BÀBÀ WÁLÉ FADU KO SI ENI TO LE DENA WÁ ÀFI ÀWỌN TO BÁ FẸ́ PARUN, TORÍ KO SI BABANLA ẸNIKẸ́NI TO LE DENA ISE TÍ ỌLỌ́RUN TÍ PARÍ DÚRÓ LÁṢẸ ÈDÙMÀRÈ, ỌPẸ NI KÍ GBOGBO WA MA DÚN FÚN ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ TO FI ÀNU RẸ TU WA SÍLÈ LAI JAGUN, ÒGO NI FÚN ỌLỌ́RUN LÓKÈ ỌRÙN HALLELUJAH HALLELUJAH HALLELUJAH
@alabaadejumo535Күн бұрын
BANJI AKINTỌLÉÉ, THE DEBUNKER. AWA YẸ́ MA ṢẸ RÉÉRÈ..
@idowuajagbe961422 сағат бұрын
Provesor banji akintoye the bunker
@clemawosika66822 сағат бұрын
Arole Olofin Otufe,Oluko Agba.
@KemiAdenuga-v1qКүн бұрын
Thank you mama wa
@GbemisolaOgungbemi67Күн бұрын
ÌYÁ WA AROLE OLOFIN OOTU UFE
@oluwakemiadenuga4041Күн бұрын
Ekueto o Baba Wale Ali a ma ju yin se o lase Edumare
Ẹ lọ jáwọ nidi ọ̀tẹ̀. Ọdàlẹ balẹ lọ. Ìyá yín Onitiri dà? Awọn ọmọ yín to fẹ gba jọba niibadan ti fẹ ẹ kú tán.
@adebayoadesola940817 сағат бұрын
Aape ko to ye e oju e mato ja
@o.oademola410814 сағат бұрын
You must be commenting for money?
@alabaadejumo53510 сағат бұрын
ọmọ yorùbá ko da owo fùn yin mọ, aṣírí ba tuu, ẹyin alabosi dédé, oku alfa ati adogan ṣẹ ẹyin ti gba? ẹyin ọmọ álé yorùbá. gbogbo wa fẹ gba ilu wa, kalẹ, kabọ niun oko ẹru, gbogbo yin sọ di business ẹfi kawo si apo ara yin. inun yin ndun. Onitirí fi document gba ilu fun wa, ilẹ wa ti duro, eyin ni ẹ lè process ẹẹ.. ko ni pẹ ti o ma yẹ gbogbo yin. ẹ ṣẹ suuruu.