Hi sire. Blessing upon your life. Can i have one affochè
@brightonikosi8423 Жыл бұрын
Baaaaabaoo, Agbala leo maada eo nidi agbaya pelu ase eledumare, Eniola yio maa gun si nio aaaamioooo
@YetundeOpeyemi-vd8oq4 ай бұрын
Baba eese sir olorun o nl fiyin sile ni ase edumare
@habeebullahabdussamod2273 Жыл бұрын
Baba. Gigun emi yio je ti yin oooo.
@adeinvest13069 ай бұрын
Good afternoon Sir. Esé gaan Baba. Mo gbadun ètò yín gaan ni. Oluwa Olórun Oba amaa wa pèlú yín, A sin maa ran yín lowo tomotomo. E jowo Baba, ti a ba ti fi konkon ati ose ewé yi we fun ojo meje, kini kati se àwon konkon meje yi?
@hassannofisatmorenikejimop4618 Жыл бұрын
Sir se taba ja awon ewe yen se ewe ewuro LA pe,ati akoko yen, bawo LA se ma pe won,ko le ba he dada
@yusufsani5152 жыл бұрын
May almighty allah bless u with paradise
@tochiukwueze19732 ай бұрын
Baba emi tin wa ewe akoko ti o lu for almost 1 year. E mi ori o. Ewe ewuro ni mo ri to pe. Sungbo ewe akoko to pe bi e se San emi o ri. Se ona abayo wa baba?
@funkeabimbola3470 Жыл бұрын
Baba daada eseun sir,ejoo baba Mon la efori koja lati ojo pipe ,mositi gbiyanju gbogbo nkan sibe kolo ,eranmilowo sir
@adeiyebolanle40592 жыл бұрын
Baba ẹ seun, adura yin a gba l'ase edumare, titi l'aiye la o dúpẹ lọwọ yin. Ẹ ṣeun Lẹẹkansi.
@abiodunadanlawo4300 Жыл бұрын
Eseun pupopupo sir, alaanu Koni wonyin sir
@adesojisunday60972 жыл бұрын
Adupe baba ewe ama jeoo ooo
@olanrewajuayobami4210 Жыл бұрын
May Allah be with you sir
@funkeabimbola3470 Жыл бұрын
Iru ose wo lale lo
@Way_out3142 жыл бұрын
Eku ise takuntakun baba,ewe aje.ejowo iru ose wo in,nje oje dandan ka lo ose dudu? Tabi ose Miran?
@mohamedwaliouenianchoro88462 жыл бұрын
Thank you sir
@adetunjilukman19052 жыл бұрын
Thank you sir olorun abami dupe fun yin oo Amin
@Molastheboss2 жыл бұрын
Se taba we laaro ale ni ajosepo pelu iyawo wa toba da alee
@posilademathew7902 жыл бұрын
Baba epe fuwa ooo
@abioladada99442 жыл бұрын
Ewe amaje sa
@olorunfemimayowa29772 жыл бұрын
E see pupo sir
@adebowaleadebisi73942 жыл бұрын
Baba hmm agbayi adaleooo
@abdullahieleweogede94862 жыл бұрын
Sai baba
@adebolasarafadeen79912 жыл бұрын
Se omo olo ko ni a ma fi olo majeje sir, ojo yin adaleee amin
@adebolasarafadeen79912 жыл бұрын
Se omo olo ko ni a ma fi olo majeje sir, ojo yin adaleee amin
@adeshinaolukoya61372 жыл бұрын
E seun sir, ko ni tan nibi ti e ti nmu
@abegundeolumide48672 жыл бұрын
E seun gaani ooo, sebi , omo olo Kan ni, Sugbon lori olo meje?
@bayojoetv2 жыл бұрын
Baba edakun, se a le lo ni ileele ,tori okuta ilonkan eyokan lowa🙏🙏🙏🙏
@bayojoetv2 жыл бұрын
Se a le lo gbogbo re ni ilele ni aye oto to ?🙏🙏🙏🙏
@tajudeenajaniojuelegbatele78102 жыл бұрын
E lo okuta eyokan lori olo kan sugbon oju ototo ni e fi loo
@bayojoetv2 жыл бұрын
@@tajudeenajaniojuelegbatele7810 ese pupo sir 🥰🥰🥰🥰❤️❤️❤️❤️❤️❤️
@abioladada99442 жыл бұрын
Adupe sa sugbon nibo ni amaju kankan tafiwe yen si sa
@kareemakinade38802 жыл бұрын
Se ale lo omo olo kan lati fi gun ewe ati ose yii ni aye ototo abi, omo olo kookan laaye kookan ni
@tajudeenajaniojuelegbatele78102 жыл бұрын
Omo olo kan ni fun gbogbo ee
@tajudeenajaniojuelegbatele78102 жыл бұрын
Call me 08023094983
@bayojoetv2 жыл бұрын
@@tajudeenajaniojuelegbatele7810 ese gan ni ooooooo
@hassannofisatmorenikejimop46182 жыл бұрын
E kasan,e seun sir, olorun olodumare awa pelu yin,se Ori olo kanna ni kati gun mejeje,sugbon Loma je oju kan na
@akinlabitestimony58852 жыл бұрын
E seun lopolopo
@olajideoluwaseun57672 жыл бұрын
Baba eku eto ,edakun efun wa ni malu
@abdalasewanou11272 жыл бұрын
Eseun pupo Baba albarka
@prophetolorundareraphael47562 жыл бұрын
Ogbon ko ni tan ni be Ase.
@Adeniyi-er2re Жыл бұрын
Esee pupo
@adejumokelawal18082 жыл бұрын
baba gege bi omo omi ise dudu ki sisee fun wa ona abayo nko
@kabiyesioluwagbemigaspirit5656 Жыл бұрын
Omo-omi tabi Irawo-omi? Ti o ba je Irawo-omi, sise wa fun yin.
@anneayabz92432 жыл бұрын
Please sir I don't understand the pounding of the leaves in different places. Are you saying I should use different mortar to pound the leaves?
@tajudeenajaniojuelegbatele78102 жыл бұрын
Use one stone but different place
@tajudeenajaniojuelegbatele78102 жыл бұрын
Use one stone but different places
@favorwealth48242 жыл бұрын
@@tajudeenajaniojuelegbatele7810 sir what at process of using it and my period comes out should I still be bathing with the soap or should I stop using it sir,
@kabiyesioluwagbemigaspirit5656 Жыл бұрын
@@favorwealth4824 Everything has spoilt. U have to wait till you finish your period n cleanse yourself before embarking on it. Meanwhile, it's advisable that u should calculate when you will be having ur menstrual period very well so as not to do it when the date is approaching.
@mercylordmercylord12752 жыл бұрын
Baba what can we use for someone that is from water so that spiritual things to work for her
@tituslinda58062 жыл бұрын
Baba Che ka gun ninu odo abi ka lo lori olo .....koyemi sa