Egbe OPC tele tu asiri nla o! o wí pé Ganiyu Adams jẹ ẹniyan ti ko fẹ ki eniyan miiran di nla bi oun

  Рет қаралды 28,331

OÒDUA TV WATCH

OÒDUA TV WATCH

Ай бұрын

Join this channel to get access to perks:
/ @ooduatvwatch
Also join our telegram channel for more update and also report what is happening i n your area
t.me/+WARKIrVvFHs0NDU0
OÒDUA TV WATCH is an indigenous and English media that Is base on political analysis, news Update and also promo Yoruba culture, traditions and history to the world.
DISCLAIMER: This Channel Does Not Support Violence In Any Way..

Пікірлер: 132
@abiolaoyebade7824
@abiolaoyebade7824 Ай бұрын
Your presentation is very appreciated sir
@AysteveAworetan
@AysteveAworetan Ай бұрын
God bless you my brother more grace odua agbe wa o
@olanikehammed8184
@olanikehammed8184 Ай бұрын
Afemi afemi lo fe baye Gani je.
@user-bj3jv4kp1k
@user-bj3jv4kp1k Ай бұрын
Good evening sir my brother, happy Sunday sir...See My brother if l didn't hear ur voice believe me,,mi o ma bo se maa n se mi (wallahi tallahi) thanks for voice,, thanks for this message God bless u sir...l Love u,,❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤
@kemoblunsky3794
@kemoblunsky3794 Ай бұрын
Very selfish and arrogant guy, GANIU adams is nobody in yoruba land of today, oti te poo, oloriburuku ti o n pe CSI ni omo oun, very rude guy.
@matthewaderigbigbe4335
@matthewaderigbigbe4335 Ай бұрын
Olorun eledumare a gbo adura baba tohun soro yi o original omoluabi oodua thank you so much
@user-nj3qx4xh2d
@user-nj3qx4xh2d Ай бұрын
III swear i will join OPC new era and fellow igboho oshaaa to the fullest 🖐️🖐️🖐️
@bolanlealaba9104
@bolanlealaba9104 Ай бұрын
Yoruba nation is the problem of adamu ganiyu
@adenikebabatunde1407
@adenikebabatunde1407 Ай бұрын
JANDUKU NI GANIU ADAM, HE IS WORSE THAN BOKO HARAM!! HOW CAN THE GOVT. KEEP ON TOLERATING HIM.
@cosmasadebowale5877
@cosmasadebowale5877 Ай бұрын
Good Comments from this man .
@sakaadams920
@sakaadams920 Ай бұрын
God bless you brother. You have said it all . More wisdom brother.
@estheroluseun6188
@estheroluseun6188 Ай бұрын
God bless you sir. He needs to be taught a lesson why he should know where he belongs to. Definitely he is not from the Yoruba race. Everyone in that position will face the wrought of God. The blood of the people they have killed and still planning to kill will fight against him and his followers. Judgement has come upon them. So shall it be. Amen
@hadi2artgallerytv
@hadi2artgallerytv Ай бұрын
Tenumo Baba mi 🙏🏾🙏🏾🙏🏾🙏🏾😮 💪🏾💥🔥🔥🔥
@user-ql8zn3bh1q
@user-ql8zn3bh1q Ай бұрын
I just love this man! He's saying the truth and he seems to know much about Gani Adamu's atrocities and he's ready to reveal more.
@pauladebisi9238
@pauladebisi9238 Ай бұрын
Please let him be in jail for the rest of his life 🙏 and there should not be excuse for him to say😭
@gluckdayoma9979
@gluckdayoma9979 Ай бұрын
I believe you On the ajagun gbale aspect
@abolu3564
@abolu3564 Ай бұрын
Thank you for wisdom talk ❤
@user-bj3jv4kp1k
@user-bj3jv4kp1k Ай бұрын
Koda Mo ma n download massage yin lati maa tun gbo ni,, God bless u..we will be expecting more.
@AysteveAworetan
@AysteveAworetan Ай бұрын
I think opc need to be cancelled
@FortuneoneTv
@FortuneoneTv Ай бұрын
Not the solution
@kadiritomi2353
@kadiritomi2353 Ай бұрын
Thank you brother for ur boldness on this piece, may Almighty Allah continue to grant you more wisdom and protection in every ways of life and ur household, aameen. Much love omo oko ile yoruba Yoruba nation no going back
@user-no8gn2lt8o
@user-no8gn2lt8o Ай бұрын
Whenever u want to talk on the Yoruba platform pls do not attach foreign larubawa language allah again
@mamaosun3587
@mamaosun3587 Ай бұрын
@@user-no8gn2lt8owhy not? Must people change the way they talk, to talk about Yoruba nation? Pls don’t, let people talk naturally.
@godwinjames4477
@godwinjames4477 Ай бұрын
Sunday igboho osaa is hero in yoruba land
@akinmoluakinsobo63
@akinmoluakinsobo63 Ай бұрын
Gani maa pe lewon.Yoruba nation a ti duro ki o to do😊
@olanikehammed8184
@olanikehammed8184 Ай бұрын
Gani idamu adugbo,o ti pada te alabuku.
@sundayolowoyo917
@sundayolowoyo917 Ай бұрын
Omo ale nla gba niwon, elei ti o dabi bororo yi to pera e ni oshi are, talo mo boya fulani ni Baba e
@florenceadedeji3858
@florenceadedeji3858 Ай бұрын
Eyin Oba ile Yoruba kilati fe se oro oloriburuku Omo ale Ganiyu lge Abiodun Adamu yi si ni ile Yoruba oooooo...eyin Ganiyu lge Abiodun Adamu Opc members kini isoro yin???? Se Ganiyu lge Abiodun Adamu ko bi omo tie ni ??? Se ko le ran awon omo tire nise iku ni????eyin OPC members Ganiyu lge Abiodun Adamu e pada leyin Ganiyu lge Abiodun Adamu....e ma je ki Ganiyu lge Abiodun Adamu pa yin tan ooo
@angelabailey8748
@angelabailey8748 Ай бұрын
God bless you ❤❤❤
@richrich6950
@richrich6950 Ай бұрын
Looks at ganiyu adamu very well is not a true yoruba son.
@christianaholopade8690
@christianaholopade8690 Ай бұрын
Ah uncle you really tried in this race. Right from the battle front of onitiri. You have the same behaviour with oloye. We say thank sir. ( Eku aduro ti oloye o. ). Awa yoruba dabi Aguntan ti ko ni Olusho. But God of Istrael at the Red Sea. David during the war of saul and Goliath is alive. Psalm 121. And 91. We Yorubas should be reading it dailly and increase our prayers for our land. ( father the creature of Yoruba land. Have mercy on us. ) Deliever us from the hand of the Midianite who are spoilling our farms and killing us on the daily bases.
@emmanueladeleye7982
@emmanueladeleye7982 Ай бұрын
Omo ale ni Gani Adams ati Awon elegbe re
@taiyebakare4445
@taiyebakare4445 Ай бұрын
Omo ale ni ganiyu omo tapa. Ashiri ganiyu adamu ntun ni kan kan bayi, gbogbo iwa janduku ati ko ma ba ti enian je on lo nbi ganiyu ba yio. Eni ibi ni ganiyu. Dethrone the basterd!
@richrich6950
@richrich6950 Ай бұрын
That Gani opc factions need to be canceled is no more for the interest of yoruba people 😒 Capital No
@user-fj2yo6jp5h
@user-fj2yo6jp5h Ай бұрын
Gani gbin iwa ibaje ati oro sinu awon omolehin re.Lehin Gani ba ti yo kuro ninu egbe OPC o dara ki OPC wa ni isokan tabi ki nwon elomiran.Dajudaju Are Onakakanfo titun gbodo waye laipe laijino pelu ogo Olorun.
@florenceadedeji3858
@florenceadedeji3858 Ай бұрын
Eyin OPC members Ganiyu lge Abiodun Adamu e jeki orin yin pe ooo
@user-xy8ve1bi9s
@user-xy8ve1bi9s Ай бұрын
Hmmm Olagbara Oo😢 Olorun Agba adura gbogbo wa lowo wan o, Areyin ota Ile Oodua ni ase edumare🙏
@taiyebakare4445
@taiyebakare4445 Ай бұрын
E ku ise ilu jare. Enin ibi ko le she ko ma je iya ese e. A je laiye atun lo je lorun, on ni oro ganiyu adamu
@josephmaito213
@josephmaito213 Ай бұрын
GANIYU ADAMU TI GBAGBE NI WIPE, OLOGBON AIYE KAN KO LE GBON TITI KO TA KOKO GBON E SETI ASO, OMORAN KAN KO LE MO TITI, KO MO IYE IYEPE ILE.
@user-me1wy2qq3z
@user-me1wy2qq3z Ай бұрын
Excellent speech ,God bless u my bros for saying d truth. God revenge is very crucial
@taiyeajiboye3968
@taiyeajiboye3968 Ай бұрын
OPC kilode ti won lo ba wa koju awon fulani,alabode Nii Gani Adamu ko unkankan se,eni ti o fe se ilara gani adamuko je ki won se,olorun a gba agbara lowo won.Baba adie abolorun ti o dagba,ti ko danu,Ti e ba le pari ija,ko yen ki e dakun,ti e ba ja owo lori oro Yoruba land,alale yoruba a da ejo to ye le yin lori eyin ika,alabode,onijekuje,onilara,ole alale yoruba a bi yin.gbogbo orii ti fulani pa.a fi iya to to je yin ni ase edumare.
@akataman7319
@akataman7319 Ай бұрын
Remove the title of “Aare Ona Kakanfo” from Gani Adam and his arrogance will be over. He has no power but mouth, and he’s a traitor to Yorubaland.
@cosmasadebowale5877
@cosmasadebowale5877 Ай бұрын
Oyo Mesi should do the needful.
@josephmaito213
@josephmaito213 Ай бұрын
ME TOO, I'M PART OF OPC BEFORE, WHEN I GET READ OF THEM, I QUIT THEM, I KNOW ALL THERE SECRET ALSO, YOU KNOW THEM TRUE TRUE.
@graceadeyemi7970
@graceadeyemi7970 Ай бұрын
You are Wright my brother alale yoruba a fi ya je gang .
@samuelogunlaja7451
@samuelogunlaja7451 Ай бұрын
Ose omo Yoruba original (eso e brother mi)
@AysteveAworetan
@AysteveAworetan Ай бұрын
Gani ole pads his destruction has come
@adeyemoademolajammy2002
@adeyemoademolajammy2002 Ай бұрын
Bi inu ile kan ba n toro omo ale ibe ni o ti dagba, omo ale ti dagba bayi ooo, ki olorun oba olojo oni ba wa mu, omo ale kuro lori ile.
@kazeemganiyu8160
@kazeemganiyu8160 Ай бұрын
Gani gani gani, oruko ti adamu hun je ni o fe le mo oloye igboh Lara,baba to hun soro yi mo gani adamu dele dele, ko si Ohun ti won fi paro mo gani, Ohun ti gani fi oju alaka ri ni Ibadan ni ki a so ni.
@kazeemganiyu8160
@kazeemganiyu8160 Ай бұрын
Ibo ni gani ti ri gbogbo owo to hun na fun Awon Olori, eni to je pe Ohun fi oruko omo Yorùbá wu iwa aburu ni.
@florenceadedeji3858
@florenceadedeji3858 Ай бұрын
Eyin alale ile Yoruba ooooo9 e gba agbara owo ati agbara ipo lowo Ganiyu lge Abiodun Adamu ooooo
@olasijiolajire4656
@olasijiolajire4656 Ай бұрын
Ooooooooo amaa gba lowo eh , gani gani gani, yoruba roo loyee 😂😂😂😂😂😂
@kazeemganiyu8160
@kazeemganiyu8160 Ай бұрын
Awon agba gba to mo iwa gani po, ti won ko si fe soro ni to ri pe, awa hun wo pe won ko fe ki hun kan ba je, ja hun du ku ni man yen hooo, owo re ko si mo ra ra.
@estherewetuga8245
@estherewetuga8245 Ай бұрын
Otunba OKIKIOLA Taiyese e ni so oro tan baba Ganiyu Adamu is too proud , cocky, jealous man and too full of himself I think Gani Adamu is heading for his own destruction that is why he want to destroy Sunday Adeyemo Igboho Oosaaaaa Ganiyu Adamu o ti kolu eniti ko ye ki o kolu. Sunday Igboho is our great hero International Sunday Igboho a man who saw tomorrow full of love with a heart ❤️ of gold We love Sunday Igboho so much, May God continue to keep you safe, all your enemies will fall under your feet Sunday Igboho Oosaaaaa Ganiyu Adamu is working for the Fulanis Oluwa ti gba wa lowo Ganiyu Adamu Oju ti ti Ganiyu Adamu Yegede re oju ti e Ganiyu Adamu Ganiyu Adamu ti si se aya ko o si fila lori baba Bola Ige, omo ita ni Ganiyu Adamu, omo buruku Remo a jewo fun were alakoruwo, o ba pin e Ganiyu
@user-bj3jv4kp1k
@user-bj3jv4kp1k Ай бұрын
brahismail to sope fake report iku (ORO) lomaaku,,iku (ESIN-IN)lo maa pa e ,,pls inu osu to n pari loyii,,ola awon ti fulani ati gani atawon OPC ti pa danu..OFO lomaa se ibrahimsmail
@oluwafemijohnmiracle9877
@oluwafemijohnmiracle9877 Ай бұрын
Aseedumare
@adesumbooginni4762
@adesumbooginni4762 Ай бұрын
They will do that because that is where they are eating they did not care if Yoruba people died for fulani because they are gaining from fulani people ile Yoruba a gbe wa odale Yoruba nikan ni o ni gbe eku eto e si ku otito inu
@AysteveAworetan
@AysteveAworetan Ай бұрын
Gani has no power
@omolaraogundare7989
@omolaraogundare7989 Ай бұрын
I and my entire family are fighting Ganiyu Adamu and my tribe the Yorubas.
@MJG135
@MJG135 Ай бұрын
Omiyale realy exposed GANi today, almost everyone forgot how Gani took out cap from BOLA iGE HEAD and beat the baba head with the cap, that’s shows GANI contribution to LATE BOLA IGE DEAD.
@titilayocrowther9669
@titilayocrowther9669 Ай бұрын
Awon ti won joko si abe OPC ti Gani Adams, ibura ti won jo se ni o nja won ni aya. Elomiran de je eni ti ko mo nkan ti o fe. Oni iwa ki wa eda! Ojo ti o ti di olori APC ni gbogbo e ti wo.Gani Adams OPC se kiss larin NNPC Ejigbo ati Ijegu Ikotun. Ni asiko campaign fu 2nd tenior Tinumbu as a governor. Emi sonu lai mo iye.
@afusatarowolo2268
@afusatarowolo2268 Ай бұрын
ALLAHU AKIBAR
@oluwalanaolubunmi2567
@oluwalanaolubunmi2567 Ай бұрын
We came to social media to begin to open our yansh. Oga ooooo
@florenceadedeji3858
@florenceadedeji3858 Ай бұрын
Ganiyu lge Abiodun Adamu olorun yio se idajo gbigbona fun e lori oro Yoruba Nation movement ati lori oro Sunday Adeyemo lgboho....
@adeomoade6682
@adeomoade6682 Ай бұрын
Aaamin
@adeomoade6682
@adeomoade6682 Ай бұрын
Ègbón mi, Sunday Adeyemo, ( Ìgbòho Òòsà), wà pẹ bí mope tí npè, apá apa kàn kìí kà apa o, àpá ọmọde kíì ká ìgi oṣe, apá ọta koni ká yin
@olatunjiunique9061
@olatunjiunique9061 Ай бұрын
Aare ona Kako ofo . Yoruba nation is his problem,he doesn't want self determination for Yoruba because he's secret wil open. Gani Adam has never volunteered say I'm Yoruba and I want Yoruba freedom. Awon omo ale Ile Yoruba niyen.
@AkinolaYisa
@AkinolaYisa Ай бұрын
A o le gbagbe Sunday igboho, nile Yoruba nitori oun lo ji gbogbo omo Yoruba kuro loju oorun lati Le wa ja funrawa ati fun iran wa.
@user-op6mp4ov9t
@user-op6mp4ov9t Ай бұрын
❤🎉
@afusatarowolo2268
@afusatarowolo2268 Ай бұрын
EKU ETO SIR EKU ISE TAKUNTAKUN OOO
@DayoAdewale-os3jz
@DayoAdewale-os3jz Ай бұрын
We're won onise orire oloriburuku niwon
@OyeledunOla
@OyeledunOla Ай бұрын
Gani adams Supposed to be Stripped Of his Chieftaincy title.
@gsjhsgshsusbbgshshshsjs5703
@gsjhsgshsusbbgshshshsjs5703 Ай бұрын
Eyin Omo yoruba esji ewoju adamu se ojo oju Omo yoruba tapa leleyi oju Le koko
@princeabimbolasalami7715
@princeabimbolasalami7715 Ай бұрын
Governor Makinde of oyo State should disbanned OPC immediately to avoid BLOOD SHED
@adesinaolatunde5551
@adesinaolatunde5551 Ай бұрын
Sir more power to your elbow l really appreciate your effort, but for christ sake there's particular man baba ooda ward wide ASHAOLU FAMUNSANMI by name the man still alive his now one hundred and thirty years by age, the baba has a lot to testify about this man called Gani Adams l don't no if it might possible to grant this baba 0odua ward wide permission to talk or narrate a little bit story about the this man called Gani Adams ẹru a ba àwon eniyan kọja ohun ti a nsọ yi, please l so much appreciate if you can get it touch with him, ẹ o gbọ winrinwinrin ọrọ lẹnu wọn ẹru a bayin
@abayomi.amenolasupo2713
@abayomi.amenolasupo2713 Ай бұрын
Gani ti ba de oju e o ma lo se won ni agbara Olorun Olodumare
@idowubakare3325
@idowubakare3325 Ай бұрын
Olorun oba maa pale Gani Adams mo kuro ni ile Yoruba lase edumare.
@user-nj3qx4xh2d
@user-nj3qx4xh2d Ай бұрын
Oooooooooshaaaaaaaaa number 1 of Yoruba Land ♥️🤣🖐️🖐️♥️♥️🖐️🖐️🤣🤣
@adeolajoshua371
@adeolajoshua371 Ай бұрын
Awon to ntele Gani Adams,enia buruku Lawon naa, ika lontele ika.
@adeomoade6682
@adeomoade6682 Ай бұрын
E kú iṣẹ takuntakun, Eledua yóò Máa fún yín ṣe, awọn onilẹ́ koni deyin lẹyin gbogbo ọmọ Yorùbá tọkàntọkàn ni'le, l'oko, l'ajo ati lẹyin odi, E jọwọ, ibeere mi nipasẹ awọn ọmọ ẹyìn Ganiyu Adams 17 to wà latimole latimole, kíní igbesẹ wà tí a lé gbé lórí wọn ?
@joelbalogun9254
@joelbalogun9254 Ай бұрын
Fulani ni Gani Adams jise fun. Eni epe ni Oloriburuku odale ni. Idile olote odale ni Gani ti wa. Sebi baba baba e won le won kuro nilu tapa nitori Iwa idale.
@janetagunlejika5752
@janetagunlejika5752 17 күн бұрын
Olin to wa assist god
@florenceajiroba5776
@florenceajiroba5776 Ай бұрын
A je wipe Gani ni Baba obo, baba omugo
@josephmaito213
@josephmaito213 Ай бұрын
MY BROTHER, NKAN TI WON MA JE, KO JE KI WON GBON NI.
@ogboabeyone
@ogboabeyone Ай бұрын
E ba wa so fun won ooooo esply adagba ma danu osi weerey, abora agbalagba e
@damifatima959
@damifatima959 Ай бұрын
❤❤❤❤❤❤❤
@ditty6828
@ditty6828 Ай бұрын
His not suppose to play with stone not to talk of throwing the stone out.
@user-ue3ew6lq5s
@user-ue3ew6lq5s Ай бұрын
adara fune baba oni subu danu koseni tolegbagbe majasola igboho osa afeni toba yomo ale awon olebitiena lokojo eniti kiba sole bitie akuro leyine
@mamaiya6633
@mamaiya6633 Ай бұрын
Gani Adamu omo nobody. Omo koni iran. Let all of us Omo-Oko Yoruba tooto banish Gani Adamu, like the way they banished his grandfather out of Epimi Akoko and he ran to Arigidi Akoko. So that we can have peace in Yoruba land.
@sakaadams920
@sakaadams920 Ай бұрын
I have been saying it that he has nothing. Empty barell makes the loudest noise. He should be dethroned and back to Nupe land as motor tout .
@user-qx1lw1gm7n
@user-qx1lw1gm7n Ай бұрын
MY BROTHER E PARO MO GANI ADAM KOLE SORO KI WON SORO LE IGBERAGA RE PO TI AWON ONIROHIN BAWA SE IFOROWERO PELU GANI KO KI GBA KI ONIROHIN SORO LE ORO TOBA SO AWA JAGBE ONIROHIN PE JEKI NSORO ATI GBAGBE PE ORI AFEFE NI OHUN WA IGBERAGA TI PO JU
@ditty6828
@ditty6828 Ай бұрын
gani Adams ri man na fin ju ju. Buoda Tinubu 😂😂😂😂😂
@sussanahogunbo6681
@sussanahogunbo6681 Ай бұрын
BABA MI ORO RE MUYAN DOKO ODODO ORO LE SO OLUWA A GBE WA LEKE OTA ILE YIO SI MU WA DE ILE WA LAYO YORUBA NATION NOW NOW NOW
@user-fj2yo6jp5h
@user-fj2yo6jp5h Ай бұрын
Gani kiise Yoruba gidi,Tapa ni .Eleri wa si oro yii.Gbogbo awon ojulowo omo Yoruba ko fe Gani Adamu mo nile Yoruba.Awon Fulani ti yi wa ka ti Gani Adamu si mo nipa re.Oba ilu Iwo naa je ara won ti nwon gbabode ti ile Yoruba.Gbogbo nyin ni Olorun ma mu.
@kehindeakinlawon8058
@kehindeakinlawon8058 Ай бұрын
Afi fila perin ojo kan lomo
@josephmaito213
@josephmaito213 Ай бұрын
CONFIRM MESSAGE BROTHER MI.
@user-ot9wg1tm3k
@user-ot9wg1tm3k Ай бұрын
Ogun lomapae are you member of OPC,iro ti ba ayeyinje ema segbe gbeyin ni ATI awon toranyin Ni,who no you in OPC ise owoe lonse werrey
@adenijioluwasegunsamuel961
@adenijioluwasegunsamuel961 Ай бұрын
Aree ona kakanfo awon fulani ni gani adams
@OjoDele-tc8zu
@OjoDele-tc8zu Ай бұрын
Olori buruku ni loje
@ojoabuletagba6561
@ojoabuletagba6561 Ай бұрын
Akoni ni yin baba
@matthewaderigbigbe4335
@matthewaderigbigbe4335 Ай бұрын
Ododo fojuhan
@NurudeenCodjo
@NurudeenCodjo Ай бұрын
Gani idamu omo tapa ti fe tuu ile yoruba ka ooo
@kehindeakinlawon8058
@kehindeakinlawon8058 Ай бұрын
Osi ki ba ni lagba ati kekere ni
@ayindecharles2962
@ayindecharles2962 Ай бұрын
The yorubas urgently needs to cancel the word OPC and use another name please. Thx
@josephmaito213
@josephmaito213 Ай бұрын
ATAGBA, ATOMODE WON KO GBON RARA
@sakaadams920
@sakaadams920 Ай бұрын
He is proud and arrogant. He should be dethroned and he is not a Yoruba man . Why must Yoruba accept this nonsense. Enough is enough.
@YusufFolasade-tn7jh
@YusufFolasade-tn7jh Ай бұрын
Ti ile ba ndun omo ale ibe ni koti dagba omo ale ibe tiwa dagba bayi o gbogbo eni toni ani simi nile yoruba Nation olorun mafi emi re se etutu fun omo yoruba Nation
100❤️
00:19
Nonomen ノノメン
Рет қаралды 38 МЛН
格斗裁判暴力执法!#fighting #shorts
00:15
武林之巅
Рет қаралды 91 МЛН
$10,000 Every Day You Survive In The Wilderness
26:44
MrBeast
Рет қаралды 53 МЛН
Тяжелые будни жены
00:46
К-Media
Рет қаралды 5 МЛН
Jacob Zuma udalula okwenziwa uKhumalo esethengwe ngemali
9:05
Sthembiso Mngoma
Рет қаралды 7 М.
ADURA ALE (NIGHT PRAYER) || WAKATI ITUSILE || VEN TUNDE BAMIGBOYE ||03.06.24
Pastor Tunde Bamigboye - WAKATI ITUSILE
Рет қаралды 257
Asiri iku to pa Oko Oloyun (Alh. Fatal Yusuf) - Kola Olootu
26:18
Lagelu FM 96.7
Рет қаралды 174 М.
BABA HAS BEEN RELEASED
Julie Ams Gist
Рет қаралды 19
Nkan to fa Ija larin Oba Solomon ati awon Babalawo - Kola Olootu
14:52
E362 Navigating the Bible: The Historical Books
53:22
Saddleback Church
Рет қаралды 39 М.
100❤️
00:19
Nonomen ノノメン
Рет қаралды 38 МЛН