Baba Ekiti E ku oro ile wa olorun a gba omonira na fun wa patapata lagbara olorun olodumare a o ni wa eni kokan wa ti ta ba gba orileede Yoruba nation lagbara olorun olodumare amin
@OmitogunDennis21 күн бұрын
Amin l'ashe Edumare 😊. Up Yoruba Nation ❤. No going back 😮.
@olusolaayindefakeye442621 күн бұрын
Amin Anin Amin, .ki Eledumare ba wa gba òminira fun ile wa Olominira Orile Ede Yoruba
@bunmitayo89621 күн бұрын
Baba Ekiti e ku ifomo enia se. Yoruba nation all the way no going back. E ku ise takuntakun.
20 күн бұрын
Baba Ekiti: May God bless you because you are telling it like it is. Won ti da ile Yoruba!
@alaotijani676921 күн бұрын
Happy new year yoruba nation no going back
@christianaholopade869021 күн бұрын
Baba Ekiti. Akikanju Akoni Omo oduduwa ti oti wasi aye ri ni yin. Ti Olorun tun wa da yin pada lati wa sise igbala fun wa. Eseun gidi gaan. Loruko Jesu Christi ori ni eja fi nla ibu ayee ja. Ase ye. Ati ase yege ni tiyin. Ko ni su yin ko si ni re yin lase Edumare.
@giwaabdul-rahman40621 күн бұрын
Baba Lekiti eku eto, Happy New Year 2025 to you and your family. Baba Lekiti, lotito loso gbogbo awon Oba ile yoruba loni jekuje, alatenuje, Awon oba ile yoruba lota gbogbo ile yoruba fun awon Fulanis. No wonder they put the kings under the local government, nitori won mo pe awon ni obayeje ni won. Awon oba gan loba ilu je.
@olaolu31521 күн бұрын
Good Morning Baba. Happy New Year
@FolaAyamolowo-gk1qv21 күн бұрын
Laakaye yin o ni joba Baba Ekiti. Oro lomo eleti nje. Eni awifun, Oba jeogbo, eni asorofun Oba jeogba. Eyi to ko tio gbo, Ijimere a gun igi aladi.
@omoyorubaedide969721 күн бұрын
Baba mi lekiti you are the best, odun Ayo ni olodumare yio se odun tuntun ti fun wa, ile YORUBA yio gbe wa oo
@JosephAjewole-s4w21 күн бұрын
BABA EKITI E KU ODUN A SEYI SAMODUN NI ORUKO JESU. YORUBA NATION LAFE.
@AnisereSunday-w5p21 күн бұрын
Baba Ekiti ria eku ise Olorun a pelu yin
@adebayolawal323021 күн бұрын
Which governor in Yoruba land can greet Ooni of ife like that I pity Yoruba land in the hands of our Obas and leaders
@OkeowoTaiwo21 күн бұрын
Baba mi lekiti,ko ma ni baje fun yin ni ase olorun eledumare.eku atunse ori gbogbo wa ni ile yoruba ni gbogbo igba sir.olorun maa gba wa lowo won ni kiakia ni agbara eni to nile aye atorun
@giwaabdul-rahman40621 күн бұрын
Baba Ekiti, there was a time I witnessed Tinubu at party stood up for Oba Elegushi and he refused to stand up when Oba OOni came into that same party. That was before Tinubu become the President of Nigeria.
@uniquebabybabygirl564021 күн бұрын
😂😂😂awon oba alatenuje shameless leaders and elders of yoruba land I like how governors are dealing with them ooni is the problem of yoruba land
@monisolarahman76221 күн бұрын
Oba ile Yoruba ti di agba Yahoo, Opo ninu won ko ye ni ipo Oba, won ti di contractor, won ti di oba shawarma, oba spaghetti, won ma ma Jo ijo were Kiri party, Opo oba ni oba Tinubu 😢😢😢😢
@Elizabeth-r3g6i21 күн бұрын
Afi agbada ,iyun ati ade china.
@Tayese164521 күн бұрын
A to oba te le, ki o to Joba ki si iwa wu.
@Elizabeth-r3g6i21 күн бұрын
Opo awon ti ko ye ni oba, ni won fi njoba ni akoko yi. Show off, period
@oe652621 күн бұрын
Babalekiti, please be thankful to God that your obas are glorified caretakers because the obas of the olden days that you are praising all owned slaves - onigba eru ni gbogbo won. History tells us that Na them sold our people to trans Atlantic slavery and slave trade o jare. And the slaves rained curses upon them and their unborn generations as the oyinbos dragged them away in chains and shackles. Se bi gbogbo yin na ngbe won sepe lowo lowo bayi. If God had not placed them under politicians, they would have asked the 'abenilori' to go and get you long time.
@ayankunleagbolade400421 күн бұрын
Which of Governors past and present will ever bowed to Ooni of Ife ? Never
@FunsoAdeniyi-cr8pl21 күн бұрын
BABA EKITI EKU-OHUN ELEDUA AWA PELU YIN,ODUN AYABO FUN GBOGBO WA,ABO-ORO,LA-NSO FUN OMO-LUWA-BI ,TO_BA DE-INU - E, ADI-ODI-NDI.OMINIRÀ ILE YORUBA NI KAN NI ONA ABAYO.ADANIEAYE A RAN WA LOWO ASE EDUMARE
@dennisa686621 күн бұрын
Our Oba's are the problem of yoruba people and they're the set back of the Yoruba agitation. Imagine we as their children fighting their fight? That's too bad.
@JosephOlowojoba21 күн бұрын
Ooni of Ife is a snitch and sellout . A betrayer to Yoruba tribes . How I wished other Oba didn't follow Ooni of Ife to Buhari in daura. The reason is very unknown to any Yoruba people till today But I could summarize their visit as a shameful one belittled all Yoruba races.. What good has Buhari did to all Yoruba than destruction . Ooni of Ife has disgraced himself and the entire Yoruba races