Omogiesi ise lense o Eledumare amadabobo yin alo ATI abo yin yio ma da. Ayun lo Ayun Bo lowo nyun enu. Baba ejo se ale ri kokoro Yi ra ATI wipe ise wo ni ise Yi maa se.
@AdewoyinOlawoye-ud3tn10 ай бұрын
Ogun yi dara pupo edakun eje ki ada ewe agba juja mo
@OTUNBAAdegbite9 ай бұрын
Hm! Wonderful soap baba Ara o ni ninyin, araba nla ni yin ee ni wo lailai, ose nla ni ose yi eru olorun ba mi
@omogiesitv9 ай бұрын
Se bi eyin RI ise OSE yen, olorun seun, o tumor SI wipe Kii se iro ni a n pa Lori net. Adupe
@AFUNYINTANOLUWASEUN6 ай бұрын
This man brings back my lost interest on traditional herbs, man yi gba mi lowo awon family iyawo mi ti won fe ba temi je.
@omogiesitv6 ай бұрын
Smile, olohun ko ni fun aye laaye lati ba ti waje lase edumare sir