Olótùú, ẹ ṣe ìwádìí ọ̀rọ̀ yìí dáadáa. Ọ̀rọ̀ náà rújú.
@steveayoade575 Жыл бұрын
Good morning Awikonko,there is more to this issue than what this man is saying.I will urge you to please find out from the other party.I am also a stake holder of the Alaketu throne,though born and bred in Mushin Lagos State ,but presently based in Germany for over 20 years.I am from Mefu ruling house in Ilomu compound and the great grand child of Adebia the 42nd Alaketu of Ketu that reined from 1816-1853.We hope to hear from the other party soon
@Afro_Updates Жыл бұрын
Thank you steve.Are you from benin republic
@OLATUNJIOLAYIWOLA-qy2vs7 күн бұрын
This man is saying the truth,the new oba aketu cannot speak Yoruba fluently
@fabriceabidemiadetokounolo2351 Жыл бұрын
Sir OLOOTU eba sewadi Oro yi daada
@olasunkanmiolanrewaju5388 Жыл бұрын
Ileri Ọlọrun ni yóò wasi imuṣẹ
@kehindejosephkashimawo9410 Жыл бұрын
Òmìnira kọ́ ló pín àwọn Yorùbá sì ilẹ̀ Faranse, orílẹ̀ èdè Benin. Ìmúnisin àwọn tó pín wá bí ilẹ̀ Faransé (France) àti UK (ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì)., ní wọ́n yà wá sí ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀.. Tí wọ́n wá kò ilẹ̀ Ketu, tí ó jẹ́ ilẹ̀ Yorùbá kúrò lára ibi tí ilẹ̀ Yorùbá tá gbọ́ go àti ewé dé.. Ṣé òmìnira nìyẹn??
@fabriceabidemiadetokounolo2351 Жыл бұрын
Se sunday igboho tun je odale ni? Because oloye sunday igboho wa si odo alaketu ni ketu.
@adebolaayeni89627 ай бұрын
Se arakunri yi gbe ni Benin ri ni tabi Nigeria lo ngbe, nitori ko soro bi omo Benin, he speaks like a Nigerian, so I don't know why he is fighting for the throne, olootu e Bawa wa idi oro yi da da