Sir, ki nse gbogbo okunrin lo ma da bi ẹyin. Ikinni, obinrin gbọdọ so ara rẹ. Ohun ti obinrin ko le so fun ọkọ ko ma ṣe ṣe. To ba de sesi ṣe,pe ọkọ e, ko so fun. Ṣugbọn ma gba awa obinrin niyanju pe ki won rora. Awọn iwa to ba ti nwu ki o to fe ọkọ, ma se mọ ooooo, akoba nla gidi ni oooo.