Ẹ seun Bàbá mi, àsetì kìí bá ọjọ́, kí ọjọ́ kó má yọ,àsetì kòní ba yín
@alaodauda1439 Жыл бұрын
You are doing well my brother success is yours ❤️
@abdullahisade5127 Жыл бұрын
Okay
@tellaabudlakeem1795 Жыл бұрын
Anu Oluwa yio wa yin rii.
@gofarazeez7348 Жыл бұрын
🔥🔥🔥
@mujidatuadunni7228 Жыл бұрын
Amin Oyeolohun ko tope ooo
@olawaleakanbi3099 Жыл бұрын
Eku eto sir olohun asanu wa oo
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun pupọ bàbá mi, Ẹ kú ìfẹ́ Olódùmarè lára wa ✌️
@IyaboAdeduntan-bx5el Жыл бұрын
👍👍👍
@olawaleakanbi3099 Жыл бұрын
🤣😂😁😀😅😃
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Ẹ seun Bàbá mi, Ẹnu Ẹ̀rín wá kòní kan
@user-mx5ep7qi6f Жыл бұрын
Lot of laughs ..keep up the good work sir 😂🎉
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Thank you, I will
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Thanks
@ajeyemimayokun267 Жыл бұрын
All is well
@disuolayiwola9736 Жыл бұрын
Olootu, ti eba le pe akiesi Oba Oniba ti Ilu Iba si akiesi oro oko ti e fe ra, won yio se iranwo fun yin. "Jafo Authority" Alhaji Suleiman Adeshina, Oba Oniba ti Ilu Iba ni ilu EKO je eni to nife si iru eto yin.
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Hummm! Ó dára, Ẹ seun sir, Olódùmarè kòní da ẹ̀yin náà dá bùkátà yín, a gbọ́ ọ̀rọ̀ tí ẹ sọ ṣùgbọ́n ṣe ẹ mọpe ènìyàn kò lè kùfìrì lọsi ọdọ Alayeluwa láì jẹ́ wípé a ní ìpinnu láti pàdé (appointment) pẹ̀lú wọn? Àbí kíni ẹ rí si? ✌️
@disuolayiwola9736 Жыл бұрын
Ododo oro ni, ipinnu lati pade se pataki.
@ogunlekemayowa9057 Жыл бұрын
Emabinu wipe o kere
@Oluwasegun0 Жыл бұрын
I’m mad at you guys. You skipped my town. Ilaji oke 😡 😡
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Eyeah! Sorry not like that, ọjọ́ tí a fẹ́ lọ sibẹ wọn sọpe balọdẹ ibẹ̀ ti waja, wọn kosi ti jẹ òmíràn ✌️