We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
Пікірлер: 55
@saheedadewale59013 ай бұрын
God bless you 🙏 the king 👑
@Bisioluwa-wo7qe3 ай бұрын
Oloriburuku omo ale, akidanidani oba... Eni tara ile e lopor, koni rira bo da owon...
@taofeekakanni56723 ай бұрын
Amin ooo, kabiyesi
@Salamihikmat3 ай бұрын
God bless you sir Oba Iwo
@IsmailKenneth-d7o3 ай бұрын
Almighty Allah bless you Oluwo Oba tomo Olorun ododo.
@krystalamb7643 ай бұрын
Se allah na ni Oran ki olo jawon ni ole ni Ilu Oyinbo … eyin ole gbogbo yi
@saheedadewale59013 ай бұрын
Aameen yah Robih
@DadajamesAreo3 ай бұрын
Oluwo of iwo should warn his family in-law (fulanis) to stop killing our people yorubas, because they are the ones who the scarcity of food for we- yoruba race
@_Abdussalama3 ай бұрын
Allah á gbà ádùrá àti ibadah Ọba Olúwòó Rashidi Àkàǹbí. Kò ní ṣe Hájì Makkah ní èèwò gbogbo Mùsùlùmí òdodo o.
@ijoimoleolodumareagbaye3 ай бұрын
Ọ̀pọ̀ èèyàn sọ pé Ọba yìí ń mu igbó. Àwọn ènìyàn ní ọba yìí ti lọ sí ẹ̀wọ̀n rí
@FasasiOlajide2 ай бұрын
Kabiyesi o Baba ke pe fun o AMIN You're highly wlcm sir E tun bo ba wa ba president tulubu soro o ebi Yi po ju ooo
@moyomoyo48603 ай бұрын
Is it now that you oluwo just noticed that they have closed the border? You are only looking for the support and forgiveness of the Yorubas. Wèrè lo jo.
@IdowuadewuyiAmos3 ай бұрын
Olorun nikan lajulo gbogbo nkan patapata ki emi oba oogun dadaa kabiesi oo oba oluwoo
@NURUDEENBADMUS-q5z3 ай бұрын
Jazzakumllahu khaira oluwo, oba AbdulRasheed
@Rafiu-y6t3 ай бұрын
Oba Oluwo o ni le so oto nitori pe o fe omo fulani o yen lo si oko ko lo ma ba da oko so president Nigeria ko fun e ni owo lo ma fi da oko e se ki so fun president yiu president ko tax gbogbo awon Oleselu won San tax mekun lo je iya e mo bi won se ijoba ole ni gbogbo yin
@AnceintVeiledSecrets3 ай бұрын
Oloriburuku Oba were. How can a supposedly cultural protector be talking rubbish about same culture?. How can a criminal be a king sef?. Eranko ara e ro wipe gbogbo wa ni ori wa o pe rara. Ole (thief) na n se bi eeyan gidi.
@OlawoyinMaroof3 ай бұрын
Awon family re ni oloribuku
@AnceintVeiledSecrets3 ай бұрын
@@OlawoyinMaroof do you still live in Abidjan ,omo eran?. Eranko jati jati
@omololaamao70863 ай бұрын
Ododo oro, Kabiyesi ke pe
@adesinawasiu79933 ай бұрын
Eru ni bobo yi obo dudu
@Solomonity3 ай бұрын
He returned to Nigeria to advise us again to be patient with Tinubu. Hmmm.
@aladjimoustaphaiguewassiou95763 ай бұрын
Orí ọba yí ti burú,,kii se tulasi ni ki Musulumi jẹ ọba, ẹjẹ ki awọn ẹlẹsin ibilẹ ma jẹ ọba
@Fattylincorn3 ай бұрын
Orí baba e buru
@MaryAlex-sp7yz3 ай бұрын
@@Fattylincornode
@odunolaalli67733 ай бұрын
O fa epe si Ori Ara re, Iwo sepe fun oba? Se ko si agba ninu Ile yin ni? Always think before u write something. Elderly pple demand respect by our culture.