Oluwa gba mi, ma je ki aye pa mi togotogo, ma je ki aye pa awon omo togotogo, ki araye ma so wipe o tan fun mi ati awon omo mi loruko Jesu
@olufunmioke3474Күн бұрын
I thank God for today's prayer
@adeyemiileaje4238Күн бұрын
Amin Jeeesu
@adeyemiileaje4238Күн бұрын
Oluwa fa mi dide tomotomo, so wa di eni pataki lagbaye, so awon omo mi di eniyan pataki, so won di eni nla, so won di olokiki laarin awon eniyan pataki laye loruko Jesu - amin Jesu
@adeyemiileaje4238Күн бұрын
Ogun ko se, ide ko ja, iji ko duro, ire ko wa sinu aye mi ati awon omo loruko Jesu
@florenceshobowale1273Күн бұрын
Amin Amin Amin Amin Amin Amin Amin ni oruko Jesu
@christianahfadipe1957Күн бұрын
Amin
@adeyemiileaje4238Күн бұрын
Gbogbo ohun ti ko fi aye gba ire lara mi ati awon omo mi, ina gbe jade loni, ohun to n dena ire ati aanu ninu aye mi ati awon omo mi, Oluwa fi ina gbe won jade loni loruko Jesu
@adeyemiileaje4238Күн бұрын
Ki ni n be lara mi ti aye fi n jeun, ni oruko Jesu jade, ki ni o wa lara awon omo mi ti aye fi n jeun, ni oruko Jesu ba ina jade, ina Oluwa gbe won jade lara wa loni loruko Jesu
@adeyemiileaje4238Күн бұрын
Ohun to n be lara mi ati awon omo mi to n da ire ati aanu duro, ina Oluwa gbe won jade loni loruko Jesu
@adeyemiileaje4238Күн бұрын
Amin amin amin Jeesu
@adeyemiileaje4238Күн бұрын
Emi ijakule ati idapada seyin jade ninu aye awon omo mi, emi ojukan ati ijakule jade ninu aye emi ati awon omo mi loruko Jesu
@adeyemiileaje4238Күн бұрын
Oluwa ko wu mi mi aye mi wa lojukan, ko wu mi ki aye awon omo mi wa lojukan, Emi Mimo mu wa kuro lojukan a fe tayo sinu ola, ibukun ati ogo tuntun loruko Jesu
Ona aanu mi ati awon omo mi la kedere lose yi, alaanu saanu fun wa loruko Jesu
@adeyemiileaje4238Күн бұрын
Oluwa mu ise mi ta yo, mu aye awon omo mi tayo, ni ile iya ati baba, Emi mimo mu mi tayo tomotomo mi loruko Jesu
@adeyemiileaje4238Күн бұрын
Ni oruko Jeesu, Emi Mimo, majemu ti kii je ki omokunrin tayo ni idile oko mi, lori awon omo mi, Oluwa ba je, gbogbo majemu ti kii je ki omokunrin laluyo, ti kii je ki awon omokunrin se oriire, ni ile oko mi, Oluwa ba won je lori awon omo mi loruko Jesu
@BukolaToluniКүн бұрын
Oluwa da ku wa ranmilowo Tomo toko eniyan ni mi o ni agbara