Eku et o sir, and any time you always come on program i always happy to hear from you about Yoruba status and way forward. Thank you baba..
@samuelfolorunsho58172 ай бұрын
Baba where are those people now? That story has comma sir.
@abolarinolayinka74762 ай бұрын
EKU ise o baba wa olorun a ma fun yin se o abo olorun a ma wa lori gbogbo wa o Amin Amin Amin ase Edunmare 🙏
@loladeakanji89712 ай бұрын
Baba mi ko ni baje fun yin se lase Edumare amin. E ku lakaye ba mi. Mo gbadun etoo yin. Lati UK. Eru gan ba ni ati wa si Nigeria.
@modinatsolomon75062 ай бұрын
Lo baa tan. Big time Jubilation all over even in Diaspora. I remembered very well. I was in the hair saloon that faithful day. A called came to my air stylist and she broke the News see Joy see Jubilation. It was like somebody won big lottery like to win baba ibeji big time. That was the Jubilation then.
@modinatsolomon75062 ай бұрын
Ti ifee. Oyaa ri kan le ni ooo
@usmanwahab62622 ай бұрын
Yoruba nation lafe
@modinatsolomon75062 ай бұрын
Allah Akbar. Ti tobi fun olorun. Omo Abeokuta ni Diyaa.
@modinatsolomon75062 ай бұрын
Aaanu ni ooo. Better.
@modinatsolomon75062 ай бұрын
Ipade apero nlaaaa. Ododoo oro ninoo.
@modinatsolomon75062 ай бұрын
Ejooor. FACTS
@TiamiuNurudeenolaiya2 ай бұрын
Yoruba Nation ni anfe
@modinatsolomon75062 ай бұрын
Allah beeni ooo. Awaa adee yee ra aa. Fun won oo. Beeni oo. Baba. Ohh bi egungun nii.
@modinatsolomon75062 ай бұрын
Eku eto baba. Ase se oo. Aaaaameen
@modinatsolomon75062 ай бұрын
Subuhanalilai. Awon eyan ebee ru olorun. So daaa bee. Allah Arkbar. Omaase oo. So SADD
@modinatsolomon75062 ай бұрын
Kabiesi olorun. Hummmm that was then. Ni gbati oti sii wa aa.
@modinatsolomon75062 ай бұрын
Iraa hausa fulani niii.
@azeezbabatunde95422 ай бұрын
Baba, Olohun ko ni pa lakaye yin. Emi yin o si gun. Mo feran ipe ti e mu wa loni. Omo alakata lo se bi obo ko gbon, obo gbon tinu obo lobo nse. Tinubu ko seleri kankan fun wa nigba idibo 2023 ju pe 'emi lokan' 'ma si tesiwaju lati ibiti Buhari ba de'. Emi ko gba wipe Tinubu bo sowo awon Fulani rara. Eni ti a ko nika to gba, o ni ika ninu teleni. Awa ti amo Tinubu bere lowo awon to ntele lasiko idibo wipe kini awon nkan to se ni Eko ti won fi gba wipe yi o tun Nigeria se, ko si eni to le toka si nkan meta pataki to se leko ju oselu lo. Eyi ti o wo mi lara ninu eto ti e se yi ni wipe kini ona abayo fun omo Yoruba lati kuro loko eru. Odaju eniyan gbaa ni baba yen, ilu nle o ni ki a lo fokanbale, di ojo wo? Olohun a gba wa lowo re o, amin.
@asaatiiseluyoruba13562 ай бұрын
Ameen
@modinatsolomon75062 ай бұрын
Subuhanalilai. Hummmmm
@sundayolowoyo9172 ай бұрын
Yio daa funyin baba mi
@modinatsolomon75062 ай бұрын
Beeeni
@hopealivewithevang.olubunm22872 ай бұрын
Gbogbo ohun ti CSI nso niyi. Se won ri support ni? Ote po!
@AdetunjiFatai-b8w2 ай бұрын
Eku ise yoruba nation laafe
@olaniyijaems19362 ай бұрын
Baba, they cannot do that because there is many King s the politician Kings, few of them original king
@foluhandelakinfosile31782 ай бұрын
Beni sir, ni kia kia Yoruba ti ye ko jade kuro ninu Nigeria ti pe. E ma je ki Tinubu da Yoruba duro si nu Nigeria. Nitoripe Olorun Oba ti fun wa se. A stich in time saves nine. Let's beware before it's too late. 21:00
@modinatsolomon75062 ай бұрын
Awon Yoruba ni inu iran kan so o. Hummmm
@modinatsolomon75062 ай бұрын
If owoo so owo opo. United they Stood. And They conquered. Back then. I don't about now?
@taiwohenryolajide12622 ай бұрын
E ku eto sir. (Idobale ni mo wa) otito oro gba le so Baba. Bi eru ba ko oke, to ko isale, o ni ibikan ti awon Baba n'la wa ma n'gbe ka. Ileke to ba ti fo, okun o le gba oju e duro. Nigeria o le da mo rara. Yoruba Nation ni kan lona abayo. E je ki afi orikori, ki afi ikunlukun, ki a le gba Yoruba kuro ninu ide ti awon oyinbo britiko fi wa si yi.
@modinatsolomon75062 ай бұрын
So SADD
@tajudeenaminu14292 ай бұрын
The forced marriage called One Nigeria can never never never never never never never work for ever, The only solution to the blood shed and poverty in Yorubaland is Yoruba nation
@hopealivewithevang.olubunm22872 ай бұрын
Sir, se o ye ki e bebe ki awon ti e nba soro mo ohun ti o ye ki won se lati ojo wonyi wa bi? Ki olukuluku di ilu ati agbegbe re mu . Ti Oluwa nile o.
@sundayolowoyo9172 ай бұрын
I think our major problem is: a ti si Oba Yan, this present Ooni is the highest disgrace in the entire Yorubaland, even far worst than Asiwaju, this Ooni is too greedy, and self centered man, he doesn't really care about anything concerning yoruba, all what he wants is food, wives and contracts, he's not an Oba, I was dancing and clapping when he was chosen, I didn't know he's just an alawada kerikeri man, Yoruba nation have no place in his heart, he's also doesn't care about all the Yorubas outside the country, like Cuba, Brazil, Haiti, Jamaica and others, not even in republic of Benin behind our backyard here, as far as baba see women oro orun won ti tan