Ah!! Ki olorun ki o sanu fun wa ni igbehin aiye yi, enikan so fun oko mi pe mo ti kole , sugbon mo so fun oko mipe mi o ni ile debi pe mo ma ko ile lai so fun oko mi. Ki awon eyan rora fun awon ti won ma jise ti olorun ko ran won. Ki olorum sanu fun wa ni orilede Nigeria, amin 🙏🙏🙏💔💔💔
@Adex9172 сағат бұрын
Love your music yoruba gidi Sugbon ki olorun ko gba lo awon amokun se ka
@SoulyaAtanda9 сағат бұрын
Otoju suni o olagbara gan ni ki olorun sanu fun wa ki olorun GBA wa o amin
@bamideleademolasalami242311 сағат бұрын
Olagbara oooooo, k'Olorun sanu wa oo
@adetunde66524 сағат бұрын
Thanks for the Good Work you are doing : True Spiritualists will know ( Diagnose) if these people has a MENTAL HEALTH ISSUE or they have SPIRITUAL PROBLEMS, from spiritual attacks !
@truthsquestions15325 сағат бұрын
Ki wor wadi awon obi e, its possible they too into bigger egbe okunkun that uses glory. Thats not IFA spirituality, but introduced spirituality into yoruba land
@TracyKnight-uq7gm7 сағат бұрын
Hmmm pelu igbagbo okan atI Adura lodo woli baba eri Hmm Honestly omi eri Tito lasan