Рет қаралды 314
Mimo ni Jesu Kristi,
Gbadura wa Olore,
Nigba taba sun mo O,
Gbo ti wa Jehovah.
2. Jesu Oba Imole,
Tan mole re sarin wa,
Ire l’Oba Oludande,
Gbo ti wa Jehovah.
3. Jesu Ore elese,
Dariji awa elese,
Ire loba Oludande,
Dariji awa elese. Amin