Kabiyesi Oba Mufutau Kasali Moyegeso of Ijebu Itele. Kabiyesi se eranti junior yin Orenuga ni Ijebu-grsmmar school. E seun ojo o. Ojo a di ale oye a mo ori o. Kini o sele ti e fi m fopa Rin KABIYESI. Olorun a mun yin ni Ara da o. Orenuga lati América. Amin o.