OWO ORILE-EDE YORUBA ( RUBA ) È TETE LO FORUKỌ SILẸ

  Рет қаралды 4,853

AROLE BABA 10 10 TV 1

AROLE BABA 10 10 TV 1

Күн бұрын

Пікірлер: 157
@oluwarantimijoshua2625
@oluwarantimijoshua2625 12 минут бұрын
Ekuse olorun yio wa pelu yin, Olorun yio je ki gbogbo wa de ile ileri wa Amin, Baeo ni ase le fi oruko sile sir
@mykeoyelowo3493
@mykeoyelowo3493 Сағат бұрын
Onawo ni alegba lati fi oruko sile. Eku ise takuktakun❤
@remilekunakinwunmi9769
@remilekunakinwunmi9769 Сағат бұрын
Nibo lati ma registere ko ye wa rara awa agbalagba o yoruba nation no going back kudos for every one of u ❤❤❤❤❤❤❤
@debbydare9720
@debbydare9720 3 сағат бұрын
Well done Arole Baba 10 10. This is great news. Yoruba Nation no going back.
@PatrickPatoo-h4l
@PatrickPatoo-h4l Сағат бұрын
Eku ise ile odua yogbewa Amin ejo wo awa tiawa ni ipinle oyo bawo ni ase le se ifi oruko sile
@gbolahanshittu9031
@gbolahanshittu9031 3 сағат бұрын
E ku ise ooo, Oduduwa yio gbe wa ooo. GOD BLESS YOU ALL 🙏 ❤️
@josephoguntade4483
@josephoguntade4483 10 сағат бұрын
Bawo ni àwon OMO YORUBA se ma rin nipa iforuko sile? Ejowo e salaye bi àwon oni kara kata kereje se le forukosile.
@OlamilekanOmognolaha
@OlamilekanOmognolaha 6 сағат бұрын
Ejowo bawoni asemafi oruko sile kiesalayefunwa❤❤❤❤ Yoruba nation no going back Yoruba must collect our glory back home lagbara ogunlakaye osunmole lagbara awon irunmole
@FalujoTunde
@FalujoTunde Сағат бұрын
E jowo ba wo ni mo se le gba iwe idani mo. Yoruba Nation! No going back.
@phillipagboola197
@phillipagboola197 8 минут бұрын
Eku ise olorun afunyinse nibawo latileri idention card Yoruba gbà ejo eranwa low Lori e Yoruba national no going back.
@FolakemiOlugbade
@FolakemiOlugbade 7 сағат бұрын
E ku ise takuntakun arole baba 10 10 e jowo bawo la se le foruko sile e salaye fun wa ni kiakia olorun awa pelu yin Amin
@taiwotinuoye329
@taiwotinuoye329 10 сағат бұрын
Yoruba Nation no going back God bless my country Yoruba Nation God bless Yoruba land
@matthewogunrinu
@matthewogunrinu 10 сағат бұрын
Ona wo ni ao gba lati fi oruko sile oo E jeki a tete mo lati le see ni kiakia yoruba nation ti wole de oo amin ogunrinu thanks
@helenahmed9189
@helenahmed9189 7 сағат бұрын
Eku Ise takuntakun. God bless you all. Yoruba nation now now now in Jesus name!Yoruba nation no going back.
@BumiAkibeda
@BumiAkibeda 4 сағат бұрын
Yoruba nation no going back no surrender no retire ba wo ni a ma se fi oruko si ile
@adeyemioluwasogo9850
@adeyemioluwasogo9850 2 сағат бұрын
E ku ise Oluwa a ma tiyin lehin Bawo ni a sema fi oruko sile
@gbolahanshittu9031
@gbolahanshittu9031 3 сағат бұрын
Arole baba 1010, God bless you, sir 🎉
@sundayoyewole8803
@sundayoyewole8803 3 сағат бұрын
THANK GOD FOR YOUR LIFE, YORUBA NATION ALL THE WAY, NO NEGOTIATION,GOD BLESS YOU ALL
@monisolarahman762
@monisolarahman762 4 сағат бұрын
Yoruba Nation no going back, Jekanmo! Jekanmo!! Jekanmo!!! I ❤❤ Iran mi daku
@o.oademola4108
@o.oademola4108 3 сағат бұрын
Everybody deceiving Yoruba shall never find peace on earth in Jesus name
@naslanre5061
@naslanre5061 5 сағат бұрын
This is great news may God continue to protect you all
@PastorStephen-vp9fe
@PastorStephen-vp9fe 9 сағат бұрын
Baba arole oba Lola jp EKU eto sar olorun yo ma tiyin leyin loruko jesu bawoni ni awati awa ni Nigeria se mani anfani lati open ruba AC bank
@victoriaibiwoye
@victoriaibiwoye 4 сағат бұрын
Awon alale ma duro ti yin Yoruba nation is the solution
@olayiwolaottun9719
@olayiwolaottun9719 7 сағат бұрын
Ẹ ku isẹ o. Yoo maa juṣe fun yin o. Alale yoo gbe wa o, amin.
@yinkaawoyemi712
@yinkaawoyemi712 6 сағат бұрын
E ku ise takuntakun. OLORUN a maa fun wa se loruko JESU. Bawo ni awa omo Yoruba tooto ati omo Yoruba atata se maa fi oruko sile fun RUBA - YORUBA NATION MONEY? GOD bless YORUBA NATION.
@AGBAJELOLAOLADIMEJI
@AGBAJELOLAOLADIMEJI 3 сағат бұрын
ADUPE OLOHUN YOO MAA RANYIN LOWO . ELAWA LOYE BAWO NI ASEFE REGISTER SIR M
@ModupeolaBello-zi2yw
@ModupeolaBello-zi2yw 10 сағат бұрын
BE ni oooo my brother Sugbon bawo ni a wa ti a wa ni Nigeria se ma ri ibi ti a ti ma Fi Oruko SI le Sir❤ Gbogbo awon OMO Yoruba Atata n dupe Lowo yin I Lani loye yin sir❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤
@SikiratOpaleye
@SikiratOpaleye 6 сағат бұрын
Ejowo eku ise ribiribi ti ense sugbon nibo ni awa ti awa nibi sañgo sele lo foruko sile Yoruba nation no going back
@AdejumobiSolomon
@AdejumobiSolomon 8 сағат бұрын
Baba Arole 10 10 e see lopolopo atileyin EDUMARE Yoo ba WA yori gbogbo re layo Yoruba Nation Now
@AkingbadeAyoWilliams
@AkingbadeAyoWilliams 5 сағат бұрын
Bawo ni unho seni nkan ti añso Yi,e la mi loye
@hassantaiwo1626
@hassantaiwo1626 2 сағат бұрын
Bawo ni omo yoruba se maa forusile
@ModupeolaBello-zi2yw
@ModupeolaBello-zi2yw 10 сағат бұрын
EkAROO ooooo AROLE OMO BABA 10 10 eku ise ILU oooo OLORUN OBA a ma wa pelu yin oooooo Laseeedumare 🎉🎉🎉🎉
@estherayankola6913
@estherayankola6913 9 сағат бұрын
Arole baba 1010 , Eseun Olorun ama ran yin lowo loruko Jesu ,e bawa dupe gidigidi gan lowo gbogbo yin eku ise Olorun Olodumare ma fun yin loriyin , Ejowo mo be yin emama ro pe awon kan nso eyi tabi eyi ni ko si ohun ti Eniyan le se fun Eniyan egbere ti won Jo ju , sugbon nigbati Olorun ba yin yin iyneniyan asan ni eseun
@taiwotinuoye329
@taiwotinuoye329 10 сағат бұрын
God bless you my brother
@mathewtaiwo6936
@mathewtaiwo6936 40 минут бұрын
Bawo wani asele ma rii ti a o si ma rinon, bawo ni bank ifowo pamo si.
@M.S.Ademola
@M.S.Ademola 5 сағат бұрын
You are well done, may Almighty Allah bless you for all your efforts.
@PeterSundaySam-nh4xt
@PeterSundaySam-nh4xt Сағат бұрын
Yoruba nation tide
@fajanaflorence
@fajanaflorence 8 сағат бұрын
AROLE BABA 1010 eku eto sir E jowo bawo ni a se le foruko sile . Yoruba nation n going back
@OyelowoAhmed
@OyelowoAhmed 2 сағат бұрын
Ejowo emi na fe foruko sile
@OmololaFlorence-h7v
@OmololaFlorence-h7v 4 сағат бұрын
E ku ise takuntakun sir, bawo ni awa Omo Yoruba se ma fi Oruko sile, nibo ni a ti ma register. YORUBA NATION NO GOING BACK
@tundeopoola
@tundeopoola 58 минут бұрын
Thank you my brother youare well done l have registered my account for now
@davidolawole1939
@davidolawole1939 6 минут бұрын
Let's Koiki bring this out please.
@TonyloveTonylove-d1i
@TonyloveTonylove-d1i Сағат бұрын
Ejowo bawo ni a se ma foruko sile ni lbadan, e se e kuu ise takunakun arole
@veronicaaduVBA
@veronicaaduVBA Сағат бұрын
👍 ❤👍 ❤👍
@PatrickPatoo-h4l
@PatrickPatoo-h4l Сағат бұрын
❤❤❤
@ModupeolaBello-zi2yw
@ModupeolaBello-zi2yw 10 сағат бұрын
BAWO la se ma se tabi nibo ATI ma registered sir❤ Nitori Ilu EKO Ni EMI ATI awon OMO ATI AWON OMO OMO WA Oooooo
@olufunkeadebayo1375
@olufunkeadebayo1375 9 сағат бұрын
Yoruba Nation no going back lagbara ELEDUMARE. Ibunkun ni fun ORILE Ede Yoruba.
@Abb-r8d
@Abb-r8d 6 сағат бұрын
E maa tan arayin eyin were a maa wo ibi ti e ti fe naa owo were yin ati ibiti e ti fe lo passport yin
@ekundayooladele5098
@ekundayooladele5098 5 сағат бұрын
Mo ro pe were ni iwo ti o nsoro yi, abajo omo Fulani ni e, Fulani ni o fun iya re loyum ki o to lo gbe fun baba re omo ale ni e. iwi akuri yi, isoju re ni o ma se, ni igba ti YORUBA ba de oju lo ma fi ri, ete re ko ni to rara.
@badmusibironke4358
@badmusibironke4358 2 сағат бұрын
Kilode ti eniyi fisope ema tan Ara yin Haaaaaaaa Laduru bi ilu SE le to yi ,kokan yin eyin tewa ninu ola Hmmm Olorun nbe o.
@TaofeeqQuadri-k7f
@TaofeeqQuadri-k7f 4 сағат бұрын
Bawo ni a wa na se ma foruko si le sir
@FunsoAdeniyi-cr8pl
@FunsoAdeniyi-cr8pl 7 сағат бұрын
OMINIRA ILE YORUBA NI A FE
@racheldavis2554
@racheldavis2554 8 сағат бұрын
Make dem no write any stupid Arabic to d money cus we no Dey Saudi, or make we stay in one Nigeria like dis
@sundayobolanle6860
@sundayobolanle6860 6 сағат бұрын
God bless u, we don’t want any arabic on it
@idrisibukun2516
@idrisibukun2516 Сағат бұрын
Bawo lase fe mo office ruba
@AdelekeAsogbon
@AdelekeAsogbon 10 сағат бұрын
Bawo lase ma register
@OlowonyoIbrahim
@OlowonyoIbrahim 9 сағат бұрын
Ebawa se kole je irorun fun iran Odua ooo emi ni temi okaan mi ti wa lonal lati fi oruko sile
@kolawoleowoeye4456
@kolawoleowoeye4456 10 сағат бұрын
How can will opened ruba account and which bank will l opened it.pls reply soon.
@victoriaibiwoye
@victoriaibiwoye 4 сағат бұрын
Ejowo ona wa lamafi oruko sile
@adenirandejoke9315
@adenirandejoke9315 10 сағат бұрын
How do we registered
@usmanwahab6262
@usmanwahab6262 6 сағат бұрын
Olorun bukun orilede mi Yoruba
@aderibigbematthias8646
@aderibigbematthias8646 Сағат бұрын
Bawo a se lee foruko sile (register)
@victoriaibiwoye
@victoriaibiwoye 5 сағат бұрын
Bawo lasele fi oruko sile
@libertyd8782
@libertyd8782 7 сағат бұрын
Wao!!!!!
@oluwanisolaoluwatobiloba
@oluwanisolaoluwatobiloba 10 сағат бұрын
Bawo la se ma get e
@segunmathew4738
@segunmathew4738 4 сағат бұрын
😂😂😂😂😂 funny people, ruba KO, aroba ni
@olumike9935
@olumike9935 2 сағат бұрын
What’s your problem ?
@akinkunmibabalola5370
@akinkunmibabalola5370 38 минут бұрын
It has been in existence since and I have register my own over two years now! So if you are not inform dont condemn
@GbadeboIvukunoluwa
@GbadeboIvukunoluwa 7 сағат бұрын
ODUA YIO GBEWA OOO....LASE ELEDUA.
@graceadegboyega7597
@graceadegboyega7597 7 сағат бұрын
E kira fun Baba
@ajetunmobimicheal193
@ajetunmobimicheal193 4 минут бұрын
E jowo bawo ni a o SE fi oruko sile bii ojulowo omo Yoruba ni agbegbe wa?
@AdebayoIbitoye-k6t
@AdebayoIbitoye-k6t 8 сағат бұрын
Eku ese opolo, YORUBA NATION I stand with You
@catherineolayinka3441
@catherineolayinka3441 10 сағат бұрын
Ejowo e je ki a mo bi ase ma register o. Eko ni awa o.
@AdeolaOlusegun
@AdeolaOlusegun 9 сағат бұрын
Bawo lase Le ri FSCC yen gba ,papa fun awa towa Benin Rep to je omo Yoruba
@ekundayorotimi8342
@ekundayorotimi8342 27 минут бұрын
Bawo ni a se maa fi oruko sile? E se alaye fun wa ni ekun rere.
@sakaadams920
@sakaadams920 5 сағат бұрын
How can someone register with this . Please throw more light.
@0lusolaAkinbode-y1e
@0lusolaAkinbode-y1e Сағат бұрын
Yoruba nation, no going back
@AishaOlatunji-cd8jy
@AishaOlatunji-cd8jy 8 сағат бұрын
Bawo la se ma get e sir
@Arole-Baba-10-10-TV1
@Arole-Baba-10-10-TV1 8 сағат бұрын
+27682414404
@fatimahabubakar3458
@fatimahabubakar3458 5 сағат бұрын
Well-done arole baba, you are blessed. How can we living in Nigeria register and participate on this programs. Thanks oodua nation, no going back 🙏🙏🙏⭐⭐⭐
@arowolosirhenry847
@arowolosirhenry847 11 сағат бұрын
How can i register
@olanrewajutayo5381
@olanrewajutayo5381 24 минут бұрын
How can we download this
@FunmilayoElugbaju-lu3dy
@FunmilayoElugbaju-lu3dy 9 сағат бұрын
Nibo ni bank na wa
@AdegojuLateef
@AdegojuLateef 2 сағат бұрын
Emi wa pelu yoruba nation, bee bawoni a ma se fi oruko sile fun kati gba iwe tie so yi ati nipa ruba account, ati fssc.
@libertyd8782
@libertyd8782 7 сағат бұрын
I can I register?
@RidwanulahAkumojud-pe4ft
@RidwanulahAkumojud-pe4ft 9 сағат бұрын
Bawo lasefemo office ruba. .
@michealawe4883
@michealawe4883 11 сағат бұрын
BAWO LA SE MASE. EKO LE MI WA OO?
@taiwotinuoye329
@taiwotinuoye329 10 сағат бұрын
bawo ni ase mase ti afi change owo wa si RUBA
@sundayolowoyo917
@sundayolowoyo917 2 сағат бұрын
Where are we going to register?
@oluwolepalmer1970
@oluwolepalmer1970 5 сағат бұрын
Pls where can we go to register
@AKANDE.Kolawole
@AKANDE.Kolawole 5 сағат бұрын
How can can we register am in Ivory Coast Abidjan
@JeremiahAdegoke
@JeremiahAdegoke 11 сағат бұрын
Bawo ni a se ma register
@helenahmed9189
@helenahmed9189 7 сағат бұрын
They have state of origin certificate issue by Local government after authentication from compound elders and king.
@victoriaoloba7634
@victoriaoloba7634 10 сағат бұрын
I want to open ruba account. I'm Nigeria where should I go?
@damifatima959
@damifatima959 11 сағат бұрын
Morning sir, EKU ise takuntakun, God will reward you, please sir what are the step to take about the ruba account
@JosephAkindele-lc9hj
@JosephAkindele-lc9hj 6 сағат бұрын
Pls how do we register and open Acct with the CBN of Yoruba Nation. What is the minimum of deposit including the maximum.
@mustaphaabdulganiyu3484
@mustaphaabdulganiyu3484 7 сағат бұрын
Baba Arole 10 10, thank you, sir, for doing a good job for the Yoruba Nation. How do we register to Ruba Currency? Thank you
@lateefmafinwonla7332
@lateefmafinwonla7332 6 сағат бұрын
Please kindly help us how to open the RUBA ACCOUNT ❤❤❤
@oregbesanmulikat8292
@oregbesanmulikat8292 8 сағат бұрын
Yoruba nation no going back
@sundayolowoyo917
@sundayolowoyo917 2 сағат бұрын
Please where can i get my own?
@TaiwoIbrahim-zc9gj
@TaiwoIbrahim-zc9gj 10 сағат бұрын
Yoruba nationa no going back confirm ni p
@FunmilayoElugbaju-lu3dy
@FunmilayoElugbaju-lu3dy 9 сағат бұрын
Nibo a o ti ruba yi se nigeria sir😊
@oladelealara5274
@oladelealara5274 44 минут бұрын
Sir bawo ni ase ma register ati pe bawo ni ase ma open account ruba
@raymondoladimeji2887
@raymondoladimeji2887 4 сағат бұрын
The Lord will see you through in Jesus Name . My question is this, how are we going to register RUBA Account ? Oodua agbewa
@elijahabiodun9149
@elijahabiodun9149 4 сағат бұрын
Sir what is the procedure for opening a ruba acct? YORUBA NATION NO GOING BACK .
@josepherinolu296
@josepherinolu296 8 сағат бұрын
Bawo ni ase maa fii oruko wa sile?
@ajayijoseph1937
@ajayijoseph1937 Сағат бұрын
Ejo monife si Owo Yi e ran mi lowo
@olamicheal734
@olamicheal734 7 сағат бұрын
Baba 1010
O ṢẸLẸ  AWỌN ỌMỌ TINUBU KỌ LU ỌBASANJỌ
4:16
Alaroye onlinetv
Рет қаралды 1,5 М.
When u fight over the armrest
00:41
Adam W
Рет қаралды 28 МЛН
Haunted House 😰😨 LeoNata family #shorts
00:37
LeoNata Family
Рет қаралды 16 МЛН
EYI NI ITAN OMO YORÙBÁ TO JÉ ÈNI AKỌKỌ TO DARÍ GBOGBO ÀGBÁYÉ
56:29
È WO BI SAIDI SHITTU SE ṢẸSIN
1:04:05
AROLE BABA 10 10 TV 1
Рет қаралды 5 М.
È GBỌ ỌRỌ BÚBURÚ TI MUFITY IWO TUN FI ESIN ISLAMU SỌ SI AWA OMO YORÙBÁ
1:09:10
ÌKÌLỌ PÀTÀKÌ FÚN ỌBA GHANDI TI ILU OGBOMOSHO
33:11
AROLE BABA 10 10 TV 1
Рет қаралды 1 М.
OONI ILE IFE! EYIN GANGAN LE WA NIDI IYA TOUN JE AWA OMO YORUBA
2:34:19
AROLE BABA 10 10 TV 1
Рет қаралды 4,7 М.
ALAIGBỌRAN LAWON NNPC YII O
6:36
Alaroye onlinetv
Рет қаралды 1,9 М.
Awon Alfa tu asiri Anobi Muhammad
21:10
Tani Olohun
Рет қаралды 16 М.
ỌBA OLÙWO RÁN AGBANIPA SIMI LATI WA PAMI MỌLÉ
34:01
AROLE BABA 10 10 TV 1
Рет қаралды 16 М.