BI YIN LERE,
@YouTubepolice___11 күн бұрын
❤😂
@luqmanbisuga942611 күн бұрын
Iro musulumi level
@solabolaji536411 күн бұрын
Nipa eso won la o fi mọ won! Ti e ba mo Olorun ni tòótọ, e o je eni alaafia!!! Eni to gbe kewu le yin lowo, adigun jale ni! Nje eyin le mo Olorun nitooto?
@ajebabs379610 күн бұрын
All of una dey craze, mostly Muslims. You are all confused.
@florencebeauty732210 күн бұрын
Anobi wa ko si ni ile yoruba ni o.
@KehindeoseniSaliman-ou4jt11 күн бұрын
Afha kosi ija ni arin WA ooo esin woni esin tio koko de ile Yoruba SE esin ABAlaye ni abi esin ajogi mejeji ATO Hun Rin WA Lo koko de si ile Yoruba ni edami Lo Hun ooo
@hadi2artgallerytv10 күн бұрын
So, it's true that it's written in a book all those atrocities commited my Anobi 🤔😱 Hmmmmm it is finished 😮 👳🏿♂️👳🏿♂️👳🏿♂️🐪🐂🐂🐐🐐🐐
@olawaleagugom39511 күн бұрын
Ahha I never comment on any propagandist of all this Alfas insha Allah this alfa walahi talahi Allah will always accept your request 🙏this is type of people we want in the communities to give us what's truth in Islam many people have lost about because of ignorance please this alfa I love your truth verses thanks enlighten them more.
@adebayoyunus261010 күн бұрын
This is the highest order of ignorant.
@james_smith910 күн бұрын
Elebo taratara ni wa o, estop e o. Alfa e stop e! Kile fin sere ke? Muhamed wo, muhmed ti ko le bo bata ese Jesu. Olohun wa ni Ile Yoruba is not Allah. Allah is in the Kaaba of Quraysh tribe ni Mecca, awon lo ni Ile nla (Bayt Allahu) ni Kaaba ni mecca.