Ika eniyan gbaa ni Kunle Ologundudu for rubbishing his friend shamefully like this in death. This is very unkind of this man.
@abiodunjhon88882 ай бұрын
All the people that wont to bring him down go and pass another way God is walting for them there agbala Gabriel continue your good work more anointing in jesus name
@BiolaTola2 ай бұрын
Well done my sister Mrs Biola Bolarinwa from Houston
@OlufunkeFajimolu2 ай бұрын
Baba suebebe said that Agbala should take him to wherever he is going & he should build a house for him in ibadan.
@madamsusan79582 ай бұрын
Pls where is Olushola yussuf ??? I hope she will come out and stage another show for U omoalalubarika iyalaje to moye olokan tutu bi adaba eniti inu Olorun dun si abiyamo oloja aaremo ti ki jeki Omo ko jabo . Look here and let me assure you u Egberu Olusola yusuff ti aye e ti jona raurau ko le gbe e subu Laila . Keep doing great baby girl ur good work is appreciated anyday anywhere !!!! Olushola Yusuf ti lule her looks is not appealing at all just like a sadist and so envious of U iyalaje Omo to gbaski to duro tan to tun ri aanu gba 👍👍👍👏👏👏Awa abiyamo toto Dey ur back gigigba .
@debraolufunlalemi78262 ай бұрын
Ologundudu gegebi ore to sunmo suebebe tobe,se koye kolo yoju si alagba Gabriel nigbati o wa laye ati lehin burial. Ore wo niyen
@oluremiajoke2 ай бұрын
ivalaje eku ise opolo loruko jesu opolo yin ko ni. daru loruko oke oke lema lo awon omo ti na wari anu gba nibi. gbogbo lona gbogbo amin
@ariyoitunnu23972 ай бұрын
Sue bebe himself asked Agbala Gabriel to take him to Ibadan in order to take good care of him. He was the one that asked him to build the house in Ibadan. Even no one can stand in his room then, even he was brought out on that faithful day before any interview.
@OduwoleOlabisi2 ай бұрын
Ologundudu opuro agbalagba ni yin sir. Dalerudaleru okunrin.
@biolasaka91832 ай бұрын
All I know is that all the enemies of agbala Gabriel will be put to shame by the grace of God
@omolaraadeyemo36892 ай бұрын
Amen ooo 🙏🙏🙏
@mhbj99022 ай бұрын
Aameen
@mummytriplets80792 ай бұрын
Our Lord Jesus suffered persecutions,they conspired against him for doing good to people. The Suffering of our Lord Jesus Christ should be Agbala Gabriel consolations . it is well with him.
@debraolufunlalemi78262 ай бұрын
Agbala Gabriel Amusan ko gbodo help lati kole fun enikeni mo,ibase ibadan or anywhere. Enough now
@mhbj99022 ай бұрын
Yes
@akinwolaclara4712 ай бұрын
Baba ti ko gbadun rara, Ole
@Princelandproperties2 ай бұрын
Iya laje thank God bless you, they just want to bring agbala Gabriel down but God won't give them chance
@mhbj99022 ай бұрын
Aameen
@titilayoomole72272 ай бұрын
Baba yi ti wo ara re Nile.
@omodaraTheresa2 ай бұрын
E k'use Iyalaje, Tani Ologundudu n pe ni a gbo Jesu ma gb'oyinbo gan an na? Se Ademilua omo Amusan to ti n lepa ijoba orun lati kekere ni Ologundudu n pe ni a gbo Jesu ma gb'oyinbo? Iwo to d'agba to bayi bawo ni Aarin Iwo a ti Jesu se Dan Moran si? Se oyinbo lo maa gbe Ologundudu de ijoba orun ni? Ohun ti aye yi ni Ologundudu fi n se igberaga si eni to ti Yan ona to Dara ju tie lo? Oyinbo melon ni Ologundudu gbo gan? Madam Olorun ko ni pada lehin yin l'oruko Jesu.
@toyinbakare72112 ай бұрын
Yes baba said so you are right 👍👍👍👍👍👍
@sampsonkomolafe8322 ай бұрын
Ologududu is so darft olofodudu
@andrewomotere38342 ай бұрын
Baba Ologundudu njabo ni sha agba tinde, epe awon Oloselu nja Ologundudu ni, Agidi lonlo ko gba rara pe onjebi Oro to so, ojeki awon nsepe fun awon Omo olomo, arugbo e ti do agbaya,
@FolukeAdeolu2 ай бұрын
Iyalaje please Don't let the pastor build house for anybody again because please are ingrate
@yemisioladapo20112 ай бұрын
Se eti togbo alo loma gboabo ni, baba you would have done proper investigation before jumping out to tarnish agbala Gabriel's image, . You didn't do well o ologun dudu
@olajideolasoji27082 ай бұрын
Ologundudu gbagbe wipe,ti oun bamò òrò ni sisò, gbogbo wa na mò òrò ni gbigbò. Èniti o se oju, ko dabi èniti o se èhin, ka dupè lòwò Òlòrun pèlu agbala Gabriel.
@toyinorry46592 ай бұрын
I'm so skeptical about this issue,how are we sure this is not d hand work on AJIGINNI & CO?
@olusegunAdenigba2 ай бұрын
Ologundudu 5and 6 pelu BABA Dayo Ore timotimo kilo de to ri iranlowo kankan se fun ninu aisan ati igba isinku iru ore wo leyin, ologundudu e wa nfi oro re kewi lati fi pawo, BABA e toro IDARIJI ESE .
@odunolaalli67732 ай бұрын
Ologundudu ko gbadun o, Pastor must take dis man matter up‽
@funmilolaomotoye49172 ай бұрын
Whatever agbala Gabriel did ologindudu can not do half
@OlufunkeFajimolu2 ай бұрын
Where is this man when Agbala Gabriel went to ekiti to bring baba Suebebe to ibadan. What was his problem now, no one sent him messages.
@debraolufunlalemi78262 ай бұрын
Suebebe was not a responsible person but God mercy sent an Angel to take care of his end life,no single person. So the person angel now is the bad person kowa siro owo hunnnnn
@kunleogunmoyela68752 ай бұрын
Ologundudu behaved like an irresponsible old man. If he has sensible children, I think they should talk to him and monitor his interactions with people. He’s probably going senile.
@odunolaalli67732 ай бұрын
Awon wo ni akose ma se freedom? Baba yi o gbadun o. Agbala should take this baba to court bcos he did not sober abt what he did.
@adefunkebello95002 ай бұрын
Ti, yoruba ba kin yin,E ka ro.E lo wo oju orun .A bosi po
@FolukeAdeolu2 ай бұрын
Sorry because people are ingrate
@OdunRuth2 ай бұрын
Edakun elo ni awon oloriburuku ajinginni fe san fun olgun dudu tohun naa fi di oloriburuku bi tiwon
@omolaraadeyemo36892 ай бұрын
Yes baba Suebebe said it ,i heard it very well, Suebebe lo so be pe ki nwon le maa toju re nibe,e ye Rubbish ara nyin lowo awon omo to kere siyin bi ti GABRIEL,e BERU OLORUN oo, lastly NIGBATI NWON se donation fun Suebebe,sebi American le wa , how much is ur contribution oo
@adenadi97102 ай бұрын
Bi emi se ri oro Ologundudu si ni wipe alaropin ni. Ko reti nkan rere kan lati sele ni sakani Sule Suebebe. O so ninu oro e pe Suebebe nfi akoko sofo ni at wipe out fi won sile lodo Sunny Ade, oun lomulo siAdo Ekiti, o gba ile fun. O ni o nfe iyawo kiri, o mbimo kiri, onmutikiri. I am not sure this how to describe someone you claim was a long term friend. Ologundudu has just revealed he lacks any real value as a friend. If there's any man or woman friend who is yet to reconsider their relationship with this devil. The end result is not worth contemplating. Only if the dead can see what they leave behind.
@theophilusoniyide36972 ай бұрын
Oro ologundudu alaje fenu nule bi ediye ti di Igbe kinkinni leti awo gbegiri, won ni ki a nu kuro ki a ma jeun lo, bi oju ba kuro nibe se okan le kuro nibe ni?
@OdunRuth2 ай бұрын
Bi oluwa ti hun be ologundudu koni jere gbogbo ohun to faye re kojo tomo tomo kinni lode laduru aanu tori gba ohun de tun rin ninu ibinu olorun
@OdunRuth2 ай бұрын
Ologunddudu ti hun iwa kan si olorun ti olorun si fe fi se esin lomu ki osi iwa huki ohun pelu koja sinu gbogbo ilu ejigbo okuta ni won osolu nibe eni itiju lologundudu pada da
@OdunRuth2 ай бұрын
Emi nitemi maun wo ologundudu bi eniyan kan babara ase won yepere to bayi
Se ile ni awon omo fe wa wo ni abi alafia baba won? Se Ologundudu ko le se nkan to nso yi fun ore e ni?
@OdunRuth2 ай бұрын
Olorun ngbo Oju elewi pataki kan ni mofi maun wo baba yi ase emi naa lefi 10k bee won nise nibi taye won baje de
@OdunRuth2 ай бұрын
Ologundudu lati oni loo anu olorun jia sio tomo tomo re
@OdunRuth2 ай бұрын
eni ete dajun
@OlarewajuJuliana-u8w2 ай бұрын
Ika ni Kunle ologuun dudu saliu elenu gboro were
@OjeyinkaFlorence2 ай бұрын
Boya won gbowo fun baba yi pe ko kewi ibaje owo si ti baye je o ga o
@OdunRuth2 ай бұрын
Eni ti koni iru eni kole monyi eni bi ologundudu ba bi awon omo ologo toni laari bi ti agbala yio ni iberu lati hu iwa oponu bee
@aminouadidja90572 ай бұрын
Iya laje epe agbala keba soro dada tioba fe kole fun awon eyan komakole fun won sita
@FAMOTEMITEMILADE2 ай бұрын
Ko ti e si ile kiko Kan Kan mo fun enikeni ki awon ebi muideen ati awon baba Ologundudu le je ki omoolomo o raye gbe
@aderemiajayi6792 ай бұрын
We no dey build house for people again na foundation house we dey build now, enough is enough
@akinwumioluwafikayo35542 ай бұрын
Ologundudu fuck up in big term Alabosi eda ni, the only truth he said was the fact that Oriyomi was the brain behind Muideen saga. Ologundudu said it was Oriyomi that helped Muideen to claim his house from Agbala Gabriel.
@aminouadidja90572 ай бұрын
Iya laje baba suebebe sobe agbala lobere wipe baba ije emo ohun tofa ti awon famili kofiwawoyi baba suebebe ni awon komo amo ohun ti awon roun sini pe boya ile tiwon kole si adoni gbogbo awon omo baba suebebe naa kobere baba ejeka soro sibi oro wa ohun ti agbala se koda
@Princelandproperties2 ай бұрын
Ki lo se ti ko da.... Melo ni iwo ti se to da... you are just commeting nonsense
@hannahagboluaje90032 ай бұрын
Kinni Agbala se ti ko dara, e si beru olorun,. Where were you, when Agbala went to his hut to bring him out, can you please have the fear of the Lord by honouring him, for what the Lord is using him for.
@godisgreatalways62082 ай бұрын
What bad has Agbala gabriel done? When hope was lot for baba suebebe, God sent this prophet to him, his family and children rejected him but Agbala found him and took care of him through the monies his fans contributed for him. So what has he not done well.
@omolaraadeyemo36892 ай бұрын
KINI ko dara MBE OO, SEBI Suebebe GAAN lo fenu e so jade wipe IBADAN ni ki nwon KO ILE SI FOUN ,ki o le ma RI ENI TÓJU RE NI BE, Agbala Gabriel SI SE ITOJU E NI TI OLOJO Fi DE,,ko SI SI ENIKENI Kan TO LO beere Re nibe To fi KU,every OLORUN