Mo fi ogo fun Olorun Loke orun ti o je kin je alabapin ninu oniruru adura iranse olorun Tunde Bamigboye.Adura ranti mi oluwa APA kinni ati ikeji so mi di eni otun,o yi oruko mi pada Lati ayalegbe di Onile.Oluwa ranti mi owo oluwa mu akanti kuro Lori ile ti mo ti n tiraka Lati ko lati 2005 laarin 21days. Mo gbadura ni oruko nla Jesu ifami ororo yan yin ko ni gbe,Oluwa a so agbara yin di otun.
Amin loruko Jesu , mo dupe pe owo Olorun ma dasi oro awon omo mi ati ogun ki nki la ala ki ma ranti lati isinyi lo.
@juliantiyamiyu81316 жыл бұрын
Ope ni fun Olorun wa Oba tikoje ki esu ati awon iranse re sope bee ni awon nfe ni ayemi ati awon omo mi ogo ye Olorun Olurapada mi oun lomu aisan ososu kuro ninu ayemi oyi igbami pada oso ayemi di otun, Ogo nifun oruko re mimo alagbara ni sioni eseun, dadi modupe fun pipe ti Oluwa peyin lati gbala ati lati tusile Agbara Olorun koni dagbere kuro ninu aiye yin ati idile yin oo ni oruko JESU Kristi Oluwa wa amin ifami ororoyan yin konigbe lailai amin