Long time oye olohun gbogbo ile nko hope there's no problem
@OYEOLOHUN_TV10 ай бұрын
A dupẹ fún Ọlọhun ìyá mi, kosi laburu kankan má, Ẹ seun púpọ̀ ✌️
@vincentafeni10 ай бұрын
Oro agba, I learned something from man
@OYEOLOHUN_TV10 ай бұрын
Thanks sir my lovely brother, Thanks for stand by us, may God leave you not
@omolara999310 ай бұрын
It’s been a long time. I really missed your show
@OYEOLOHUN_TV10 ай бұрын
Ẹ seun @omolara9993 ojú kìí ti iná alẹ́, ojú kò ní tì yín láyé láyé lágbára Olódùmarè ✌️
@ogunlekemayowa905710 ай бұрын
Weldone sir may God bless your work, I am enjoying your program long time sir
@OYEOLOHUN_TV10 ай бұрын
Amen and you too, Thanks for the love ✌️
@OlayinkaAjasa-iy3mw10 ай бұрын
First person to comment, long time sir hope there's no problem sir
@OYEOLOHUN_TV10 ай бұрын
No problem at all, thanks ✌️
@olawaleakanbi309910 ай бұрын
Eku alobo ijo mẹta ooo
@OYEOLOHUN_TV10 ай бұрын
Àwa nìyẹn ooo bàbá mi, Ẹ seun pupọ, Ẹ kú gbogbo ìgbà wa, kosi post wa ti ẹ ko comment sabẹ rẹ rí, kòní bàjẹ́ fún yín sir ✌️
@ogunlekebosede637210 ай бұрын
Eku ojo meta baba wa oye Olorun gbogbo ile mi nko sir
@OYEOLOHUN_TV2 ай бұрын
A dúpẹ́ púpọ̀ fún Olódùmarè, àlàáfíà lawa ooo. Ẹ seun ✌️
@peterjoel630510 ай бұрын
Olootu, bawo la se le de odo baba?
@OYEOLOHUN_TV10 ай бұрын
Just contact us on WhatsApp 08069316812 to collect his phone number.
@gofarazeez734810 ай бұрын
Weldone sir please I need this Wolis number oye olohun. Thank you sir
@OYEOLOHUN_TV10 ай бұрын
No problem my brother, just contact us on WhatsApp 08069316812 to collect his phone number. Thanks ✌️
@OjuolapeAbeke-xs5lu10 ай бұрын
Weldone sir eku ojo meta se dada ni gbogbo ile wa o
@OYEOLOHUN_TV10 ай бұрын
Ẹ seun, ọjọ́ kan pẹ̀lú, àlàáfíà ni gbogbo wa wà ooo✌️
@akinolaadebayo456610 ай бұрын
Ogaoo, nkan nbe ooo
@OYEOLOHUN_TV2 ай бұрын
Nnkan nkan, ẹni to ba kan lo mọ, Ẹ seun ✌️
@MosopeoluwaADE10 ай бұрын
Too much fake of them. There is one who took my money and nothing update. You too dnt answer call. Even on what App. No response from u on messages sent to you. So hard to believe them
@OYEOLOHUN_TV10 ай бұрын
Who is not answer your call sir? And what's your name? Thanks
@KosenatAdufe-ty2lq10 ай бұрын
Eku eto sir olorun ama pa alo atabo yin mo
@OYEOLOHUN_TV10 ай бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun ìyá mi ✌️
@adedejiademola396510 ай бұрын
Hummm! This baba woli must be decent, weldone Oye olorun
@OYEOLOHUN_TV10 ай бұрын
Ẹ seun sir, bẹẹni ✌️
@AyindeAishat-dm7hc10 ай бұрын
Ekuse opolo sir olorun koni pada leyin yin ooo
@OYEOLOHUN_TV10 ай бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè àti ẹyin naa, Ẹ seun púpọ̀ ✌️
@abdullahisade512710 ай бұрын
Oye olohun bawo ni o olorun ama fu e se ooo
@OYEOLOHUN_TV10 ай бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun pupọ bàbá mi ✌️
@haqqiganiyy470610 ай бұрын
Long time sir it's been a while you post on your channel last hope everything is going well sir
@OYEOLOHUN_TV10 ай бұрын
No problem my brother, Thanks for your concern, may God bless us ✌️
@IyaboAdeduntan-bx5el10 ай бұрын
Otojo meta sir sekosi ikan olorun koni pada leyin yin sir
@OYEOLOHUN_TV10 ай бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun ìyá mi, kosi wahala kankan