I tremble at your feet in praise to thank you for everything you've been doing and will do in my life and that of my daughter in Jesus name 🙏🙏🙏
@adeyemiileaje42387 ай бұрын
Lati oni lo, mo gba testimony, eri ojo to pe farahan ninu aye mi ati awon omo mi, lati oni lo ogun jija awon omo mi tan, orun wa si, a ri ogo wa lo, agbara to ni mi o ni lo tomotomo, Oluwa gbe mi loruko Jesu
@adeyemiileaje42387 ай бұрын
Ni oruko Jeesu, agbara to n gbe eri mi ati ti awon omo mi, Oluwa fi ina le won jade, ogun to so ara re ti centre point ninu aye emi ati awon omo mi, Oluwa gba won wo ile, gbogbo eni to gba ise ibi se lori awon omo mi, awon ti won sowopo lori awon omo mi, Oluwa fi ina le won jade, Oluwa fi ina gba won wo ile loruko Jesu
@adeyemiileaje42387 ай бұрын
Owo airi ti ko je ki n ni isimi, Oluwa ge danu, owo airi to n dena ire aye emi ati awon omo mi, Oluwa sa won pa, owo agbara to ndena iserere ati aanu lori aye awon omo mi, Ogun orun e ba mi lu won pa loruko Jesu
@adeyemiileaje42387 ай бұрын
Amin Jeeeesu
@adeyemiileaje42387 ай бұрын
Gbogbo owo airi to n dari ire ati ti awon omo si ibomiran Oluwa ba mi ge danu, owo airi to joko le ayanmo mi ati awon omo mi, Oluwa ba ge won danu loruko Jesu
@adeyemiileaje42387 ай бұрын
Emi ati ile mi ni ire kan, awa ni aanu kan, awa ni oore-ofe kan nitori Oluwa ti yan ogun eyin ti awon ota wa, Oluwa ti gbe ogun aye wa mi ni isegun, Oluwa ti fi ese wa le ori apata ki ese wa ki o mase ye loruko Jesu
@adeyemiileaje42387 ай бұрын
Gbogbo eni to n yo mi lenu, to n yo aye awon omo mi lenu, iku gbe won mi, eni to n yo ise mi lenu, to n yo ise awon omo mi lenu, to n ni aye wa lara, ile lanu gbe won mi, gbogbo eni to n yo akobi mi lenu, to n yo abigbeyin mi lenu, to n da ile aye won laanu, ti ko fi won lokan bale, loni ki won wo lule loruko Jesu
@adeyemiileaje42387 ай бұрын
Emi mimo gbe mi dide, gbe awon omo mi dide, owo airi to divert ire mi ati ti awon omo si ibomiran, Oluwa ba mi ge won danu, gbogbo owo airi to joko le ayanmo mi ati awon omo mi, Oluwa fi ida ina ge won danu
@adeyemiileaje42387 ай бұрын
Amin Jesu
@YusufAyisat-fj9up7 ай бұрын
Amen
@ibitoyevictoriaolowatoyin56567 ай бұрын
Amin, Amin, Amin ni oruko Jesu.
@adeyemiileaje42387 ай бұрын
Gbogbo alatako awon omo mi, ile gbe won mi, awon to n tako ogo ati iserere mi ati awon omo mi, ile gbe won mi
@adeyemiileaje42387 ай бұрын
Mo ti rogo mi loo, awon omo mi ti rogo won lo, Halleluyah
@adeyemiileaje42387 ай бұрын
Gbogbo owo airi ti ko je ki n ri iyanu, ti ko je ki ni isinmi, ti ko je ki awon omo mi lo, Oluwa ba mi ge won danu
@adeyemiileaje42387 ай бұрын
Loru oni, Oluwa ran angeli jade nitori aye mi ati awon omo mi, gbogbo eni to n da omi aye wa oru, angeli ibinu run won danu,
@adeyemiileaje42387 ай бұрын
Amin Jesu
@adeyemiileaje42387 ай бұрын
Gbogbo ogun ati idamu ti ota pese sile fun mi ati awon omo mi, Oluwa fe won danu loni, owo inira ati irira ninu aye emi ati awon omo mi, Oluwa so di riro, Orun ge won danu