OGBOJU ODE NINU IGBO || Idi ti a ko fi gbe fọ́nrán ìfọ̀rọ̀wérọ̀ pẹ̀lú àwọn ọdẹ síta dada mọ́.

  Рет қаралды 2,729

OYEOLOHUN TV

OYEOLOHUN TV

Жыл бұрын

#papaya #yoruba #asa #cute #edeyoruba #esabod #ewaede #kingsolomon #tundeednut #obasolomoni

Пікірлер: 65
@deobisi8483
@deobisi8483 Жыл бұрын
Love your unique style of expression more grace,👍
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV 9 ай бұрын
Thanks ✌️
@tellaabudlakeem1795
@tellaabudlakeem1795 Жыл бұрын
Olorun ko ni pada leyin yin (Amin)
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun pupọ Ẹ̀gbọ́n mi dada✌️
@IyaboAdeduntan-bx5el
@IyaboAdeduntan-bx5el Жыл бұрын
Weldone sir iyanu ma sele sir
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Ẹ seun ìyá mi, Olódùmarè Á fi ọ̀pọ̀ rọ́pò fun yín ma✌️
@AlabiAdekunle-jm5ln
@AlabiAdekunle-jm5ln Жыл бұрын
Amin sir, olorun a senirotun
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun pupọ ✌️
@florenceapete6068
@florenceapete6068 Жыл бұрын
Amen 🙏 olohun atubo ma fun yin ni alafia ati wisdom
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun pupọ A dúpẹ́ o✌️
@abdullahisade5127
@abdullahisade5127 Жыл бұрын
Weldone Oyeolohun TV
@alaodauda1439
@alaodauda1439 Жыл бұрын
Amen may God let your dreams come true sir
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Àmín ooo, Ẹ seun pupọ Ẹ̀gbọ́n mi ✌️
@anthonysmith3720
@anthonysmith3720 Жыл бұрын
My man, more winning in jesus name
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Amen o, Thanks boss✌️
@olawaleakanbi3099
@olawaleakanbi3099 Жыл бұрын
Ekuse oooo eku ìjọ mẹta oo😊
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Ẹ seun sir, ọjọ́ kan pẹ̀lú, Ẹ kú ìfẹ́ Olódùmarè lára wa ✌️
@haqqiganiyy4706
@haqqiganiyy4706 Жыл бұрын
Amen o may God crown your efforts sir
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Thanks a million. Amen✌️
@ogunsijijoseph802
@ogunsijijoseph802 Жыл бұрын
Eku igbiyanju sir olorun a gbe awon alanudide sir
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun aláàánú kòní jìnà sí ẹ̀yin naa✌️
@ogunlekemayowa9057
@ogunlekemayowa9057 Жыл бұрын
Amin sir olorun a ranyin lowo awa ne ma send iye taba ni
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun sir, a o ma retí ọwọ́ yín sir✌️
@ajeyemimayokun267
@ajeyemimayokun267 Жыл бұрын
Olorun A gba fun wa ema ri owo mi laipe but ejeki a mo bi owo yen bati nlo si ki a le mo ohun tama sesi sir
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun adua ti yin náà á gbà, moti rọ́wọ́ yín sir, Ọlọhun A fi ọ̀pọ̀ rọ́pò fun yin
@princesamuel5702
@princesamuel5702 Жыл бұрын
ASE
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Ẹ seun ✌️
@abassireakari2715
@abassireakari2715 Жыл бұрын
Olorun A se e ni irorun sir
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, ìrọ̀rùn lọ̀rọ̀ ti yín náà á já sí ✌️
@sukuratibrahim7414
@sukuratibrahim7414 Жыл бұрын
Olorun A gbadua wa sir
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun púpọ̀ ma✌️
@florenceapete6068
@florenceapete6068 Жыл бұрын
E ku ijo meta sir
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Ọjọ́ kan pẹ̀lú ma, Ẹ seun pupọ ✌️
@mujidatuadunni7228
@mujidatuadunni7228 Жыл бұрын
Oyeolohun mo ki yin sir olorun a jeki osese sir
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun ìyá mi, kòní ṣòro fún ẹ̀yin náà ma✌️
@abubakiriismail605
@abubakiriismail605 Жыл бұрын
Wow! Omo see proverb on top proverb I am one of your program lover be expecting something tomorrow sir
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Ẹ seun sir, àwa náà kọ́, Olódùmarè Ọba ni Ó ń dárà, a dúpẹ́ ooo✌️
@opeyemioluseye3934
@opeyemioluseye3934 Жыл бұрын
Olodumare yi o sina aanu re fuuyin. 🙏
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun mo dúpẹ́ púpọ̀ ✌️
@ogunlekebosede6372
@ogunlekebosede6372 Жыл бұрын
Olorun asiju anu re wo gbogbo wa amo mo ma ngbadun eto yin kima parọ àwa na a dasi lagbara olorun
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun púpọ̀ ma, Ẹ má bínú wípé ó pẹ́ kí n tó rí àtẹ̀jísẹ́ yín, un kò fi ṣe àfojúdi ooo✌️
@daudaalao1337
@daudaalao1337 Жыл бұрын
Oyeolohun eku eto sir ejeki a soro labe aso, olorun koni pada leyin yin oooo ama ju yin se
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Ẹ seun Ẹ̀gbọ́n mi, Ẹ kòní wá owó tì lágbára Olódùmarè, bí ẹ bá tí ń ta á, á ma jó, bí ẹ bá tí ń lùú á ma dún ✌️
@AderibigbeOlawale-ku6ej
@AderibigbeOlawale-ku6ej Жыл бұрын
May God provide for our needs I will send my token now sir
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, I really appreciate it sir, may God rewards you abundantly ✌️
@ayanlekeayanniyi6705
@ayanlekeayanniyi6705 Жыл бұрын
OK sir
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Thanks ✌️
@OlayinkaAjasa-iy3mw
@OlayinkaAjasa-iy3mw Жыл бұрын
Humm I understand you now bcos when you was request for money before you released the number that day its not clear to me. Weldone sir
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Ẹ seun ✌️
@gofarazeez7348
@gofarazeez7348 Жыл бұрын
Amin but I thought you have a car before?
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
No! Thanks ✌️
@AyindeAishat-dm7hc
@AyindeAishat-dm7hc Жыл бұрын
Hummm moki yin ku aforiti sir
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Ẹ seun ma✌️
@user-mx5ep7qi6f
@user-mx5ep7qi6f Жыл бұрын
Wallohi you're really trying
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Ẹ seun sir mo dúpẹ́
@jacobakinwumionifade8436
@jacobakinwumionifade8436 Жыл бұрын
The introductory statements is too much.
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
You can forward it to enjoy it more Thanks✌️
@adedejiademola3965
@adedejiademola3965 Жыл бұрын
Kudos to you don't worry my brother God is your strength
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Thanks sir ✌️
@rahmonzainab1661
@rahmonzainab1661 Жыл бұрын
Amin o, biru mi yi kani mo lowo lowo ni mio ba ra Toyota sienna fuyin
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Ẹ̀rín músẹ́, ó da ẹ seun ma
@tawakalituabeke9920
@tawakalituabeke9920 Жыл бұрын
Hummm! Eku igbiyanju sir olorun a jeki osese sir nitori awa naa ti missed yin gan ohun tawa na bani lagbara amafi sowo siyin
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun Alhaja ẹ ku gbogbo ìgbà wa, Ọlọ́hun kòní fi ẹ̀yin náà sílẹ̀ ✌️
@ogunlekemayowa9057
@ogunlekemayowa9057 Жыл бұрын
Amin sir olorun a ranyin lowo awa ne ma send iye taba ni
@OYEOLOHUN_TV
@OYEOLOHUN_TV Жыл бұрын
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ọlọ́hun kòní da ẹ̀yin náà dá bùkátà yín, moti rí owó ti ẹ fi sọwọ́ sí wa ✌️
Пробую самое сладкое вещество во Вселенной
00:41
WHO LAUGHS LAST LAUGHS BEST 😎 #comedy
00:18
HaHaWhat
Рет қаралды 17 МЛН
WATCH THIS: If Your Work is Not Going Well or You Lack Money
27:50
Adun Asa Yoruba TV
Рет қаралды 12 М.
OGBOJU ODE NINU IGBO IRUMOLE PART 3
29:34
Ojopagogo TV
Рет қаралды 13 М.
Asiri bibo by ifabukola
7:20
Ona ola Tv 1
Рет қаралды 228
Many People Ran Away For Me When I Was Sick--Taiwo Hassan Ogogo
15:55
City People TV
Рет қаралды 149 М.