Fún alaye àti ibere nípa Itan Yoruba ẹ kan si wa Aare Laji Abbas +2348023687432
Пікірлер: 19
@mamaiya66333 ай бұрын
Oloye Laji Abass, a ku ara fera ku Chief Abimbola Davies. Olorun a fi orun ke won.The Lord will comfort his family in Jesus mighty name.
@taofiqowolabi3 ай бұрын
Oluwa ko fi orun ke Otunba ABIMBOLA Davis. What a loss.
@akeemadedayo96263 ай бұрын
I have always heard his name for long. Olorun ate won si afefe rere
@olorunfemifemi38973 ай бұрын
Are olupitan laji Abasi God bless you 🙏🙏for your lecture❤❤❤❤👌👏👏👍
@user-si6di4yq1e3 ай бұрын
Emiyin ogun fun wa lase edumare Baba wa Aare laji Olohun Agba orilede ile wa fun wa
@MikhailAwolowo-zm7fr3 ай бұрын
Aare Opitan. A ku ara feraku. Itan yoruba ko ni gbagbe won gegebi awon naa ti pada di ara itan. Ki iwaju ti won koju si, ki Olohun jeki o dara, ki ehin ti won fi sile ma baje. Ki Olohun jeki ojo jina sira.
@MikhailAwolowo-zm7fr3 ай бұрын
Otunba Abimbola Davies. Ki Olohun se aforiji fun won, ki Olohun se iku ni isinmi fun won. Ki ile won ati nkan ti won fi sile ma baje. Amin.
@FolamiAbiodun3 ай бұрын
Are Opitan ejo ebay wa so itan Igboho ki e si so eniti oba tosi ninu oba meta to wa nibe.
@oyeyiolaoladipupomutiu48623 ай бұрын
May baba soul rest in peace
@badmusalumeltextra26933 ай бұрын
I love u sir , Aare Laji Abass may God keep guarding and protecting u sir 😊
@anthonyfresh3213 ай бұрын
You're doing a good job sir sorry for the lost
@MikailOmiata-ds1fm3 ай бұрын
Eku ISE lajiabas.olorun yio ma gbehin ga
@allstars64433 ай бұрын
You hit the nail
@VeriteEquite3 ай бұрын
Abimbola Davies and Arthur Nzeribe were key members of Association for Better Nigeria (A.B.N) which was used by IBB to frustrate the actualisation of MKO June 12 election. He granted an interview in the erstwhile "The Tempo Newspaper" sometimes around August, year 2000. I know him fairly well. I don't think history will be kind to Abimbola Davies. He betrayed the course of Yoruba people over the June 12 election.
@VeriteEquite3 ай бұрын
@@TRUESON_4EVERU can't rewrite the history, @Abimbola Davies addressed the press to narrate what they did, after the damaged had been done. Probably because his conscience was disturbing him.
@AinaBamidele-tw8uf3 ай бұрын
Abimbola Davis was the Director General of association for better Nigeria which the duo of Arthur Nzeribe and Abimbola used to truncated Abiola's victory of June 12th 1993 presidential election. Many Yoruba agitators lost their lives and many languished in prison including myself. Alabode omo Yoruba niye!
@fataisanni71063 ай бұрын
Ẹ ku ọrọ̀ èèyàn... Ọlọhun yoo mú àwọn ẹbí wọn dúró. Ẹ kú ìṣẹ́ ọpọlọ Ààrẹ Laji Abass... Ẹ dakun mo wo Video kan nibi ti àwọn ọba mẹta ti n claim original ọba ni Ilu Igboho. Àwọn Ọba mẹta yìí loni Ààfin ni ilu Igboho.
@emmanymatthew25393 ай бұрын
Sorry for the loss, the reason for the death could have been sleep apnea. Nigeria needs serious awareness on sleep apnea, I’m not sure if Nigeria has respiratory therapist…