Рет қаралды 9,708
Ile-Ife, The Cradle Of The Yorubas
This Lineage Is Dedicated To Our followers from 'Ile-Ife' Members
Omo onife abure omo adede oworemo, Ife omo olodo kan otere
Omo olodo kan otara, omo olodo to n san wereke to n san wereke
Tode eyinkule osile todi abata, iran asakeke o gbudo bumu be ni iran ababaja o gbudo buwese, oni soboro niyo mumi odo naa gbe.
A i duro ki won n'Ife Oni
bi a ba duro ki won n’ife ooni , eru ni baba won n mu ni se
A i bere ki won n'ife lembebe
bi a ba bere ki won n'ife lembebe ebo ni baba won n fini ru
Emi wa ki wan nife mo lakun, Oba wan loni sese efun, bante gboro lo mu ife wunmi.
Aso funfun ni mu ile won wu mi duro si, ori a fa kodoro nii mule baba won su mi lo
Ife Oni ti olofin Oduduwa Adeyeye Ogunwusi Enitan Ojaja 11, baba e Oba, iku baba yeye
Idobale nimowa oluaye, mosun moba ni igba egbeje mojina soba ni igba egbefa, Aroba fin loba npa, Ife sa nile Oduduwa
Edumare bawa da Ile-Ife si
Amin, Ase
by Asadoyinabefechanter
#explore #igainwithseed #publicity254
#gainwithtedbrown #gainwithspike #gaintrain #gaintrick #vscoke #bobrisky #gaintrain #publicity254 #10over10
#ileife #ooniofife #ooniofifepalace #chanters #chantersinlagos #chantersinibadan #yorubaculture #yorubaheritage #yorubaentertainment #itagetv #itagetelifisan #ewi #ewiyoruba ##ewìyorùbá