Oloun ko ni je ki Semiu pada sori apere yen mo In Sha Allah
@waleikujuni94635 күн бұрын
All the indigene & residents of IFO should write ✍️ petition against him to Ogun State Government ASAP and as a matter community safety
@funmilayobalogun84524 күн бұрын
Eleyii ki se oba o, babanla omota ni
@sobowaleamos.83983 күн бұрын
Olorun o oo😢😢😢. Semiu ti ba aye jè o 😢
@StephenAdelekeTemiosoro4 сағат бұрын
Tout lo ba yii,ki se oba gidi
@LuckyKolawole4 күн бұрын
Oba Lolo Oba jakujaku Oba Thout Oba gbatigbati Oba aronipin.
@beautywealth49354 күн бұрын
Ọba ti bọ lori Sęmiu yio, ki ifa yan ęlòmíràn lati fi ję Ọba, ki iṣe Ọba ti wọn maa fi owo gba lọwọ ifa ooo
@samsonakintomiwa9453 күн бұрын
Oba ofo
@TawaRufai4 күн бұрын
Seri eni to soro otito loso ni ilu ifo yen ko somona tole soro alabode poni abule ifo yen botiri botije gan ni arakunrin so gbogbo awon tora ile sibe ti oba yi ba pada de emi ko de rara onise ibi niati gbogbo awon odale toko mara eku ise onile yio gba Yoruba fun wa amin amin ❤
@AsabeAfrikaTV4 күн бұрын
Oloriburuku Oba Jaku-Jaku, Eni Abamo. Oba ofo. Can you imagine?
@Beatzbymuller4 күн бұрын
Long time sir happy new year
@Ire...68384 күн бұрын
Iran Oba Farao Ni...
@OmotayoOgungbenle-d3d4 күн бұрын
oba were oba ofo gbogbo ibi tiebakusi oloun amamunyin ni agbara olorun onide tobade iku oro lomaku onijere koniyee ni agbara olorun ajere ijere onijere onidemo o ewon lomakusi o
@MandiClement4 күн бұрын
Ifa mu èiyan kan, ęni k'o lowo, ki ni ę lero pe ęni ti o ni owo ma fi oju yin ri? Ilę Yoruba k'ole ni ilòsiwaju pęlu oun ti ęyin şe yi.
@babatundesokunbi32744 күн бұрын
Ere mi nbo kankan lati sofun olukaluku gegebi ise owo e. Olorun Oba ari ejo da fun awon alagbara aiye ti o nfi ipo ni awon eniyan laara.
@alabaadejumo5354 күн бұрын
Ko si ọba mọ ni ilẹ́ yorùbá, gbogbo wọn ma ku si ẹwọn, ni aṣẹ edumaré.
@habeeboki92284 күн бұрын
Ameen
@julietayeni16065 күн бұрын
With All His Money and Land he Has No one to Bail Him
@nuridinadams92194 күн бұрын
You read my mind, The idiot could not get someone to bail him for 5 million naira. I was at first sympathetic but after people's evidence showed that this idiot is a wicked soul with satanic and scary methods, I changed my mind. May he root in hellfire?
@ModupeEsho4 күн бұрын
Oloriburuku oba oshi
@blessedbabe33165 күн бұрын
Babanla Opressor Werey Eleribu gba ni oba Ifo yii .
@rukayatolabode67764 күн бұрын
Ola ori ori ti oba elewon semiu ti ran lo si orun aremabo semiu oba elewon koni de mo wa joba nilu ifo yi mo inshallah ola wutuba ti won ma ke lori gigun mererin oni
@taibatsuleiman47924 күн бұрын
Koni pada lagbara olohun
@gloriabamzy59574 күн бұрын
Amin
@Ukthorncarver4 күн бұрын
Meta Ni AYE: Afefee, Omi ati Iyepee. Bi o ba seere, META a je o se! Bi o ba se Ibi, won Aduro de o loju Ikorita META!!!
@OmiwoletaiwoJacob4 күн бұрын
Oloriburuku oba ifo
@sakamoses6065 күн бұрын
Imado ibase bi elede wan a baloje beru ba joba wan wu iwa ika.
@oniluproductions15 күн бұрын
Aja ṣ’omi la, koo ma baa la’ro, Nayan nayan ṣọ’yan na koo ma baa na ẹni Ọba, Ijimere ṣọ’gi gun, koo ma gun’gi Aladi.
@Abdullahi-pf1lu5 күн бұрын
😭😭😭😭😭😭
@taiyeajiboye39685 күн бұрын
Eni aiye ye ki o rora se,Oba semiu o beru olorun,sise sise ti o ba ewure ni o ba semiu.iwo omo kekere ti olorun gbe ola fun,ti o si ipo lo,idajo olorun lo se le lori bayi.
@adesuaolanrewaju7524 күн бұрын
Ode and mumu ni Awon ara ifo
@AdetunjiAkinbowale5 күн бұрын
OMO ALE ILU IFO NI SEMI.TI OMO ALE ILU KAN KO BA TI I DAGBA ILU YEN SI MA TORO ,OBA SEMIU JE OMO ALE TI O WA TI OKO WA BA ILU JE.AWON AFOBAJE ILU IFO KI WON SE ATUNSE.
@waleikujuni94635 күн бұрын
This Crazy king should be dethrone permanently. And he should remain in the prison for another 35yrs
@adewaleojo15395 күн бұрын
Eni ti eeyan o lee mu, olohun oba nii mu iru won.
@kafidriscomm56054 күн бұрын
I am a victim of that area too. I sold the house i was building and ran away. In fact i was begging to get paid any amount for the house. I got there rich and left flat broke. I saw hell before I was able to reset myself. Bad past experience.
@kemoblunsky37945 күн бұрын
Osinwin Oba oran 😅, SMH
@vivianegbumokei26032 күн бұрын
See hus chics like puff puff
@wyseroyideas5 күн бұрын
Iwo gan o safe o.be careful
@fafunshoolorunwa29294 күн бұрын
He want to famous and new he's famous 😂😂😂, OBA ELEWAN
@andrewolawoye61715 күн бұрын
Otilo
@oyewole55305 күн бұрын
Oloriburuku olosi traditional ruler omo ale Oloriburuku kabiyesi I hope he will never come back as kabiyesi again loruko Jesun he is such an evil spirit.
@AFOLABITAOFEEK-j9g4 күн бұрын
OLORI BURUKU OBA NI IRU RE KOLE SELE NI IBADAN ILU IFO TI DI ERU JEJE OBA YEN KO GBO DO JE OBA MO
@Ekùnomoobaolákilè4 күн бұрын
Is government not going to arrest those thugs and criminals working for the king?????
@moshiasarena4 күн бұрын
What are you people be doing all these days that you have not cried out
@Ire...68384 күн бұрын
Koni iro ninu oro yin. Gov wa Dapo Abiodun.... Emi ti sonu ninu ilu lfo o