Arin Adabiyyah ati Markaz ko ni baje laelae, Alubarika Sheik Alimi lodo Olohun, Ilu Ilorin ko de ni daru pelu ogo Olohun
@ahmodshekoni15242 ай бұрын
Angbo yin ya sheikh
@issajimoh27012 ай бұрын
Ibanuje won ni pe, Mudir Markaz ko ku, toripe won fe ki Mudir oku ni, sugbon Alihamdulillahi Olohun ti doju ti won. Pelu ogo Olohun, gbogbo won ni asiri won ma tu lokokan laipe, atunbotan ti won na ko de ni da ayafi ti Sheik Adam tabi Mudir ba to si gbogbo iwa buruku ti won nwu