OWO TE ALASEJU OMO @LE IWO MUFTIU IWO

  Рет қаралды 15,376

Lady k News Carrier

Lady k News Carrier

Күн бұрын

Пікірлер: 92
@AbosedeShofarasin
@AbosedeShofarasin 18 күн бұрын
Omo ale ni muftiu. Oloriburuku ni alaye baje eda
@beautywealth4935
@beautywealth4935 18 күн бұрын
Oriburuku naa ni Mufti ati Ọga rę ati awọn isọgbe rę maa ku si pęlu igo Ọlọrun
@folarinhassan7342
@folarinhassan7342 18 күн бұрын
Lead k olori buruku ni mufut
@beautywealth4935
@beautywealth4935 18 күн бұрын
Lagbara Ọlọrun Ọba Ashakę Aiyé, Ashakę ọrun, 2025 ayọ, itunu, alaafia ni o naa ję fun gbogbo awa ọmọ Yoruba laṣę Edumare. Amin Amin Amin
@olusholaadegoke4370
@olusholaadegoke4370 17 күн бұрын
Mufti Iwo eeyan Yinusa Toliat Daluru Daluru imam of Ogbomosho,enu Jawaya imam,ariwo lenu mic,enu mi gboro ,
@olusolaayindefakeye4426
@olusolaayindefakeye4426 18 күн бұрын
Gbogbo awon omo ale alabosi esin to fe gbe Sharia wo ile Yoruba, abosi lo ma bo won mole. Orile Ede Yoruba yio di olominira
@izukmidorya8711
@izukmidorya8711 18 күн бұрын
ORO .UFUTI JU OMO ALE LO TOBA RI ORUKO MI TI ALE PE EWO BI OHUN NA TIRI ENI OFO ENI ADAUN LE LEYI OOOOOO
@AderemiAdewunmi-q6e
@AderemiAdewunmi-q6e 17 күн бұрын
Oloriburuku ni nwon,ole ni wo n Banla nwon ko ti se so ile Youba di ti muslimi Gbogbo eyin te fe fi oro esi ba ile Yoruba je ni olorun yio ba je patapata lai ni atunse
@FunmilayoDeborahOlayiwola
@FunmilayoDeborahOlayiwola 18 күн бұрын
Lady K,otito Oro ni e so nipa Mutif iwo ati Oba Oluwo,won ti gba Owo lodo awon larunawa ni, gbogbo epe ti Mutif iwo nse , lagbara Olorun epe na yo jeti Mutif iwo ati awon ebi re L K wa ma taa lagbara Oluwa amin
@TemitopeSobowale-zl8tb
@TemitopeSobowale-zl8tb 18 күн бұрын
Ti ilu ba nro ponla ponla ju , o fe te ni . This man and his cohorts would never see the end of the crises they want to cause .
@AdebisiMichael-b9k
@AdebisiMichael-b9k 18 күн бұрын
Omo Ale akotileta oloriburuku ni Mufti ati oga re Emir Oluwo.
@FolorunshoTanimola
@FolorunshoTanimola 18 күн бұрын
Gbogbo eronko enia won kole fi esin alakatakiti kole fi esin di ise oluwa lowo
@AdesolaSikiru-fu9dv
@AdesolaSikiru-fu9dv 18 күн бұрын
mufutiu iwo komon outi won upeni esin olori buru niwan gbogbo won loloru mamu patapat
@beautywealth4935
@beautywealth4935 18 күн бұрын
Lady K well said, it will be well wt you for saying the truth. God bless you much. Thanks
@mukailaolaniyiabolade956
@mukailaolaniyiabolade956 18 күн бұрын
Gbogbo awon ota Ile Yoruba sise sise ni yio mabawon alale Ile Yoruba lomadawon ni ederu
@funkefasesin2381
@funkefasesin2381 18 күн бұрын
Ibukun ni fun orile ede Yoruba lagbara Oluwa Eledumare. Yoruba Nation now. Yio dara fun yin o eyin eniyan mi- Yoruba.
@adijatadenekan4589
@adijatadenekan4589 18 күн бұрын
Lagbara olorun oba ko ni bo ninu wahala re amen 🙏🙏 he should go to his northern fulanis area amen 🙏🙏
@AderemiAdewunmi-q6e
@AderemiAdewunmi-q6e 17 күн бұрын
Awa omo karo oojire ko ni gba,Awon na ti duo de nwon Esofun kio sora re
@folarinhassan7342
@folarinhassan7342 18 күн бұрын
Olori buruku ni mufut iwo
@makokin21
@makokin21 18 күн бұрын
We would keep that video for mufti iwo,eyan melo lo fe na,omo ale omo foolani,ole 419
@beautywealth4935
@beautywealth4935 18 күн бұрын
Gomina Makinde, o ṣee ooo, ilu Ibadan ko ni baję lori rę, aṣe yè, aṣe yę, aṣe jèrè loo maa ma ṣe laṣę awọn alalę ilę Ibadan. Oloriburuku ni Mufti ati Ọga rę awọn ọmọ ale ilę Yoruba ti nfi ọwọ òsì júwe ile baba wọn. Owó(money)ti wọn gba lọwọ awọn ti o ran wọn niṣę naa lo naa pa wọn pęlu aṣę Edumare
@cynthiaadeolaobafemi4450
@cynthiaadeolaobafemi4450 18 күн бұрын
Amukun eru e wo, oni oke lenwo ati isaele ni oti wo o, nigbati ti olori ilu Nigeria ti gba muslim muslim rulers kin won ma se olori ilu ti o jepe eleya meya esin ni o wa ni inu ilu Nigeria. Shioooooor
@scarcegoldgold3916
@scarcegoldgold3916 18 күн бұрын
MUFTI TAHUN, THE DAN FODIO OF IWO
@olusholaadegoke4370
@olusholaadegoke4370 17 күн бұрын
Yinusa Toliat ti launch re Logbomosho naa
@tonyrufus4965
@tonyrufus4965 18 күн бұрын
Oloriburuku muftiu iwo......imam olofo
@funmilayoodularu5244
@funmilayoodularu5244 18 күн бұрын
Oyo ni won ti fe bere kise ibadan
@beautywealth4935
@beautywealth4935 18 күн бұрын
Ati Ibadan ati Ọyọ kini Capital rę? Ṣebi Ọyọ ni
@daddywura5290
@daddywura5290 17 күн бұрын
Oloriburuku omoirankiran ni bobo mufti yen
@salaudeenadebisi1822
@salaudeenadebisi1822 15 күн бұрын
ISE OWO TI MUFTI IWO ATI OBA OLUWO GBA LOWO AWON SAUDI NI WON NSE LATI BA ILE YORUBA JE PELU ORO SERIA. OLORUN KO NI GBA FUN WON.
@AderemiAdewunmi-q6e
@AderemiAdewunmi-q6e 17 күн бұрын
Ale se kama ri omo alelarin wa .owo ye ni won fe AFI TI ABA NPA AWON OMO AIE ARIN WA NI OKAN KAN
@BolatitoSunday
@BolatitoSunday 15 күн бұрын
Ki Gomina Adeleke tete dide si Oro mufti iwo yio
@AfolabiOlajide-h1h
@AfolabiOlajide-h1h 18 күн бұрын
Se enu SEYI MAKINDE KO KA LATI CONTROL STATE E NI, O YE KI MAKINDE TI GBE WERE MUFTI YI SATIMOLE
@AdeolaAdedokun-v3w
@AdeolaAdedokun-v3w 18 күн бұрын
Yoruba nation no going back
@adeniyibankole-f1y
@adeniyibankole-f1y 18 күн бұрын
E je kon ma bo o! A ti da Mufti , Rashid ati awon toku mo. To ba doju sisu enu idi a la. I must say this, Yoruba need internal cleansing.
@gbemisokeonanuga3396
@gbemisokeonanuga3396 17 күн бұрын
O sese bere ni o.
@StephaneMoise-n8t
@StephaneMoise-n8t 18 күн бұрын
Aminoooô Aminoooô Aminoooô Aminoooô Aminoooô Aminoooô Aminoooô ooo Jesu oluwawa Amin
@MumeneRahmon
@MumeneRahmon 14 күн бұрын
Olo Ori buruku nio jo
@olabodeolajuwon4318
@olabodeolajuwon4318 16 күн бұрын
Werey mr seal aja to ngbo
@muritalaakande69
@muritalaakande69 18 күн бұрын
O ye Olohun
@FaugahAbolaji-b1f
@FaugahAbolaji-b1f 18 күн бұрын
Muffin Omo ale ni
@AFESOMUENITANOGBONNUTAPA
@AFESOMUENITANOGBONNUTAPA 18 күн бұрын
Ogbologbo omo aleni mufuti
@AderemiAdewunmi-q6e
@AderemiAdewunmi-q6e 17 күн бұрын
EMA FI IYE DERU BA WA MANDELA JIYA FUN IRAN RE KO SE AWON ENIA RE
@seyioluwaseyin8323
@seyioluwaseyin8323 17 күн бұрын
In a state where there are leaders, it's surprising that people like mufti Iwo.and others could be left unchecked. Is it when there's riot before these people would be taken care of?
@MichaelAlake-b3l
@MichaelAlake-b3l 17 күн бұрын
Yoruba Nation no going back.
@bukolaladyb7821
@bukolaladyb7821 17 күн бұрын
Awon Alale lo ntu aşiri won
@AFESOMUENITANOGBONNUTAPA
@AFESOMUENITANOGBONNUTAPA 18 күн бұрын
ORI iyalaya mufuti community tidaru
@iretiebiesuwa9071
@iretiebiesuwa9071 18 күн бұрын
E ku ise takuntakun
@FaugahAbolaji-b1f
@FaugahAbolaji-b1f 18 күн бұрын
Yoruba natiion now now now
@mamaiya6633
@mamaiya6633 18 күн бұрын
Rasheed Akanbi Oluwo ati Mufti Iwo ti fi ile yoruba gbowo lowo Arab world wipe awon yio so Ile yoruba di Afghanistan! But by the grace of God almighty who gave us the real Omo-Oko yoruba tooto our land will not allow it to be possible for them.I pray that may the good Lord almighty let it possible for us to get our yoruba land so that all these nonsense will stop over us in yoruba land! Yoruba Nation is the solution to it all,real Yorubas let us come together and get our own freedom out of Nigeria!
@beautywealth4935
@beautywealth4935 18 күн бұрын
Ko si nkan ti o kan awọn ọmọ Yoruba pęlu yęn, ki Mufuti ati Oluwo lọ da owo ti wọn gba pada fun awọn ti o fun wọn lowo lobatan
@olawale817
@olawale817 18 күн бұрын
So, how does Oluwo get arrested?
@KamoYisau-yg8yw
@KamoYisau-yg8yw 18 күн бұрын
seria kosi ni ilu iwo
@LamidiJamiu-h4y
@LamidiJamiu-h4y 18 күн бұрын
Yoruba nation no going back yoruba nation now now now
@AderemiAdewunmi-q6e
@AderemiAdewunmi-q6e 17 күн бұрын
SE,ESE SE MO NINOWON GBA OWO LATII ILE IRAN SAUDI,OPE TAO DA LOWO OLODUMARE NI PE ARI AWON MUSILIMU ODODO LARI AWON OMO YORUBA ODODO LARI AWON MUSLIM YORUBA
@aladesuraju5372
@aladesuraju5372 17 күн бұрын
Ex convict
@olurantiosadare1873
@olurantiosadare1873 18 күн бұрын
Lady K you need a good background to display your goods.
@OluwasanmiJacob
@OluwasanmiJacob 18 күн бұрын
He is a fantastic but he can't gain ground in Yoruba land. He has been brainwashed 😢
@loantha2996
@loantha2996 18 күн бұрын
you meant fanatic mohamedan
@aliduoladokun3222
@aliduoladokun3222 17 күн бұрын
OUR ISLAMIC SCHOLARS OF NOWADAYS ARE SHALLOW IN THINKING ,ISLAM DOES NOT AGAINST CULTURE AND NORMS OF ANY COMMUNITY. I AM A MUSLIM, MOST OUR ISLAMIC SCHOLARS ARE NOVICE IN UNDERSTANDING ALL ROUND KNOWLEDGE, ISLAMIC KNOWLEDGE PART OF KNOWLEDGE.
@FunsoAdeniyi-cr8pl
@FunsoAdeniyi-cr8pl 18 күн бұрын
ILE YORUBA NI A NPE IBI YI, AWA OMO YORUBA A NI: ASA,EDE, ISE, ESIN ATI IWA OMO-LUWA-BI KI ESIN -AJEJI,TO -DE SI ILE-YORUBA ,AWA OMO YORUBA A KO FE OFIN SARIA RARA NI-LE YORUBA.OMINIRA ILE YORUBA PATA-PATA KURO NIUN NAJIRIA NI AWA OMO YORUBA FE,KI GBOGBO AWA OMO YORUBA RANTI OJO- OLA AWON OMO WA O, ESAN A KE O, ADANIWAYE JO-WO ,M A SE FI WA SILE
@nurulahiimranalowonle5823
@nurulahiimranalowonle5823 18 күн бұрын
You're totally mad
@tayoakoni6356
@tayoakoni6356 18 күн бұрын
LadyK
@gracemenkiti2851
@gracemenkiti2851 18 күн бұрын
Yoruba Nation no going back. We have nothing to do with Sheria Law in Yoruba land. Please go to North and continue with Sheria Law not in Yoruba land.
@sakamoses606
@sakamoses606 17 күн бұрын
Of a truth this people are not doing this because they love Islam neither are they true Muslim but have been payed
@graceolushoto7115
@graceolushoto7115 17 күн бұрын
Owo 👐🏼 nilati tę nitori elebu ni Mufutiu Iwo bata 👟 rę ti nro ni aroju o dę lati tę patapata porogodo nitori new generation ni o wa ni ita bayi "NO GREE FOR ANYBODY" IS THE NEW SLOGAN NOW NO One can bring any nonsense or madness to Our Yoruba Land thistle is another generation entirely and we won't take it from anyone enough of all ur nonsense amongst us
@MatthewsJeje
@MatthewsJeje 13 күн бұрын
U r insulting ooni.y
@samueloluwashina633
@samueloluwashina633 18 күн бұрын
You need to talk in time you waste too much time for ur anaylist some people are using data
@AdebomiIsiaq
@AdebomiIsiaq 17 күн бұрын
This woman and this alfa onijekuje becarefull, fear ALLAH both of you saying robbish because you want sell clothes Insulting religion of ALLAH you will see your end
@KaflatKaflat
@KaflatKaflat 15 күн бұрын
Allah na Saudi god,not capital letter G
@AdebomiIsiaq
@AdebomiIsiaq 15 күн бұрын
You don't know anything you are unbeliever Bible said gentiles shall trust in Jesus name christian finished Islam is the best
@KaflatKaflat
@KaflatKaflat 14 күн бұрын
@@AdebomiIsiaq Islam is the best for your own view(,mumu).
@AdebomiIsiaq
@AdebomiIsiaq 14 күн бұрын
There is no religion except Islam if you die without Islam in the day of judgement you would perish
@BarclaysukPlcbank
@BarclaysukPlcbank 18 күн бұрын
Olosho your topic is not what u are saying oloriburuku
@ademuyiwa3898
@ademuyiwa3898 18 күн бұрын
U r more oloriburuku more than her
@olu7349
@olu7349 18 күн бұрын
Stick to your drug therapy, Bud. You are still not well enough.
@AbbeyKey-mh1lk
@AbbeyKey-mh1lk 18 күн бұрын
Yoruba nation no going back
14 Yrs In Prison For Stealing Chicken; Marvelous Update
14:17
Adeola Fayehun
Рет қаралды 77 М.
Tani Olohun versus ilu ilorin Lekan si
50:11
Tani Olohun
Рет қаралды 22 М.
Chain Game Strong ⛓️
00:21
Anwar Jibawi
Рет қаралды 41 МЛН
To Brawl AND BEYOND!
00:51
Brawl Stars
Рет қаралды 17 МЛН
IL'HAN - Qalqam | Official Music Video
03:17
Ilhan Ihsanov
Рет қаралды 700 М.
Moba Baba Iyawo mi lori Iyawo mi
1:04:57
Yinka TNT
Рет қаралды 15 М.
GANI ADAMS MA DOGUN SILE NI ILE YORUBA O OBA IFE KI ISE ENI ANRIFIN
38:27
Lady k News Carrier
Рет қаралды 3,6 М.
EMỌ RÈ OOO, MECHANIC GENERATOR NI EWỌN 26 YEARS.
1:09:02
Lady k News Carrier
Рет қаралды 2,1 М.
AWE 100 DAYS TI DA WÀLÁÀ LE SI BABA ADEBOYE LO RUN
31:31
Lady k News Carrier
Рет қаралды 10 М.
Chain Game Strong ⛓️
00:21
Anwar Jibawi
Рет қаралды 41 МЛН